Está en la página 1de 51

EBO RIRU

Obara Kosun Temple - Baba Kehinde


Faseyi Anisere Akinwale Awo Rere
VERSION COMPILADA POR IFAKOREDE EGBEYEMI ANISERE AKINWALE

Marcamos en iyerosun:

I I X X I I
II II X X I I
I I X X I I
I II X X I I

OSE OTURA ODU DE LA EJIOGBE


ADIVINACION

-Una vez terminada la impresión de los Odù en el Opon ifá, el

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Bàbálawo pondrá en un plato o igba el eko. Colocará el dinero
del cliente en la parte superior de opon ifa y encima del dinero
pondrá pedacitos de nueces de kola, cowries, granos de maíz…

Nota importante:
-Cuando el Ebo se hace por el Odu Ejiogbe, se imprimirá en la
derecha el Odu Oyeku Meji
-Cuando el Ebo se hace por el Odu Ose Otua se imprime en la
izquierda el Odu Ose Irete

-Se entrega el dinero con los pedacitos a la persona o cliente y


pedirá con con el dinero y el eko cercano a su boca, todas las
cosas buenas que desea obtener.

1
Mientras se continúa dando cuenta para quien se realiza el ebo y
se pide por la persona y se reza lo siguiente:

Orunmila o gbo
Agboru Agbotu ebo (nombre de la persona) ni o
Kii se bi ejo (nombre de la persona)
Iwa ni o fi toro lowo re
Ba segun ota
Je ki adura re o gbo
Ki iku ko mo pa
Ki arun ko mo se
Ki aje ko de fun
Ki ebo re ko wo ode orun

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


El siguiente rezo se dice después de cada verso cuando el cliente
no este presente en el Ebo:

Afefe ki i fe ko mo kan igi oko Lara


Ki afefe ebo yii ko ko fe kan Lara (nombre de la persona)
nibi to ba wa.

(Para que el ebo sea aceptado. Esto se repite después de cada rezo)

Ke e dakun
Ke e daboo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara
2
El Babaláwo solemnemente solicitará la presencia y atención de Òrúnmìlà,
y rezará por el éxito y la manifestación del Ẹbọ. Un ejemplo del Odù Ifá
que el awo puede rezar para comenzar el Ẹbọ es Osá-L′Ogbèjo.

Osá-L′Ogbèjo

Agbonrin igboro ko yole e te


Koma baa deran igun
Koma baa deran aje
Koma baa deran iya mi
Dia fun ajagbe
Ti won mu re igbodu lote ni fa
Babalawo kii rubu ogberi

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ogberi kii woo igbodu lai te ni fa
Ifa lo wa di obiri
Molo wa di ewe apadase

(Suyere):
Oferegege
Ajagbe a dide o
Oferegege
Bi ewure bi mo lóojo adide

3
Oferegege
Ajagbe adide o
Oferegege
Bi aguntan bi mo lóojo adide
Oferegege
Ajagbe adide o
Oferegege
Bi adie akuko bi mo lóojo adide
Oferegege
Ajagbe adide o
Oferegege

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Bi iku nbo, Jo koo tee
Bi arun nbo, Jo koo tee
Bi ofo nbo, Jo koo tee
Nijó ajé nbo nile elebo, Nijó aya nbo nile elebo
Nijó omo nbo nile elebo, Nijó ire gbogbo nbo nile elebo
Ki gbe idi ki je ki oto owo elebo

Cuando se están rezando las últimas líneas se levantará el opele o ikin y se


le tocará la frente a la persona, después se pondrá en el piso delante del
Opon

4
Se dejará el dinero en medio del opon ifá con los obi, cowries
etc.… y el plato con eko encima del dinero.

ATEPA IWORI
(Después de recitar este verso se toca la parte derecha del opon
con el ebo y se saca del tablero y se pone frente el Opon)

Atepa iwori Awo Erin, Lo difa fun Erin


Erin n mo bi eleri
Erin n lo oke alo, nile Baba re
Ebo won ni ko se
O gbebo nbe orubo, O gberu, o teru
Ati agba, Ati ijokun
Lo ba ni ki Erin mo de alo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Oun ati Erin nijo n lo
Erin nigbawo lo goke
Ni isin sinyii la ri Erin
Erin nigbawo lo goke alo
Ko si eni to le duro
A fi oke A fi igbo
Bi igbo aduro a o San
Bi oke aduro a mugun
A fi oke A fi igbo
Itakun poolo lo ba ni ki Erin mo de alo
Ati oun Ati Erin Nijo n lo

5
Se reza la Ijuba

Oni beni ooo


Omo irunmole nle o eee
Omo irunmole emo tie seun seun eee
Agbara nla ni yabe si poro oko
A difa fun iba
Ti somo olodumare
Gbogbo iworo, gbogbo iworosope
E je ka mo juba ka to sawo
Iba olodumare
Iba baba, Iba yeye
Iba oluwo, Iba ojugbona

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Iba iyanifa
Iba panpasigidi adaso momuro
Iba eyin iyami aje
Iba Baba Araba Fadare Anisere
Iba Akinwale faseyi
Iwerenjeje
Parakun obarisa
Iya banise, Baba banise
Ori banise, Ikin banise
Asefin oo, Asegba

6
Emi Awo Orunmila (mi nombre) onise ebo fun Oruko
(nombre del cliente) ni Odu (nombre del Odu) Pelu awon
(se nombran los materiales)
Nitori Iku nlo, arun nlo, ofo nlo, ejo nlo, gbogbo ayewo
nlo…
Ati sodide ire aiku, ire aje, ire omo, ire gbogbo…

Después de esto, es muy posible que haya otros awoses en donde se esta
ofreciendo el Ebo. Es apropiado e inteligente el pedir ayuda para que el
Ebo sea aceptado en Iwàrun.
Nota importante: Cuando se esta recitando este canto, se espera que los
awoses que estan presentes pongan atención. Inmediatamente cuando
termina, se espera que los awoses presentes usen su mano izquierda para
tocar el opon Ifá para añadir sus bendiciones y su asé al ebo que esta
siendo ofrecido.

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Asa lo lapa
O fenu soro
Awodi lo lapa
O fese Jale
A difa fun alukaka
Ti n sawo regbo egba
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo
O gberu o teru
Alukulaka ohun awo ba fi owo ba ni fin lebo
Kasai fin lebo
Ohun awo fowo ba.
7
Después de esto ahora pone su mano DERECHA encima del dinero que
está utilizando para ebo diciendo:

Otun, awo won lode aba, lodifa fun won lode aba
Nijo won n sunkun pe awon ko laje
Ebo ni won ni ki won o se
Won rubo lode aba ni won ba nla aje

Retirar la mano derecha y poner su mano IZQUIERDA diciendo:


Osi Awo won lode abose
lodifafun won lode abose
Nijo won nsunkun pe awon ko ni Aya,
Won n sunkun pe awon ko bimo,

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Won nsunkun pe awon ko ni Ire gbogbo
Ebo ni won ni ki won o se
Won rubo lode abose
Ni Won nba nlaya, ni won nba bimo, ni won nba ni Ire
gbogbo

8
Quitar mano izquierda. Ahora colocar AMBAS MANOS, primero la derecha

Ati otun, Ati osi


Ki rubo fun ni aimoda
Asewele, Lo difa fun omo okunrin adepenu
Ti n sawo regbo adewure
Aba degun, aba depele awo lori ko le da
Asewele deoo
mode omo okunrin adepenu
Epe ibaba, Epe ikoko
Egun oluweri ki imu olodo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Kini yoo pa elepe fun mi?
Sawepepe Ifa ni yoo pa elepe fun mi
Sawerepepe

Ke e dakun
Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

9
Quitar su mano izquierda e ir PRESENTANDO los materiales del ebo a el
PECHO y la CABEZA de la persona.

(CONTINUAR EL PROCESO CON LA MANO DERECHA)


Erigi lawo agbasa
a difa fun won nisese ega
difa fun won ni sese agere
won ji won ko mo ohun ebo
ebo won ni ki won o se
won gbe bo
won o rubo
o gberu o teru
''EKO ti n be nile
yii ko ohun ebo ni se
erigi lawo agbasa

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


ifa ari ohun ebo...''
Repetir verso de (ERIGI LAWO AGBASA) con TODOS LOS MATERIALES para
el ebo.
(Eko, epo, oti, omi…)

10
Siguiente paso diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Ewe kan tele omi
A difa fun ori
Ti se baba awure
Ori eni nlawure eni
Orisa bi aji lowuro ka gba ori eni mu sigi sigi
Ori eni nlawure eni
Ke e dakun

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

11
Siguiente paso:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Bisu ba kan ngidi
Gbogbo ayaba ni gbowo ijó
A difa fun adabo
Ti se ojíse olodumare
Ni iku awise
Ni iku awise nile ifa
Adabo, Jowo je ki ebo oo da
Ni idoromi awise nile ifa

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Adabo, Jowo je ki ebo oo da
Ni iwonran nibi ojumo rere ti mo wale aye nile ifa
Adabo, Jowo je ki ebo oo da
Adabo
Ke e dakun
Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

12
Siguiente paso:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Sejee ko mo eni oba
Ojo ko mo eni owo
Eni ojo ko ba se lowo
Gbogbo won ni eji nda le Lori
A difa fun ibiye
Ti somo ajani warun
Ebo won ni ko ma se
O gbebo oru ebo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gberu o teru
Ibiye a ko ri ibi mo
Okan yee yee yee
Ibi si ye danu.
Ki ibi oye kuro lori re
Ase (nombre de la persona)

13
Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Tekiti lawo omode
Tekata lawo alare
Ika kan soso lo ku ko deji oye
Beeni ko le deji oye
A difa fun baba asebo korun o mo
Awa ti sebo orun awa ti mo fun gbogbo ibi.
Ki Orun re o mo fun gbogbo ibi.

Ase (nombre de la persona)

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ke e dakun
Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

14
Siguiente paso diciendo:

Ke fin dandandan, Ke e gba dandandan


Mole ti mori olu
Baranhin awo ode ido
Ogoron biti awo ode ijesa
Erigi dudu ni sawo ilusakun
A difa fun olofin
Ti n ba ibi sun
Ti n ba ibi ji
Ebo won ni ko se
O gbebo oru ebo, O gberu o teru

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


A sin ibi ile olofin lo eluju lonii
A si ko ire wale
Igba ni ewe olowonran sansan oko
Bi kasai sin ibi lo eluju
Bi kasai ko ire wale
Asoni nibi di nibi lo
Ibi di, Ibi a lo eluju
Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu, Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

15
Siguiente paso:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Efufu yege nyege
Babalawo aso
Lo difa fun aso
Aso nraye ogbo
Ebo won ni ko se
O gbebo oru ebo
O gberu o teru
Enikan ki igboku aso

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Jee jee jee laso gbo
Enikan ki igboku Awo
Jee jee jee lawo gbo
Mo je kaye ogbo ku re
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun
Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara
16
REZAR EL ODU DE LA ADIVINACIÓN

Ke e dakun
Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

REZAR EL OMO IYÁ (4 versos al menos si es akoru, ó 1 si es asayan)


Por ejemplo:
Si está ejecutando ebo para Iwori Ogbe y recita su opuesto que es Ogbe
Iwori.

* Si la persona que se está haciendo Ebo es un Babalawo, después de

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


rezar el OMO IYÁ dirá:

(NOMBRE Y SU ODU IFÁ) Onile kii je ki ile re o baje.

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu

17
Siguiente paso se recita Eji Ogbe diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Ejiogbe ke e wa banise
Ooro tere awo Inu igbo
A difa fun aje
Ti somo olokitin sikiti
Ti ntode orun bo sode isalaye
Ti yoo fi ile Ejiogbe se Ibudo
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gberu o teru
Ko je mo fiso sile awo
Aje de oniso
Ko je mo fiso sile Awo
Ire gbogbo de oniso, Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun
Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara
18
El siguiente paso recita a Oyeku Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Oyeku Meji ke e wa banise
Iguno kannu
Ko se kanya
A difa fun Baba yeku yeku
Ti won npe loyeku Sanponna
Iku ko le pa oun ni ndafa si
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gberu o teru
Ki ni yoo yeku nu lori awo, Eji-Oye
Ifa ni yoo yeku nu lori awo, Eji-Oye
Ki yeku nu lori awo
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun
Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara
19
Siguiente paso es recitar Iwori Meji:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Iwori Meji ke e wa banise
Ke e je kofin, Ke e je koda
Ke e je kowode orun
Eruko woko woko
O fori tiko
A difa fun Eji-wori
Ti n lo je Eketa Oba ninu Ifa
Ebo won ni ko se

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gbebo oru ebo, O gberu o teru
Bi won ngun mi lodo
Bi won nlo mi lolo
Ibi rere, ni ope ngbe mi re
Ibi rere.
Ibi ire ni ke gbe de o
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu, Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara
20
Siguiente paso es recitar Odi Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Odi Meji ke e wa banise
Ke e je kofin, Ke e je koda
Ke e je ko wode orun
Ke e wa banise
Odidi kiridi awo Ori, Lo difa fun Ori
Ori nbe logbere oun nikan
Ebo won ni ko se, O gbebo oru ebo, O gberu o teru
Oju wa, Oju wa bori duro, Kere kere

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ori mi o saideleni, Kere kere
Eti wa, Eti wa bori duro, Kere kere
Ori mi o saideleni, Kere kere
Imu wa, Imu wa bori duro, Kere kere
Ori mi o saideleni, Kere kere
Gbogbo ara wa bori duro, Kere kere
Ori mi o saideleni, Kere kere
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun, Ke e dabo, Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun, Ke e fiyede gbogbo ara
21
Siguiente paso es recitar Irosun Meji diciendo:

Ke fin dandandan, Ke e gba dandandan Mole ti mori olu


Irosun Meji ke e wa banise
Itaruku Awo itaruku
Itaruku Awo itaruku
Itaruku tatata
Itaruku tatata
Rukuruku tatata
A difa fun igba
Ti n sawo lo sode Oyo
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gberu o teru
Igba rula o
Igba rukan
Igba rusu kan takitaki
Igba ta waye eni
N la nigba.

Ase (nombre de la persona)


Ke e dakun, Ke e dabo, Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun, Ke e fiyede gbogbo ara

22
Siguiente paso es recitar Owonrin Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Owonrin Meji ke e wa banise
Okuta paa alamoseje
Awo owo
Lo difa fun owo
Omo abi marun-un jere ararun
Ebo won ni ko se
Omo owo ki I toju owo ku
Omo ese ki I toju ese rorun

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ifa mo je ki n toju re rorun

Ase (nombre de la persona)


Ke e dakun
Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

23
Siguiente paso es recitar Obara Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Obara Meji ke e wa banise
Iguno lo ti kekere yokoko
Odagbalagba tan apa ko riyun ka
A difa fun baba agbolenubi agogo
Ti n fomi oju sogbere ire gbogbo
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo
O gberu o teru

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ifa ni aijemi ni o
Ni ko je ko ti ba won laje
Ifa ni aijemi ni o
Ni ko je ko ti bawon ni gbogbo ire
Ifa mo ti sebo baba agbolenubi agogo

Ase (nombre de la persona)


Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu, Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

24
Siguiente paso es recitar Okanran Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Okanran Meji ke e wa banise
Okanran kan nihin-in
Okanran kan lohun-un
Okanran di meji adodo
A difa fun Oya
Ti n sunkun pe omo o lo ile onira
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gberu o teru
Eyin omo oya da?
Awa omo oya re o
Hee hee o

Ase (nombre de la persona)


Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu, Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

25
Siguiente paso es recitar Ogunda Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Ogunda Meji ke e wa banise
Ogunda ji awo ibon
Lo difa fun Ibon
Ibon n be laarin osiri
Ibon n be laarin ota
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo
O gberu o teru

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ibon a ni oun sebo ogunda ji
Enu ti mo fi n fohun
Ni mo fi n según

Ase (nombre de la persona)


Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu, Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

26
Siguiente paso es recitar Osa Meji diciendo:

Ke fin dandandan, Ke e gba dandandan, Mole ti mori olu


Osa Meji ke e wa banise
Osa meji lakodi
Obu yankan yankan leti opon
A difa fun olukoso lalu Arabanbi
Omo Arigba ota segun
Eyi to yoo fi ikete agbo sete
Lojo to nbe laarin osiri
Lojo ti nbe nirogun ota
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gberu o teru
Nje tani n peri re?
To o
Emi ko peri re alado
Kini arira fi sete? Igba ota
Ni arira fi sete, Igba ota.
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu, Ke e fiyedekun, Ke e fiyede gbogbo ara

27
Siguiente paso es recitar Ika Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Ika Meji ke e wa banise
Tentere
A difa fun pakara
Ti n gbe ogun lo ilomi
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo
O gberu o teru
Kini yoo gbe mi leke

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Tentere
Kasai gbe mi leke
Tentere
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

28
Siguiente paso es recitar Oturupon Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Oturupon Meji ke e wa banise
Ologbon mogbo won ko ta koko emi seti aso
Imoran kan, ko mo iye yerupe ile
Arin naka ko rinna debi ile gbe pekun
A difa fun seyo
Ti n sunkun pe Omo nlo kaa kerindinlogun
Ebo won ni o se

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gbebo oru ebo
O gberu o teru
E wo ile ayo
E wo omo
Enikan ki i ba ile ayo laikun
E wo ile ayo
E wo omo
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun, Ke e dabo, Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun, Ke e fiyede gbogbo ara

29
Siguiente paso es recitar Otura Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Otura Meji ke e wa banise
Akegi nigbo fohun jo agogo
A difa fun alabebe osogan
Ti se omode okunrin Ode
Ti nfomi oju sogbere Ire
Ebo won ni ose
O gbebo oru ebo
O gberu o teru

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ire ku niwajuo
Ire ku leyin
Kuku agbado
Ire mo mo ku
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

30
Siguiente paso es recitar Irete Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Irete Meji ke e wa banise
Poro bayi
Ala bayi
A difa fun landebu
Ti se yeye oke
Ti nsunkun pe oun ko laje
Ti nfomi oju sogbere Ire
Ebo won ni ose

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gbebo oru ebo
O gberu o teru
Aje ile yii nko ti oke ni
Toke toke ni etu ke loko
Ire gbogbo ile yii nko ti oke ni
Toke toke ni etu ke loko
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu, Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara
31
Siguiente paso es recitar Ose Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Ose Meji ke e wa banise
Oke lamo laya
A difa fun won leru kumoye
Nijo Ire aje ile won silo
Ebo won ni ki won ose
O gbebo oru ebo, O gberu o teru
Aje to silo leru kumoye
Ife aje wole de

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Oke lamo laya
Ire aje ti dele wa
Ire gbogbo to silo leru kumoye
Ire gbogbo wole de
Oke lamo laya
Ire gbogbo ti dele wa
Ire gbogbo de fun
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun, Ke e dabo, Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun, Ke e fiyede gbogbo ara
32
Siguiente paso es recitar Ofun Meji diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Ofun Meji ke e wa banise
Eepa Odu, eepa Odu, eepa Odu
Aja ki igbo won lode ibon
Akuko ki poko ho Loja eji gboromekùn
Bi igbo ba peditan
Oni won wo a wo
A difa fun oyi oti li elewù oogùn
Ti yoo fi gbogbo ara to nbutu aje

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo, O gberu o teru
Oyi ni nbo Lona yi oo
Iku e para mo
Arun esi parada.
Ki iku mo pa o
Ase (nombre de la persona)
Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu, Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara
33
Siguiente paso es recitar Owonrin Sogbe diciendo

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Owonrin sogbe Ke e wa ba ni se
Esu pere jegede
Egba pere jegede
A difa fun ologesa
Ti yoo koro leje tomo tomo
Ebo won ni ko se
O gbebo oru ebo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gberu o teru
Eje awa koro
Awa ko ku mo
Atikun igba ewe jogbo
Eje Awo momo koro
Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

34
Siguiente paso es recitar Owonrin Wofun diciendo

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Owonrin Wofun Ke e wa ba ni se
Anika atirose ko mo bo bata
Atirose ni oun yoo bo bata
Tiwaju logbo, Teyin ogbo
A difa fun iyami osoronga
Ti won n sawo lo sode opó kiá
Ebo won ni ki won o se
Won gbebo won ru ebo, Won gberu won teru

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ta lo dani losu ta fi nsawo?
Iyami osoronga
Lo dawa losu ta fi nsawo
E Bani kunle fobinrin
Obinrin lobi wa, kawa to deniyan
E ba ni kunle fobinrin
Obinrin lobi Oba
Ki Oba o to dorisa.
Ke e dakun, Ke e dabo, Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun, Ke e fiyede gbogbo ara
35
Siguiente paso es recitar Ogunda Bede diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Ogunda bede oo ke e wa banise
Ogike, Lo difa fun ore obó
Ori gidipi
A difa fun iro ti yoo mo rarun kangé kangé
Asipopoleta
A difa fun ologburo ti yoo mo wa se awadá
Gburualá

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


A difa fun alabahun ti yoo jijó ayó kadé
Ebo won ni ki won o se
Won gbebo won ru ebo
Won gberu won teru
Ti ifa se loni o, Ti ifa se, Gburuala
Ti ifa se, Gburuala
Ti ifa se loni o awo ni gbogbo ré
Gburuala, Ti ifa se, Gburuala
Ke e dakun, Ke e dabo, Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun, Ke e fiyede gbogbo ara

36
Siguiente paso es recitar Ose Birete diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Ose Birete ke e wa banise
Ase bi sile aja nroju
Akose bisile aja nroju
Eewo orisa
Ipori aja ko je obi ri
Eegun ni aja nje
A difa fun gbagbara egun osun
Ebo won ni ko se

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


O gbebo oru bo
O gberu o teru
Osungaga moriro
Ko mo dubule
Ni ooro gan gan la ba osun Awo
Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

37
Siguiente paso es recitar Ose Otura diciendo:

Ke fin dandandan
Ke e gba dandandan
Mole ti mori olu
Ose Otura ke e wa banise
Konkoro awo ewi nile alado
Orunmu dede ija kanle awo ode ijesa
Alakan ni nbe lodo
Ni nlu akara aya pereperepere awo odo oluweri
A difa fun igba irunmole olukotun
Abu fun igba irunmole olukosi
Nijo ti won bo sile aye

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Won nla igbo oro
Won nla igbo opa
Won nla igbo agbara
Won nla ibi ese nto
Beeni won ko fi ti osun se
Won pe egungun
Egungun ko je
Won pe oro
Oro ko fohun
Won wa ke eepa to olodumare lo
38
Olodumare ni obinrin to si ketadinlogun yin nko?
Won ni awon ko fi tire se
Olodumare ni ki won o lo mo fi tire se
Agberegede ajuba
Ajuba naa aboju gberegede
A difa fun osun osengese
Ti yoo mo gbe ikoko
Ti yoo mo gbe ibaba
Ti yoo mo tun ebo irunmole se
Gunyan gunyan ode ido
Obinrin leyin se
Iye wa apenimo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Atifi imo je ti osun
Rokaroka ode ido
Obinrin leyin se
Iye wa apenimo
Ati fi imo je ti osun
Oya nile ira
Obinrin leyin se
Egba ti n be lode iluka
Obinrin leyin se
Atimojo ti n be lode iwo
39
Obinrin leyin se
Oke ti nbe lode ibadan
Obinrin leyin se
Iye wa apenimo
Ati fi imo je ti osun
E bani kunle fobinrin
Obinrin lobi wa
Kawa o to deniyan
E bani kunle fobinrin
Obinrin lobi oba
Ki oba o to di orisa.
Ore yeye osun

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ke e dakun, Ke e dabo
Ke e fiyedenu
Ke e fiyedekun
Ke e fiyede gbogbo ara

40
Despues de recitar Ose Otura diciendo:

Ifa dele ado o daje


Aroni gbele diwin dagba
A difa fun enlejo alaworo
Nijo won ni won ko ni Ase lenu
Ebo won ni ki won o se
Won gbebo won rubo
Won gberu won teru
Kin loni ke mo kohun Awo?
Eko, ifa loni ke mo kohun Awo
Eko.

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Siguiente paso es recitar el siguiente verso diciendo

Ewi aye lewi ebo yii


Ki egba Ode orun ko gbaa
Awo lewi aye
Orunmila ni egba ode orun
Gbogbo ohun ti ewi aye ba wi
Ohun ni egba ode orun yoo gba.

41
Después de rezar estos versos:

Si está utilizando adiye o cualquier artículo para el Ebo se va a poner la


pluma de gallina en el ebo.

El siguiente paso, ahora dejas que el dinero con el maíz o la pieza de obi
para el ebo toque el piso diciendo:

Ile o gbo
Agboru Agbotu
Ebo re ni o
Ile a fi o seri ni
A ko fi e kun ebo ru

Ahora, el siguiente paso es dejar que el Ebo toque el Opon Ifa diciendo:

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Ako pada ni je ki ebo oloja o da
Y deja que el dinero toque el ebo diciendo:

Ki ori re ko ba se

A continuación, se toca la frente del cliente con los obi diciendo:

Koko oun eepe ni agbe


Fi ledi kan ede owo ni babalawo
Fi ntun ori won se ori ti aba
Fi owo we agbo ato

42
A continuación, ahora le dará a la persona los pedazos de obi o maíz para
que los separe en dos en sus manos.

Ahora, la persona pondrá poco a poco los pedazos de su mano derecha en


el ebo mientras se dice:

O fi otun ru ebo

Luego con la mano izquierda diciendo:

Ki osi ko gba da
Ahora déle a la persona un pedazo de obi o maíz para pasarlo por detras
con la mano derecha y recogerlo con la mano izquierda y colocarlo en el
ebo diciendo:

Mo san owo agbeyin ba ebo je,


ki won mo gbeyin ba ebo mi je

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE

43
Ahora se pone Epo al Ebo diciendo:

Gburugburu
Gbuegbue
A difa fun epo
Ti somo Iya ebo
Epo gori re o di ebo
Gburugburu
Gbuegbue
Epo gori re
O di ebo

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE

44
Luego se pone Oti al Ebo diciendo: (Òtúrà-Ireté)

Òtúrà ni lalèmu
Ìrètè ni lalèrá
Diá fún Arànìsán
Ti yóó mu igba
otí kan àmu lòwó
ebo won ni ko se
o gbegbo o rubo
o gberu o teru
Ọ ọtí là ni awo n mu o
Aranisan ifa lo mu igba oti kan amu lowo
Ọ ọtí là lawo n mu o

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Aranisan lo mu Igba Oti kan a mu pa ota
Oti Ola ni awo n mu.

45
Para poner Omi diciendo (Ejiogbe)

Ela gejegeje
A difa fun olomi tutu
Ti n tode Orun bo sode isalaye
Ebo won ni ko se
O gbebo o rubo
O gberu o teru
Kin la ba olomi tutu ti n se?
Ela gejegeje
A ba olomi tutu ti n tun aye se.

Se añade Iyerosun al Ebo diciendo:

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


(NOMBRE DEL ODU) o wa te te te

46
Despues de esto se pregunta si el Ebo es bien aceptado.
Se pone el Opele marcando el Odu principal del Ebo y con el Ibo del Cowrie
se dice:

Ebo yii fin, Ebo yii da, O fin O da

con el Ibo del hueso se dice:

O ku leyin ni eegun
Si dice que no se pregunta Ebo o Ayewo.
Si dice Ebo se pregunta si se añade Epo al ebo o se preguntan por algunos
materiales para añadir.
Si dice Ayewo se pregunta como en un Idafa.
Si es aceptado poner el ebo en el suelo fuera de la estera y tocar el Epo de
dentro del ebo con el dedo para tocar despues el suelo diciendo:

Abodi awo ile

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Lo difa fun ile

Bi opon ba se

Ki ile o seri

Ile a fi o se eri ni
A ko fi o kun ebo ru

Después de esto, ahora pregunta si el ebo necesita recitar Okanran Osa o


no.
Si el ebo no lo necesita, la persona llevará el ebo al lado de Esu Odara,
pero si el ebo necesita recitar Okanran Osa, se recitará …
47
Se imprime Okanran Osa en el Opon se pone el Ebo encima. Mientras se
recita el verso se pasa el Irukere de un lado al otro sobre el Ebo y al
terminar de rezar se le arrancar unos pelos y se añaden al ebo

Okanran osa eleru


Okanran osa eleru
Okanran osa eleru
Kamu genge lu genge awo ile alakoko
Igbin ko lara ina n yiya
Awodi ko sa ko gbe eyin laya adie
Oluwo meta
Irukere mefa
Ogun ta fi esin, oko se ti a ko le se

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Irukere tiemi ni edu fi tumo won
Ki e tumo iku, Ki e tumo arun
Ki e tumo gbogbo ibi, Aranse igunnugun
Igunnugun ni oun ko ni ina ya
Aranse akalamogbo
Akalamogbo ni oun ko ni oorun ni yiye
Adie alatanroko lo ti di eran ti igun je
A difa fun gbirari
Ti sawo olukeesu
Gbireri, Gbirari
48
A difa fun ikoko
Ti n lo oko ode
Oun o ri ni ako esin
Oun ko ri ni agbo agutan
Ko si paapa ni ako aja
Ko si paapa ni mologisasa obuko
Iko eyi ko wa ti poju
Oni ti oun ba gbebo oun rubo
Oun ba ti n gberu, oun teru
Oro ti oun ki i ni abamo buruku ninu
Nigba ikoko ba pa eran je tan
Ani Babalawo oun yin gbireri

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


Babalawo oun yin gbirari
Okanran osa eleru
Bi ebo ba kan otun ko fin
Bi ebo ba Kan osi ko da
Bi ebo ro siwaju ko fin
Bi ebo ba ro seyin ko da
Bi o ba duro Laarin opon ko wode orun.

Si se reza Okanran Osa se permitirá que la persona se incline hacia abajo


frente a la IFA cuando llame a okanran osa. Y se añade este iyerosun al
Ebo.

49
Ahora se toca con el ebo la cabeza de la persona tres veces y el pecho tres
veces.
A continuación, la persona llevará ebo a Esu Odara.
Mientras la persona pone el Ebo a Esu se recitan versos de Esu
Cuando la persona regresa de Esu odara, dejará que su cabeza toque el
piso tres veces cubrirá ifa (opele o ikin) con las manos mientras se reza:

Irinpako lori efon


Igbasaka Lorun ope
Agbemo lorun jingin
A difa fun talagereje
Ti somo edu
Talagereje

COMO HACER EBO RIRU - OBARA KOSUN TEMPLE - ANISERE AKINWALE


A ki i sadi orope
Ki iku ko pani
Ope mo di o mu
Ko mo yin mi nu
Iyere aragi ki won danu
Eewo orisa Aki sadi orope
Ki iku ko pani.

50

También podría gustarte