Documentos de Académico
Documentos de Profesional
Documentos de Cultura
I I
I I
I I
II II
gnd Mj
(1)
Yoruba
O se firi kojana
A dia fun Orunmila
Ifa nlo lee gbojontarigi
Obinrin Iku
Ojontarigi nikan naa ni obinrin Iku
Orunmila si fee gba a lowo Iku
Won ni ki Orunmila o rubo
O si ru u
Igba ti o rubo tan
Lo ba gba Ojontarigi lowo Iku
Ni Iku ba mu kumo
O kori sile Orunmila
O si ba Esu lojude
He met Esu in front of the house
Esu ni nle o
Iku, Ojepe, alaso osun
Igba ti won ki araa won tan
Esu ni nibo lo nloo
Iku ni oun nlo ile Orunmila ni
Esu ni kilo de? Esu asked,
Iku ni o gba oun lobinrin ni
Loni ni oun o si pa a
Ni esu ba ni ki Iku o jokoo
Igba ti o jokoo tan
Ni Esu ba fun un ni jije ati mimu
Igba ti Iku jeun ti o yo tan
O dide
O mu kumoo re
O nlo
Esu ni nibo lo da
Iku ni oun nlo ile Orunmila ni
Esu ni a maa jeun eni
tan ka tun pa ni
O o mo pe onje Orunmila lo je yii
Igba ti Iku o mo ohun ti yoo se mo
O ni So fun Orunmila
ki o moo mu obinrin naa
Ijo ni Orunmila njo
Ayo ni nyo
O ni o se firi kojana
A dia fun Orunmila
Ifa nlo lee gbojontarigi
Obinrin Iku
Oran te e ro keke si
Ale ana ni mo fi soti
Ni mo fi mu
Gberefu
A foran yi mu taba
Awa foran yi mu taba
A o ku mo
Gberefu
A foran yi mu taba.
Espaol
(2)
Yoruba
Espaol
(3)
Yoruba
Espaol
gnd Mj el sacerdote de If del Arma
realiz la adivinacin de If para el Arma
Cuando estaba viviendo en medio
de los enemigos
Se le dijo al Arma que realizara
sacrificio
Tambin le dijeron que
siempre hablase como un hombre valiente
Y as lo hizo.
Despus de que el Arma haba realizado
el sacrificio
Empez a matar a sus
enemigos
Como uno mata a los animales
El dijo, gnd Mj sacerdote de If
del Arma
realiz la adivinacin de If
para el Arma
Cuando estaba viviendo en el medio
De los enemigos
Es la boca con la que
El arma habla
Que conquista a sus enemigos.
El dijo que
eso fue exactamente lo que su sacerdote
De If predijo.
(4)
Yoruba
Espaol
El sacerdote de If llamado
Pomu Pomu sigi sigi
pomu pomu
Realiz la adivinacin de If para
Orunmila
Cuando dispar una flecha
mat a la Muerte en la granja
Oloniimoeo dispar una flecha
Y mato a la Muerte en la granja
Nosotros alabamos a Pomu pomu
sigi sigi sigi
pomu pomu.
Se le pidi que hiciera sacrificios
El hizo sacrificios
Despus de que el haba realizado
el sacrificio
Entonces sus sacerdotes de If
le dieron tres flechas
Se le dijo que disparase todas las fechas
por todas partes en su granja.
Cuando dispar una flecha
Mat a la muerte en la granja
El dijo que eso fue exactamente
Lo que su sacerdote de If
Predijo.
Nosotros alabamos a Pomu pomu
sigi sigi sigi
pomu pomu.
(5)
Yoruba
Aguru mo guda
Aguru mo guda
Bida ko ba sun won
E je a ponida
Ka tunda gan
Difa fun Orunmila
Ifa nlo lee gba duduranran
Ti somo Alaran oyigi
Won ni ki Orunmila gba duduranran
Won ni bo ba gba tan
Ko si nkan tole tibe wa
Orunmila gba duduranran tan
Ni won ba ni o ku ibi ti yoo gba
Ni Orunmila ba nsa Ifa
Bi eni ti nsa Oogun
O si nsa oogun
Bi eni ti nsa IFa
O ni bee gege
Ni awon awo oun nsenu
reree pe Ifa
Aguru mo guda
Aguru mo guda
Bida o ba sunwon
E je a ponida
Ko tunda gun
A dia fun Orunmila
Ifa nlo lee gba Duduranran
Eyi tii somo Alaraan Oyigi
Bo se ole ni ba nba mi sota o
E joo mi
Bi abiku ba ku tan
A sin leyin aase
Bi seere ba fo tan
A sin leyin sango
Bi Aje ile lo ba nba mi sota o
Ejoo mi
Bi a biku ba ku tan
A sin leyin aase
Bi seere ba fo tan
A sin leyin sango.
Espaol
(6)
Yoruba
Gbongbo se woroko fi
woroko jana
A difa fekun
Nijo ti nlooko ode
Nwon ni o kaaki mole
O jare
Ebo ni o se
Ko pe o
Ko jina
E tete waa ba ni
ni tisegun.
Espaol
(7)
Yoruba
Espaol
(8)
Yoruba
Espaol
(9)
Yoruba
A mo oni, A o mo ola,
bi otunla omo iya re,
bi yio sunwon, bi o sunwon.
ni a mo.
Adifafun Orunmila ti o raga
bo omo re,
bi Igun Igemo. Ifa raga
boo mi, ewe ori ni raga bo ori,
ifa raga bo mi,
Etipon-ola ni raga bo Ile.
Ifa raga bo mi, bi adie ba
pa omo a raga bo omo re,
ifa raga bo mi, bi omi nla ti
se raga bo yanrin lodo,
ifa raga bomi.
Espaol
Conocemos el hoy,
pero no conocemos el maana
Ni el pasado maana,
no sabemos si dentro de dos das
ir todo
bien o no,
no lo sabemos,
estos son los nombres
de los sacerdotes
Que hicieron adivinacin If
para Orunmila
el da en que Orunmila
Quera proteger todas
sus propiedades,
esposa, hijos, Orunmila protegi a todos ellos
De los demonios malos y de los enemigos
como la hoja que cubre la
Cabeza, como Etiponola
cubri la tierra,
como la gallina cubre a
Los polluelos,
If tu eres el nico que
puede protegerme.
(10)
Yoruba
Espaol
(11)
Yoruba
Gunnugun soore,
Orii Gunnugun pa,
Akalamagbo oore,
Ma yo gege lorun,Ojo mii,
jomi, Keni ma ma
jiyan, soore mo,Oro soore,
Oro o lewe, Afomo soore,ko
legbo,
A difa fun okete,
Ni ojo ti o lo te oka nifa,
Oka i o ba gbe awo mi,
Ibi lose, ka bi o ba pe- ewusa, ti
o bafi ku,
Oka bi o ba gbe awo mi,
Ibi lose.
Espaol
Gunnugun soore,
Orii gunnugun pa,
Akalamagbo oore,Ma yo gege lorun,
Ojo mii, jomi, Keni ma ma jiyan
soore mo, Oro o lewe,
Afomo soore, Ko legbe
estos son los nombres
de los sacerdotes que adivinaron
If para Okete
en el da en que
Iban a hacer la iniciacin a Oka,
cuando Okete acab la iniciacin
De Oka,
Oka se volvi y mat a Okete.
Entonces Okete grit que
Si Oka se trag a Okete,
hizo mal porque el fue
el que
Inici a Oka.
(12)
Yoruba
Abemole eekan,
Abi oju regun regun, A difa
fun Oyi gbegi ti n sukun omo
losi ode ipo,Won ni ki
oyi ru ogun,
Obi ogun, won ni ki oyi ru ogbon,
O bi ogbon.
Tani komo pe eyin lojomo,
ki i to oyi.
Espaol
Abemole eekan,
Abi oju regun regun era el
nombre del sacerdote de If
que adivin
para Oyigbegi, cuando
Estaba llorando
porque quera tener un nio.
El sacerdote pidi a
Oyi Gbegi que hiciera sacrificio,
el cual ella hizo, cuando hizo
el sacrificio para 20, nacieron 20,
cuando el hizo el sacrifico para
30 nacieron 30.
Quin sabe que cantidad de nios
es suficiente
para Oyi gbegi.
I.- Orkis/Rezos
Yoruba
Espaol
Yoruba
. Ifa ni ire aiku fun eni ti o da Ogunda meji, ifa ni ohun yio da abo
boo ohun ati omo ati aya re. Ifa ni ko di mo ohun ifa.
. Ifa wipe ire omo fun eniti o da Ogunda Meji,ifa pe yi o bi omo pupo
laiye,Ifa pe gbogbo omo to ba bi, ni yi o ye,
Espaol
Yoruba
. Abo-adie meji, igba meji okeowo, meji, oti, obi, ewure meji.
Espaol
. Esu ni aladimu,a o fi obuko bo esu, pelu opolopo epo, oti ati obi.
Espaol
Yoruba
. Eniti o da ifa yi yio ma wure ni idi ifa ni gbogbo igba pelu oti ati obi.
. A o ma wure fun eniti o da ifa yi, nigbogbo igba pelu epo, obi ati oti,
. A o ma wure ni idi ifa ati ni odo esu pelu oti ati obi.
Espaol