Documentos de Académico
Documentos de Profesional
Documentos de Cultura
Iwefa Ifa Lustral Rite Espanol
Iwefa Ifa Lustral Rite Espanol
Òrisa para que la fiesta será celebrada es ese rey de la corona que está
tomando su o su baño espiritual. Òrúnmìlà en Òtúrúpòn-Òfún dijo Edu a
uno de sus sacerdotes para siempre lavar sus manos y pies antes de
realizar cualquier ritual.
Òòrùn jí ní kùtùkùtù
Ko yèrìyèrì
A dífá fún won ní Kàáà à-jí-jáwé
Ewé awó sà
Kà sàì jé rere
o
Ewé awó sà.
Orin:
Ewé awó sà món jé o
Gbogbo ìsèlè
Àìsà máa jé o
Gbogbo ìsèlè.
Lílé: Gbobì je o
Ègbè: Igba ewé èlùjù
Gbobì je o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Ò bá gbobì je o
Kí nní ire gbogbo nígba nígba
Ègbè: Gbobì je o
Igba ewé èlùjù
Gbobì je o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Gbata je o
Ègbè: Igba ewé èlùjù
Gbata je o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Ò bá gbata je o
Kí nní ire gbogbo nígba nígba
Ègbè: Gbata je o
Igba ewé èlùjù
Gbata je o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Gbotí mun o
Ègbè: Igba ewé èlùjù
Gbotí mun o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Ò bá gbotí
Kí nní ire gbogbo nígba nígba
Ègbè: Gbotí mu o
Igba ewé èlùjù
Gbotí mun o
Igba ewé èlùjù
- Ògúndá
Òbàrà.
Òdúndún a bi
ewé péele péele
Tètè òdàn a bi
èrìgì gborìgì gborigi
Ifá ní e wo owó
adétè e wo òdúndún
Ogbogba ni
wón jo se
Ó dífá fún
Òrúnmìlà
Ní ojó tí ó nlo le
gbe Òdìdìmòdè niyàwó
Òdìdìmòdè, ìwo
aya mi
A kò bá o pínùn
pé ká paya eni
Òrúnmìlà, ìwo
oko mi
A kò bá o
pínùn pé ká poko eni.
-Òfún méjì.
Orin:
Òdúndún ma ní tèwèrù 2x
Bóbá dàmòdun
Ma lé tèwèrù
Òdúndún ma ní tèwèrù
Bí àgbàdo bá yo ìrùkèrè
Kò jé fi lé omo
elòmíràn lówó
A pin Téélé-téélé
kárí omo re
A dífá fún esè
kan soso Ogbè
Tí won ní kò ní
telè yí pé
Ebo ni wón ní
kóse
Òun sì gbébo
níbè ó rúbo
Njé tani onílè
tóni
Tètè kò má telè
Tètè tèé rere
Ìwo ni onílè
Tètè tèé rere.
Ogbè-Atè
Orin:
Ta lonílè tóni
Tètè kò má te
Tètè tèé rere
Se bíwo lonílè
Tètè tèé rere.
Orin:
Odán dolóde 2x
Kèrèkèrè
Odán dolóde.
Orin:
Líle: Mò jákú o
Mo járùn o
Ègbè: Sasara
Mò jákú o
Mo járùn o
Sasara
Líle: Mò jéjó o
Mo jóràn o
Ègbè: Sasara
Mò jéjó o
Mo jóràn o
Sasara
Èlà yìn-ìn
Babaláwo isin
Lóki Ifa fún isin
Isin nbe lárìn òtá
Ebo ni w’on ní kóse
Ó gbébo níbè ó rúbo
È bá jáwé isin
È bá wagbò isin
Oró tí e dá isin
Isin kò sà ì là.
Orin:
Isin kò sàìlà 2x
Oró tí e dá sin o
Isin kò sà ì là
Orin
Òwú dé awo ògòdò o 2x
Sebí terú, tomo lòwú là o.
Yími ébè
Kí nyí e sí poro
Ó dífá fún gòdògbó
Tí rayé ìlaìnikú
Ebo wón ní kóse
Òun sì gbébo níbè ó rúbo
Kèèpé o, kèèjìnà
E wá bá ni láìkú kangidi
Àìkú kangidi làábáni lésè oba Òrìsà
Orin :
Kò ní bá won
Kúkú òwowòó
Gòdògbó o
Kò ní bá won.
Pápásan Èèsún
Rinrin Sàájé Portulaca oleraceae
Ògègé Gbégi Lóbòntujè
Ètìpón-olá
Orin:
Lílé: Érún Érún Lílé: Sùsù o
Ègbè: Erun Èrún.
Obaládé mà nwè
Lílé: Érún lájé Ègbè:
Sùsù o
Ègbè: Erun Èrún. Lílé:
Èjìogbè, Oba n’Ifá
Lílé: Érún níre gbogbo Ègbè:
Sùsù o
Ègbè: Erun Èrún.
Obaládé mà nwè
Sùsù o .