Documentos de Académico
Documentos de Profesional
Documentos de Cultura
IGBO DUDU 1-1
IGBO DUDU 1-1
AROBI AKOYA
Ao gun eru ori teteregun,
Eje ewure omole ati oloyunbere papo, a o
Obi ti won fi bo ifa wa po ni ose, a o wa lo be eso
Eru ori teteregun ogede palanta, a o gbe omi ti o
ba n kan lati ara ogede yi si ara gbe nkan wa lo tabi a akiyesi se
ose yi, a o ma fi owo po ose yi wipe enikan n saasi wa, a o ji ni
ti yoo fi de daada, a o wa ko idaji kutukutu, a o fi ako okuta
awon kuluso aaye yi tele iwo si inu ina ti yoo pon daada, a o
igala, a o wa fi ose yi yi eje wa bu omi swi egbe wa, a o yo
ewure ti won fi bo ifa, a o ko okuta yi sinu igba to le gba, a o
ose naa le awon kuluso yen lori wa mu eyo obi kan ninu awon
ninu iwo igala yi, a o tun fi owo obi yi, a o ge tintin je ninu re , a
fa eje die le lori, a o wa ko o fi obi yi si apo tabi ki a fi
awon obi yen le lori, a o ki won pamo, a o bu ose die ninu iwo
mo inu ose yi ti won yoo yo ori yi, a o ma fi fowo si ori ako
die die si oke, a o gbe pamo okuta gbigbona yi ninu igba, a
fun 21 days..Lilore.. ti won ba o so nkan ti eni naa se, a o wa
so nkan ti a fe ki o sele si eni onitohun di ahoro o ..Erore.. ta
naa ni aarin ojo meje, a lo da ba ri eni naa ti a si fe fun ni ero
omi ati okuta yi si ori titi oloda re, a o fun ni tintin je ninu obi
tabi ki a lo da si ori saare. ti a ti a fi pamo yi, a o tun wa ge
ba da si ori titi oloda eje re die je ninu re fi se adua lori iwo
gbodo yile laarin ojo meje, ti a naa a o da obi yi pada si ori ose
ba da si ori saare, oku gbodo naa, o daju gan ni o.
ma nan eni naa titi ti yoo fi
jewo ese re, bi beeko yoo je
ipe olodumare laarin ojo meje
OSOLE WARAWARA TODAJU
sugbon ti a ba lo daruko eniyan
DADA
kan si nitori wipe a jo ni
Oga gbigbe kan
gbolohun a so, haa, yoo so ile
Ori eye ofafa kan idana, gege bo se wa ninu
Ori aja tutu tabi gbigbe kan aworan yi, Ao fi odidi atare le
Eyin pepeye meta lori,ao da ewe abifagburu bo
Odidi atare kan monle, ao jo papo taba jo tan
Ewe abifagburu oojo abi tutu Ao lo kunna dada, ao pin ebu
yen si ona meta ao fi peak milk
Ao fi ori aja ,ori eye ofafa ati alago kan lo ebu idakan ni ago
oga ko arawon, ao fi eyin kan oru, Ao tun fi peak milk
pepeye kan si egbe ori eye agolo kan lo ebu keji ni ago kan
ofafa, ao fi eyin pepeye keji si oru ojo keji, ao tun fi peak milk
egbe ori aja, ao fi eyin pepeye agolo kan lo ebu keta ni ago
keta si egbe oga, eyin pepeye kan oru ojo keta..Akiyesi .. Ao
meta yen ma duro gege bi aro ma ro aso funfun opa meta mo
idi taba fe lo ebu yen, toba di AWORO TO DAJU
aro ojo keta tabi lo ebu yen Aso were to tobi die
tan, Ao fi akuko adie alawo Adiye asa kan to ti pa omo ri
meta se sara eyan kogbodo je Adiye ibile olomo leyin
ninu adie yen,ao fi aso funfun Eera aladi a o si tile tile
taro yen se sara pelu owo Ewe ejinrin to fa mo igbo
meta tiki se owo pupa, pelu Daada
ogo olohun ao gba owo ni ojo Efo yanrin to po die
keta tabi ojo kerin. Ewe olojongbodu to po die
Iru wooro to po die
Iyo abo meji
Epo pupa igo meji
Ilepa to po daada oko etile ni a fe ki o ma ro ni
tabi ona jinjin, a o fa iya awon
Ao gbe ile nibi ti a fe bo ise yi oromodie yi ni orun tu, a o ro
mo, a o da kobi owu iyo kan si eje re le won lori ninu koto yi, a
inu re, a o ko ewe olojongbodu o da ilepa bo lori mole, a o wa
tele re, a o te aso were yen le jo adie yen ati gbogbo eroja to
ni ori, a o gbe adiye asa yi le ori se ku yen papo, a o po ni ose, a
aso yen, a o da awon omo o ma fi fo owo le ori sare yen ni
adiye yen le lori, a o ko ewe eekan tabi eemeji losu, yoo si
ejinrin bo mole, a o da iyo abo ma so fun wa ni oju ala ti asiko
kan le ni ori, a o se adura bi a to ba fe gba adiye ba ti to, a o
se fe ki ise re ri, boya olowo ni fa ni orun tu ni ale, a o ro eje
a fe ki o ma mu wa ni o, boya re si ori ati ayika sare yen.
Ao fi awo igala te inu ape
ijogun, ao fi enu ori owiwi ati
OSE EYONU AYE
ori okete pelu ori olongbo ko
Ori eye owiwi kan
arawo ao wa to eyin adie meta
Ori okete kan
yipo re Ao fi odidi atare kan si
Ori olongbo kan
Ao da adun jije lelori ao wa ko
Eyin adie ibile meta
ewe rerinkomi bo monle ao jo
Odidi atare kan
papo toba ku die ki ise yi ko jo
Akuko adie kan
tan ao ja ori akuko adie kan ao
Adun jije
ro eje adie yen si sori ebu yen
Ewe rerinkomi tutu tabi oojo
Ao wa jo papo mo ao lo kunna
Awo igala die
dada ao pin ebu yen sinu Ike
funfun olomori meji ao da oyin OLUGBOHUN AJATO ELEDAN
original sinu ikan ao da epo Edan abo kan pelu ako kan
pupa si ori ikan, ao ma laa tinu Akuko adiye olodun meta kan
oyin yen ni aro kutu hai Ao laa Ewe esisi funfun ati pupa
tinu epo pupa yen lale Egbo inabiri
patapata..Akiyesi..to baje Egbo ijokun oojo
obinrin ni abo adie loma lo, Eye akoko kan
okunrin lo ma lo akuko adie Ao Aso pupa ti o to ran asunwon
lo gbe adie yen si orita meta ati ibowo
niooo Ale lao jo ise yi ooo. Omo aguntan kekere
Igba olomori kan
Abo adiye kan
aya, a o gbe edan abo si inu
Ao ja ewe esisi funfun, a o fi eye yi, a o gbe sinu iho igi
gbo edan ako daada, a o fi ewe iroko, a o da eje abo adie pelu
esisi pupa gbo abo edan, a o nkan ti a da si yen le lori, a o
wa pa akuko adie, a o gbe eje wa gbe edan ako yen sinu igba
re sinu igba kqn, a o pa abo eje to ku yen, a o gbe lo si idi
adie naa, a o gbe eje re sinu igi awusa, a o gbe ile ni idi igi
igba kan, a o gun egbo inabiri yi, a o wa ri igba naa mo le
ninu odo ti yoo kunna die, a o nibe, a o pada wa gbe ni ojo
da sinu igba ti eje akuko adiye keje, a o ti wa oruko kan ti a o
wa yen, a o gun egbo ijokun a o le gbagbe, oruko yi ni a o pe ni
da sinu igba ti eje abo adiye eemeta tooo, ki a to gbe jade
wa, a o wa la eye akoko yen ni o, a o so wipe gbogbo ase ti
iroko ba pa iwo ni ki o ma de o, wa gbe sinu ikoko kekere kan,
a o fi nkan yo edan yi jade, a o a o ta aso pupa bo loju A o lo
gbe sinu apo aso pupa ti a ti ran aso pupa ni ibowo meji, a o
ran ni asunwon, a o gbe da ni ko si ori awon edan yi ki a to da
lo si idi igi iroko yen, a o tun eje aguntan le lori o, aso ibowo
fun oun naa ni oruko, a o pe yi ni a o ma ki bo owo fi ko
oruko naa ni eemeta tooo, awon edan yi jade ti a ba fe lo,
gbogbo ase ti awusa ba pa a o se adura bi a se fe tabi epe,
iroko ni ki o ma de o, a o wa a o ma fi awon edan mejeeji lu
gbe abo edan yen naa sinu apo ara won ti a ba ti n sepe tabi
aso yen naa, ti a ba de ile a o adura Looto o kere pupo
pa eje abo aguntan si ara aso sugbon bi mo se ba lowo awon
yen ati ori awon edan yen, a o agba ni yen ti won si n lo fun
orisirisi asiri, ti e ba sun ibiti won lara , iroko ti aba re edan
awon edan yi ba wa, e o ma yii si eje ko ni da ni ara re lailai.
gbo ni oru ti won yoo ma ba
ara won ja bi gba ti, e ba n fi
EYONU AYE
won lu ara won, ti o ba ka yin
Ori olongbo toni irun kan
lara ti won ko je ki e sun ni e o
Adan kan
yo okan jade ti ile yoo fi mo,
Eku asin gbigbe kan
confirm ni, asiri ni kii soogun
Epo obi
bee si ni kii se abamoda rara
Odidi atare kan
otin ogogoro ko gbodo tan
Ewe adun oojo
ninu igo ti a o ma gbe si egbe
Ewe rerinkomi oojo
awon edan yii ooo , ti aba nse
Ewe iyalode funfun oojo
adura lowo ao ma tu otin si
Ewe orijin oojo ebu yen sinu awo funfun
olomori tabi Ike funfun olomori
Ao fi ewe aadun te inu ape ,ao da oyin original lelori Ao
ijogun , ao ja eku asin yen si mafi ika arin laa ni gbogbo igba
ona meta tabi merin ao ko Ao ma ro papo kato laa oyin
lelori ao gbe ori olongbo si gidi lao lo, kise oyin ireke oo.
legbe ,Ao fi Adan si legbe ,epo
obo si legbe, atare si legbe, ao
ko ewe orijin ati ewe iyalode
ONMO ARINA FUN AWON
funfun lelori ao wa fi ewe
ONIJOKOI TO DAJU
rerinkomi bo Lori Ao fi epo
pupa yio aro ao jo taba jo tan Eye karo tutu kan
ao lo kunna dada ao da gbogbo Eja ojiji aaye kan
Odidi awo olongbo gbe kinni ti a di yi si ori ewe
Ewe logbokiyan oojo eko yen, a o da awon labalaba
Eko ogi baba ti a pelu ewe ati eku le won lori, a o wa yi
gbodogi awo yi mo won ni ara, a o jo ti
Labalaba to po die a ba jo tan, a o ro sinu ado to le
Eku ajeloju onile kan ti won ju gba, a o gbe sinu awo funfun
sita olomori, a o sin gbere meta si
aya wa ni iwaju ati eyin, eyo
Ao fi okun di eja ojiji ati eye kan ni eti otun ati osi A o lo wa
karo papo, a o fi eko yi yi omi ogbungbun ati omi inu
gbogbo inu awo olongbo yi, a ibepe pelu omi agbon, a o po
o wa te ewe eko yi sinu awo meteeta papo, a o ro sinu igo
ologbo yi ti yoo lemo ni ara, a o kan, ti a ba ji ni owuro a o ta
ebu inu ado yi die sinu awo, a o ILEDI UNLA NII NO
da omi ti a dapo yen die si, a o REPERCUTION Ako ijimere kan
fi sile fun bi iseju marun, a o fi Akuko adie asa kan
omi naa bo oju wa, a o si kan Iye agbe 201
die si enu wa. Iye aluko 201
Ikoide 201
Ako alangba kan
OBA OSO OWO ALAPAJA Abo alangba kan
TAFIN DI OLORO OLOWO Ikoko unla tuntun meji
10MILLION NAIRA NI YIO KO
KO MUWA FUN YIN ASIRI Ao ko gbogbo re losi inu igbo
pelu ado ide unla kan , ado irin
unla kan , opa aso funfun kan , ti ao ma fiso fun ijimere na
odidi atare unla kan , Ao pa aso ohun ti afe ati ohun ti ako fe Bi
funfun opa kan yen ni ( Aro o ba beere sini kegbe , Ao ma
osun ) Ao pa ako alangba kan , wi fun pe , kio ma kemo , ise
ao fi eje re pa gbogbo ara ado owo ni moran ooo , Emi kofe
itin , A o pa abo alangba kan owo gbigbona , owo ti mo ma
ao fi ejere pa gbogbo ara ado fiko ile nii mo n fe pelu didun bi
ide , Ao de ako ijimere yen Eegun ni , Ao ma fise alaye
lokun towi tese , Ao je ki okun won yio , nigbatu igbere ba nlo
ti yio seku Oogun daadaa , Ao sile ti oti n re , ki o toku , Ao
gbe ijimere na sinu ajiyon ijalo , tele gbe so sinu agbada
ki otodi wipe ijimere na yio ma gbigbona pelu ijalo arare , ati
kigbe ni ao ti ma dun bi Eegun Ooye adie asa yen ati gbogbo
awon Eelo toku ti aba ko sinu Ao te eni (mat) sile , Ao gbe
ikoko tab , Ao fi ikoko keji boi ado kan si owo otun ati ado
lori ao jo papo Ao lo kuna keji ni owo osin le lori eni na ,
daadaa , ao ro sinu ado ide yio A wa na yio sun ni arin meji adi
kun , Ao ro sinu ado irin yio won yen , Ao si ti ilekun paa
kun , Ao wa da aso funfun ti enikeni ko gbodo jiwa rara ninu
apa laro osun yen ni apo unla iyara ti aba sun sii pelu ise yio ,
kan , Ao da etu ti aro ku sinu afebi abaji fun rawa , bi aba ji
apo yen patapata , ao wa ko Ao ba opolopo owo ninu ile ,
ado mejeji sinu apo naaa , Ao Ao tun ko awon ado won yii
ma gbe apo na ko si oke rere pada sinu apo ti ati kowon waa
nibitu owo obinrin kotinu toi , Ao fiko oke pada Ako gbodo
rara ninu yara owo...Lilore.... se iseyii fun eniti kobati pe
omo ogoji odun O , sugbon bi
abaloo titi di ojo iku bi enina
bati ku lesekese ni ijalo yio ti EYONU EBE AWON AGBA
bo oluware patapata Erore... META
Bi abafe ba iseyii je , A o lo so
okan ninu ado yii sinu odo oya , Efun
ao so elekeji sinu odo osa , Osun
pelu apore , Ogun yii kiise Eedu
bibuje tabi fifwe tabi fifi sa ori Onbe meta
rara O , ogun yi daju Ooo ko ni Ori olongbo kan
repercution ' abi etutu kan kan Eku asin gbigbe meta
' Eniyan Asi pe layee daadaa. Fitila oloju meta
Awo sobi unla tutu kan
Ewe ooyo nkan , ao lo epo obo keta pelu
Ewe iyalode funfun onbe keta papo mo edu ti yio
Ewe iyalode pupa kunna dada ,Ao ko sinu
Ewe orijin nkankan, ao Koko fi eleyi ta lo
Odidi atare kan mo ebu te ifa osa meji sinu
Epo obo isasun tuntun yen ,ao wa da
Ose dudu eleyi ta lo mo osun lelori ao
tun fi te ifa osa meji, Ao wa da
Ao ge epo obo yen si ona meta, eleyi ta lo efun lelori ao tun fi
ao lo kan mo onbe eyokan ati te ifa osa meji, ao wa ja eku
efun die ao ko sinu nkan , ao lo asin gbigbe meta yen lelori, ao
epo obo ikeji na mo onbe keji gbe Ori olongbo lelori,ao fi
pelu osun papo ao ko sinu odidi atare kan si legbe otun
epo obo legbe osi,ao wa ko
gbogbo ewe yen lelori , ao jo IMULE OSO DAREKANRI
papo,ao ti lo ebu yen kuna Ao
Adiye ibile to ti n ye eyin
wa po gbogbo ebu yen mo ose
ti adiye yi ba ti n ye ni ojo
dudu, ao fi ori (Shea butter)
kookan, a o mu ewe ewuro kan
epo pupa, adin dudu po ose
soso, a o fi iye owo ti o ba
yen dada, ao ko sinu fitila oloju
wuwa sinu re ati omo ataare
meta, ao fi mafi we ni ago
kan soso, a o wa di ni ikobere
meta oru ni ojo meta meta ni
pelu okun igbo, a o fi si abe ite
wiwe re ooo..Akiyesi.. Ao yowo
ti a ti pese sile ti adiye yi yoo
oja kuro Lara fitila yen ooo.
ma ye si, a o se be titi ti adiye
yi yoo fi ye tan, ni ojo ti adiye yi
ba pa omo, aa o ra oga aaye ti lori, a o lo imi ojo ati eepo obo
yoo je iye omo ti adiye yi pa, a papo, a o fon le ori aso funfun
o wa ma mu omodiye kan, oga yi, a o fi sile fun odidi iye ojo
kan, ikobere kan, a o gun po awon ike yi, ( i.e ike meta ojo
mo ose aladi, a o fi eje eyele meta , ike meje ojo meje, ike
po, a o ko sinu ike funfun kan, mesan ojo mesan) , idaji ojo
bee ni a o se se gbogbo re keji ti ojo awon ike yi ba pe, ni
patapata, ike ti a o lo yoo je iye a o ji lo si ibi ose yi pelu iye
oromodiye ti o pa, a o kan kanhinkan ti ike yi je, a o kan
apoti iroko to le gba awon ike ilekun apoti yi ni eemeta, a o
yi, a o te aso dudu si inu apoti se awon adura yi Darekan'ri ori
yi, a o wa to awon ike yi sinu mi o gbebo 3*, darekan'ri aya
re, a o da aso funfun bo won mi o gbeedi 3 *, darekan'ri
oooo, eleda mi sare tete ki o darirekan emi lagbaja omo
wa gba ire aje re oo, adifa fun lagbaja o a o se adura bi a se
ori olowo nijo ti alamo dari re fe A o wa bu ose yi si ori
kan an, o ni bawo ni oso aye o kahinkan ni eyo kookan, a o ni
se dari aje kan mi, bawo ni aje de awon ike yi pada ti a o fi we
aye o se dari owo kan mi, bawo awon kanhinkan yi tan ninu ile
ni gbogbo oloro aye o se dari iwe o, ti a ba we tan a o fi
aje kan mi, awon aye ni o di awon kanhinkan yi le ori awon
dandan ki won dari aje kan mi, ose yi ni okookan a o de pada,
nitori olodumare lo dari re o tun di eyin ojo ti awon ike yi
gbogbo kan ewe adun, atewe pe ki a tun to de idi re.
atagba ati borokinni ilu ki
gbogbo won o parapo
IMULE ISENBAYE AGBA TA'YE Aso ibora funfun ti a ti fi bora
Agbebo adie dudu kan fun ojo meje
Iye agbe kan Aso ti won fi pa ale le nkan
Iye aluko kan
Ikode kan Ao la adie ni aya a o ko gbogbo
Orii nkan inu re kuro patapata, a o
Egbo ajeobale wa fi orii ra inu re, a o te aso ti
Eye olongo kan won fi pa aale sinu re, a o wa
Eha eke ile ko eye olongo ati awon eroja
Abo alaamu kan ako kan to se ku sinu adie yi, a o ya die
Aso ti won fi gbe ipese si eti ni ara aso ibora wa yen si ona
odo meta, a o ya teere bi okun ni o,
a o fi di adiye yen daada, a o fi
epo pupa se abawon si aso ti a koto o di alaro, aluko seyinkoto
fi di adiye yen lara balabala, a o o di olosun, odidere seyinkoto
jo ti a ba jo tan, a o ro sinu ado o ju iko idi re yebeyebe, a di fa
ato to le gba, a o fi aso ipese fun osa mejinigbati o se
eti odo ran apo asunwon, a o eyinkoto gbe awon iya mi eleye
gbe sinu re ni nkan bi aago wa si ile aye, osa meji ba eleye
mejila abo oru, a o te aso ibora mule ire gbogbo, emi lagbaja
to se ku yen silele ninu yara omo lagba omo osa meji ti
wa, a o tu ekuru funfun kan seyinkoto mo gbe igba eye mi,
sinu ewe, a o da etu oogun yi ki eyin agbaagba o wa ti mi
die si owo wa, a o te ni ifa osa leyin ki n ma sise laye o, e ti mi
meji a o daniyan si wipe leyin ki n kole, e ti mi leyin ki n
seyinkoto seyinkoto agbe seyin lowo, nitoripe igba eke n fi
owo ti ile, igba alaamu ni n fi oga gbigbe 11, opolo gbigbe
owo ti e ba ogiri, gbogbo 11 , obi abata oloju merin ipa
apapo eleye, e wa fi gbogbo 16, obi abata oloju merin ifin
agvara ti eledumare fun yin ti 16, ako alangba 16 , abo
mi leyin o, gbogbo eniti o ba ni alangba 16, ewe ati egbo
ki n ma ribi lo, e ba mi fo won ajeobale oojo , ewe egele
loju, a o se adura bi a se fe, a o funfun ati dudu , ewe akisan,
sare koje kiakia, won o gbodo egbo botuje funfun, gbogbo
pada de ba wa nibe o, a o lo ifun inu okete , odidi atare 11
fon ifun adiye yi siwaju ita ni o, Ao dun ewure yen sinu ape ao
won gbodo ba ni ita ti won ba ko eroja yi le ao wa jo papo, ao
n r …. wur ro sinu sere tabi akeregbe ao
kekere tikoiti ju ojo meje lo ,
mafi fokomu tabi kamafi epo epo obo yen , Ao tu gbogbo
pupa Laa. egbo tude yen lelori, ao fi odidi
atare kan lelori, ao da ewe
EBU EYONU ATUDE KIAKIA akoko bo monle, ao jo papo, ao
mafi ata ijosin ko ina re, taba jo
Ori ako aja kan
tan Ao lo kunna dada ao da
Egbo tude idi mewa
sinu Ike funfun olomori kan, ao
Epo obo tofe to atelewo
mafi fo eko tutu mu tabi oti
Odidi atare kan
original laro ati lale..Akiyesi..
Ewe akoko
Opolopo eyan lelo ebu yi ooo.
Ao koko fi epo obo te inu ape
ijogun ao gbe ori aja yen sori
ORUKA ONMO TO DAJU yi o, a o wa fi aso yen we ni ori
Ori eran eta tutu mo orun, a o pa ori eran eta
Oruka irin tabi fashion ring yen ni pansa, a o gbe kinni yen
Itanna ako ibepe sinu re, a o gbe omi ekun eleji,
Oga aaye kan a o da le lori, a o lo ri mo le ni
Ewe imule oojo aarin orita meta, a o ko ewe yi
Aso ti a fi nu ara leyin ibalopo tele koto ti a gbe, a o tun ko le
lori, ojo kesan ni a o lo wu, a o
A o pa oruka yi mo orun oga yi, gbe wa si ile, a o ko awon kinni
a o wa gun itanna ako ibepe yi, yen jade, a o ha gbogbo awo
a o san mo ori oga yi ati oruka ara ori yen, a o gun mo ose
yen papo, ko ni koja orun oga pelu, ewe to ti ra yen ati
gbogbo posoposo ti a ba ba
nibe, yoo ku egungun ori yen ni ale ana a o so fun, nkan to sele
kan, a o ma ta omi ekun eleji ni ojo ti won bi ati asiko ti won
die sinu egungun yen, a o si ma bi, gbogbo re ni a o ma wo bi
fi oruka naa pamo sinu re ni gba ti a n wo iran, ti won yoo
eekookan..Lilore...Ao bu tintin ma gbe wa fun wa.
ninu ose yi, a o fi fo oju wa
pelu ose yi ati omi ekun eleji yi,
ASIRI IPILE TI NKAN EYAN FI
a o wa ki oruka re bo wo, ojo
NLO DEDE NINU ILE WA
metameta tabi ojo mejemeje
Eran abo elede oojo
ni a o ma lo ose yi pelu omi
Eyele funfun tako tabo
yen, oruka yoo ma wa ni owo
Ewa funfun die
wa ni gbogbo igba, pelu ase
Agbado funfun
eledumare onje ti alejo wa je ni
Oka baba funfun yen, ao da ewa (beans)
Aso funfun opa kan lelori,ati agbado pelu okababa
Ewe owuro sinu re, ao wa fi aya eyele
Ewe ire mejeji wo egbe ile yen yipo
Ewe anu round ni emeta, toba je ile
Awo funfun olomori kan (land) ti won ti ko ile si rara ,ao
Agbon toni omi ninu meje fi wo gbogbo ori ile yen kan ni
Oyin gidi emeta, ao wa jaa ori eyele abo
ao ro eje sinu ise to wa ninu
Ao fi omi agbon yen gbo awon awo yen, ao ko gbogbo tinu
ewe yen dada ti yio kii, ao fi eyele yen lelori ao wafi ori
ase se idoti re, ao fi eran elede eyele yen lelori ao wa fi apa
yen sinu awo funfun olomori eyele yen mejeji bo, Ao wa da
omi agbon tafi gbo awon ewe odun kookan, ao lo ewe
yen lelori, ao da oyin lelori, ao meteta ta fi omi agbon gbo yen
wa gbe awo yen sori aso ao lo ewe yen papo mo iyere
funfun yen ao fi ideri re de die ao fi se eyele tako tabo ni
pada akogbodo si wo aseje lepo ni iyo pelu isasun
(open)mo taba ti fi ideri de ooo tuntun, omi agbon lao fi se omi
,ao fi aso funfun yen yi papo, re omi agbon na lao mu lelori
ao wa lo gbe koto si arin ile yen ni ododun ni oo, isasun yen lao
tabi ori ile (land ) yen, ao da ma fi se aseje lo akogbodo fi
yerupe bo monle, Ao wa ju isasun yen se aseje miran ju
eleye ako yen sile laye ko lo ko aseje yen lo.
ire wa fun wa..Akiyesi..Ao mafi
eyele tako tabo se aseje ni
Ao so okun mo oga yi ni aarin
ONMO OJU ORUN TODAJU meji, a o wa so okun naa mo
okuta kekere ti ko tobi pupo, a
Aaye oga kan to je ti ibile ti ko
o gbe mejeeji sinu awo ipese, a
tobi pupo
o gbe lo si orita ni ale, a o fi iyo
olongbo kan
kekere po ekuru funfun a o fon
igi koko orisa
yipo awo ipese yi, ti o ba di ojo
Aso funfun tabi owu ti won fi di
keji ni idaji kutukutu, a o lo gbe
oku lenu
kinni yi wa si ile, a o pa oga yi,
owu dudu ati funfun
a o yo okan re, a o wa ki bo inu
otin ogogoro oju ina
igi koko orisa yi, a o fi aso tabi
owu yen di, a o wa ko ni
ikobere, ti o ba di ale ojo ti a se
ise yi, a o bu otin ogogoro oju
ina sinu awo ipese, a o wa du
eje olongbo kan sinu re, a o so IMULE OSOLE OWO
ikobere yi si, a o gbe si ori aja
Eye kowe kan
fun ojo mokanlelogun, o pari,
Ewe ola tutu
enikeni ti a ba fun ni ikobere yi
Ewe awerepepe tutu
ki o fi rori sun, gbogbo asiri bi a
Ewe egele
se bi ni kekere ati bi o se n lo
Egun agbari inaki igbo
igbesi aye bo ni yoo ri loju ala,
1000 tuntun kan
bee ni won a si so ona abayo
Odidi atare kan
fun, sugbon osu metameta ni a
o ma re kinni yi sinu otin
ogogoro ati eje olongbo.
Ao fi 1000 yen we egungun akogbodo jade sita mo ni ale
agbari inaki yen , Ao fi si abiya yen taba ti lo gbogbo ebu yen
otun eye kowe, ao fi odidi tan patapata ao fi akara elopo
atare kan si abiya osi re, ao fi se sara.
ewe egele ati ewe ola te inu
ape ijogun, Ao gbe eye kowe
yen lelori ao da ewe
awerepepe bo, ao jo taba jo GBEWA OSO UNLA
tan ao lo kunna dada, ao ro Ori oka meta
sinu sere tabi ado atoo, Ao Ori ere meta
mafi omi aye tabi omi lasan lo Ori agbe meta
ni ale patapata taba fe Iye agbe meta
sun..Akiyesi.. taba ti lo ebu yi Iye aluko meta
Ikoide meta ma mu , aso funfun ( 1 yard )
Eyele funfun merin ao wa ni ki babalawo bawa ki
Igi unla ifa odu merindilogun si ebu
Ewe orijin 201 yen , ki ifa to dara sii , ao fun
Irun afin lowo , ao sope ko bawa ta oti
die sii ebu yen ao po lose , ao fi
Obi ifin oloju merin ao gesi 201 aso funfun yen tenu apoti iroko
, obi ipa oloju merin ao gesi , ao ko ose yi sinure , Ao ma
201 , ewe awerepepe , ewe ata fiwe ojo tabawe akoni jade nile
oluwere , ori inaki igbo ao jo po Ao sope eyin tolaye E lo gbe
inu ikoko tuntun , ao ma ta oti owo unlanla wa fun mi loni , ki
si lori ina ao tun gbe igo oti kan ewa ma fi bemi nise oooooo ,
sile fun awon alejo , won yio larin osu mejo a ma se etutu re
Eturu re.. Eje ka pa agbo Awo funfun olomori kan
funfun sita kafi se saara pelu Ose dudu abi aganyin
ounje fun awon eniyan. Aso funfun opa kan
Ao wa igbe ti a ko mo eniti o ya
die, a o po mo eko elewe ati
OSOLE DAGIRIJA epo pupa die, oun ni a o ma
Ologbo eyikeyi kan fun aguntan ati ologbo yi je fun
Omo aguntan kan ojo meje, ni ojo keje a o gbe
Ewe eepin oojo ologbo yi sinu ape, a o ko irun
Ewe abamoda oojo ile barber ati ewe molagbao le
lori, a o wa ko gbogbo owo yen mo ose, a o ko sinu igba aje, a
le lori, a o jo, ti a ba jo tan, a o o ro eyiti o ku sinu ado ato to
ro sinu seere kan, a o wa ma le gba, a o ma we ose yi ni
bu ebu yi a o ma fi ro ekuru fun asiko ti osupa ba wookun, a o
aguntan yi je fun ojo meje si ma fi ebu yen je eko ninu
miran, ni ojo keje yi, a o fi igi lu ewe nii kete ti a ba we tan, oru
aguntan yi pa, a o wa la ni inu a ni wiwe re o a o da ebu die si
o wa gbe ado yen si inu ori eko elewe a o te ni ese kan
aguntan yi, a o ko eye oobe yi otura, a o wa pe gbolohun re, a
si ninu, a o wa gbe sinu o wa ma bu eko yi ni okele
agbada, a o ko awon ewe yen kookan, a o ma fi ba oju odu
bo mole, ti a ba jo tan a o pin si yen je, leyin okele meje a o di
ona meji, a o fi oyin po okan iyoku mo ewe, a o fi pamo di
ojo keji, a o lo ju si oju ona ti fi wa gba oore oro, dagirija 3*,
gbogbo eniyan n ati owo ile alara, ati ti ajero,
gba..Ofore....Dagirija3*, isun mo ni ti owarangun aga nko
omi alada odo, a bumbutan won ni dagirija ti gbe lo,
lomi awon agba, dagirija3* dagirija o ya sare lo ilu bayi
olowo ile abara funfun, abese bayi ki o lo gba owo owo won
funfun, ara n ni mi ni mo ko wa kiakia, nitoripe mo fe lowo,
egbin ile alara je, ara o tu mi mo fe kole, mo fe ra motor
mo je egbin ile ajero, otura ti n boginni, mo fe ba egbe pe
tumo le ninu idagiri a i ri nan, lawujo, emi naa fe joko laarin
ninu idagiri ai ri lo, dagirija3*, awon atata eniyan, bi igba ori
owo ile alara ni mo fi wa ya olowo ba joko ti mi o ba si ni
owo lodo re, oro ile ajero ni mo aarin won ki ara ma ni won, ki
ara ma tu emi o, ki ara o tu mi Aso funfun opa kan
si owo, ki ara o tu mi si oro, ki Igun tope toni ifun ninu
ara o tu mi si ire gbogbo Owo osi iwaju elede
EWORE a kii we ose yi ni asiko gbogbo owo ti ana patapata
ti osupa ba wa nita o gbogbo Akuko adie alawo meta
ojo ti a ba lo ise yi aso funfun
ni a gbodo ma lo o , ojo meta ki Ao te aso funfun opa ka yen
a to lo, ati ojo meta leyin ti a sile , ao gbe igun toni ifun le
ba lo a kii sunmo obinrin o. lori ao la laya ao fi owo osi na
si ao ko gbogbo owo tana le
lori , ao ko igbo mimu le lori
lopo ewe orijin , ewe anu ,
OSO OWO KIA KIA ewe aje sefunsefun , ewe
awerepepe ao fi aso yen di kaye mi gun , sawerepepe
gbogbo re papo ao jopo aoro walo ba pe olowo , olola ilu yi
sinu seere nla kan , ao pa wa bami loni , ewe aje loni kiiri
akuko adie alawo meta boo ao taje kiiri ire gbogbo , orijin
le iyere mo lara , ao ro eje adie loni kin won fu ire owo unlanla
die sile ta so lelori ao wa gbe jinmi loni , ire ile , ire oko rira ,
seere na sinh asuwon ao gbe ire gbogbo lode isalu aye , ire
ko ori gun yara ti aba fe bere gbogbo ni ke wa fi basiri mi ,
lilore akogbodo di lenu mon taba sin araye tabala , ara orun
Lilore .. Ao ma bu sowo osi , ni lani , eyin to laye edeyinbo
owo ti otun bapa osi niika ki ke wa lo dari olowo olola olori
okunrin ati obinrin na kowo ki won ma gbere owo unlanla
owo won wa fun mi , igun loni wa fun mi ni gbogbo ojo otin ni
ama fi lo larolaro odaju saka Ewe ola lopolopo
ogun owo gidi nii.
Ao ko awo elo , won yi sinu
ikoko kan Ao wa ko ewe ola
igbo lee lori lopolopo , pelu
OSO OLA TODAJU odidi atare kan aojo po , Ao ro
Odidi ori inaki igbo kan sinu seere Ao pa akuko adie
Odidi ori akala kan fun ogun yii NB... Ao pin ogun
Odidi eye igun kan naa sii , ona meji Ao lo idakan
Iye osin 16 fun osu meta, ale ta eyokan
Iye aluko 16 toku , awa meji le lo ogun yii.
Iye agbe 16
Okoide 16
ko gbogbo ifun ako alangba
EPE ATARI AJANAKU TO meje na sinu iwo yen na ao wa
GBONA fi otin po ose aladin oyo ao ko
Eyo atare 16 sinu iwo yen ao je ko de oke ,
Ata ijosi dudu taja loojo 9 ao wa fi aso pupa we , ao dipo
Ata ijosi pupa taja loojo 7 daadaa ao wa bu otin senu ao
tun sori iwo yi leemeta ao
Ao ko won tele iwo agborin abi daniyan si lati ba mule lehin na
iwo malu ao wa pa oga oye kan ao wa fi aso pupa we lenu ao lo
ao ko gbogbo ifun inu re sinu gbe epe yi pamo sibi kan to
iwo yen ao tun yo ahon oga na pamo fun ojo meje (7days )
ao fi sinu iwo na ao tun ge ase lehin ojo keje na oti beere lilo
oga na ao fi sinu iwo na ao wa niyen oooo epe sanpona gidi
niiii...Lilore... Ao yasi leemeta Yepe amon die
(Aniyan wa ) ...NB... oku Oti ogogoro
alangba mejeje yen ati oga yen
ao ri mole ni ooooo...Erore... Ao gun po ao wa toju oti baba,
taba lo epe yi tan ao fi blade to oti ogogo lao fi po erupe yan
eje apa wa ao la eje na pelu ao wa mo ni sigidi oju meji, eti
epo pupa ma fi seere ooooooo. meji, owo meji,ao toju ikoti
irin, ikoti ide, ikoti oje, ikoti
baba, ao ki ikoti irin bo ni ejika
mejeji ao fi ikoti iyoku si ni
SIGIDI IRANSE OHUN KOHUN orikerike ara, ao fi omo
Ile ikan alade werenjeje se oju re mejeji ao
Ile ode gbe sinu awo sobi ao wa lu
idodo sigidi ako ewe ina, ewe sidun 3x, Oni ohun oni anu
esisi, ewe alangba, ati ewe Eniyan loju, won ni kinni oduro
oloyin ao lo papo ao ko sinu si dun fun, ikoti ide kisun kosun
idodo sigidi naa, afi amon mon oju, ikoti baba ki sun kosun oju,
pa da, ama ao ito Idi eni tio ma ikoti oje kisun kosun oju, ikoti
lo sigidi yan po ewe ti alo yan irin kisun kosun oju, kankan
ki ato ko sibi idodo sigidi yan lewe ina jomo, warawara
sugbon ao da ewe yan si meji lomode toko esisi bo, ile ogba a
ni, ito idajin ni yio je, ao wa ko ona ogba nise ewe anragba,
gbogbo ewe ti a ti lo pelu Omo kile ma gba L omo L tekun teje
atare tio po dada sinu seere ni esinsin ode fi mo ile tire,
..Ofore..Asure ganraa 3x, arina enikan ki fi to saara ko duro ao
gerere 3x, oburinburin duro ma min seere yan fun ao wa ni
ko ki enikan ru adie niwaju re ti OSE ANU TA FI NPADA
aba fe dan wo sugbon ma OOLORE
sofun pe adie lafun o mio fun o Epo obo die
ni eniyan pelu ogo olohun yio Ewe taba tutu
mu eje adie yan tan adie yan Ewe ola
yio siku, sugbon tio ba ranti Agbon kan
wipe adie ni mo fun o yio pa Ose funfun
adie yan enito ru adie yio subu Ike funfun
lule, ao wa fun lepo pupa. Oyin gidi
Eyele funfun kan
Ewa funfun die
Agbado funfhn die
Oka baba funfun die
ose yen papo Ao ko sinu Ike
Ao gun epo obo ati ewa, funfun olomori kan, ao mafi
agbado pelu okababa yen, ose yi we laro ojo sunday,
kunna dada, ao fi ase se ko le monday ,ati thursday
kunna dada, Ao da sinu ..Akiyesi..Ao je ki omi iwe yen
nkankan, ao wa fi omi agbon ko gbe mo wa Lara ni ooo,
yen soak ose joy yen ,ti ose yen akogbodo nu omi ara wa nu oo
ba ti ro dada Ao gun ose yen (2) ojo taba ti we ose yi aso
papo mo ewe taba ,ewe ola blue tabi aso funfun lao wo
yen dada ao po ose yen mo sule ojo yen..Sara re.., Ao ra
nkan tati gun yen dada, ao wa agbado funfun agolo kan, ewa
fi eje eyele yen po ose yen funfun agolo kan, oka baba
dada, Ao wa tun fi oyin gidi po agolo kan, ao da gbogbo re
sinu Ike funfun ao da oyin gidi Aba 16
lelori, ao fi se sara si orita Sekeseke 16
meta ti gbogbo ese ngba dada, Agogo kekere 7
ao se sara yen ni ojo taba we
ose yen tan niooo. Ao ran aso fun un (idasa funfun
lo bee) alabala iye ki ye tio ba
wu wa , ao wa ewe ailu tutu
oojo ao toju okete tutu ao gbe
ASO OGUN lo poroporo apata ao koko gun
Aso funfun awon okete yan pelu ewe yan
Ewe ailu tutu na ao wa po mo ori yan ao wa
Okete se aro olukuta ao ti gbe ikoko
Oruka dudu 16 yi ka ori aro sugbon ao wa ni ko
igi si rara ao wa toju oruka gun lori ao wa fi atare kan
dudu 16, aba 16, sekeseke silegbe ao wa jo ti aba jotan ao
16,pelu agogo kekeke 7,ao to di ni ikobere kekeke ao yo
meta siwaju merin ni eyin edun aara si inu epo pupa ni ao
gbogbo iyoku ti , oje 16 yan wa somo ara aso yan ao wa
mejo niwaju mejo leyin lao se yinbon sii , aso yan wo mofi
ao wa fi awon ewe yan ra aso olohun ti ao gbodo pe jeri iro
yan ti yio lemo lara dada ao wa iwo ti o ba fe yinbon yan sun si
gbe sinu ikoko ti à se aro fun eyin dada tabi ki e ri igi fun
yan ao bu omi tutu si Ade fun ibon yan ki oma seni ni jamba
ojo meje ao wa sa ni iboji ti ao ma gbe si aye owoo.
oba gbe ao gba igbe alaboyun
si nu isasun ao fi edun aara kan
Ewe karo lopolopo
OSHOLE AJE
Odidi ori inaki igbo kan Ao jo po ao wa ro sinu, seere
Ori aparo meje nla kan ao pa akuko adie nla
Ori eye akala kan kan fi bo , seere na Ao ma fi
Ori igun kan otin lo laro laro pelu eniyan
Ori ikun kan adura owo.
Ori eye karo kan
Oga oye kan
Omo atare 201
Obi abata ifin 201 EPE TO NJE LESEKESE
Obi abata ipa 201 Egbo oro adete oojo
Ewe apada 201 Oko oka ojulowo
Etu ibon orijinal fun ija , ao ma lo iyo ku fun
Ikoide irin rere, ao ma fi kan ahon soro
Ikoide baba ao ma la epo pupa taba lo tan.
Ikoide oje