Está en la página 1de 2

ISORA ITUWO AWON AJE

Abo adie opipi, Ewe ina pupa, Eso esisi, Eso ido, Eso

werenjeje, Odidi atare kan, Oga gbigbe 1, Eku asin gbigbe 1,

Sise re : A o pa adie yii, a o fi eje re pa ara seere ti a ti pese kale ti a o

ro ebu ree sii, a o ko gbogbo ifun adie yii jade lati idi re, a o ko

ewe ina pupa, eso esisi, eso ido, eso werenjeje, si inu re lati

idi, a o wa ko ifun re pada sinu re, a o fi atare dii nidi, a o gbee

sinu agbada, a o fi oga sii legbe otun asin legbe osi, odi jijo

papo, ki a to gbe adie yen sinu agbada, a o bu epo pupa si

origun meteeta aro ti a fe fi jo ise yii, ati si aarin meji aro yen

gangan, ti a ba njo ise yii lowo, a o maa bu ata ijosi sinu aro

diedie titi yio fi jo tan. A o loo kunna, a o roo sinu seere yen.

#Lilo re... A o bu die ti fe lo, a o tee ni ifa osa meji, a o pe ofo


ree sii, a o wa fi foko mu lori odo, ale patapata abi Oru ni a o

maa lo ise yii o. #Ofo re... Aje kii je eso werenjeje, aje kii je

eso esisi, aje kii je eso esisi, aje kii je eso ido, aje kii je ewe

ina, aje kii je oga, aje kii je eku asin, olopipi kii roju fo

igannan, ojo ti o ba so wipe ohun yio fo igannan, ojo naa ni

ashiri re yio tu, yio se esin, yio se eleya, aje kaje to ba ni ohun

yio se emi ......omo... , ki ashiri re ko tu, ki o se esin, ko seleya,

etc. Adura. O daju pupo.

También podría gustarte