Está en la página 1de 1

AGBELEPOTA TOGBONA.

E ku ojo meji meta, se daada ni moba yin, aburu koni sewa, koni se emi wa. Ti aba nse Ajo asiri bibo,
osole, ejeki ama gbiyanju ise aseta, arobi, agbelepota,ki owo aye maba teyan. E bami dan asiri yi wo, e
jeki a se fun awon omo wa na pelu. Ise na niyi;

Aowa opolo ooye kan(Life Toad), aofi iyo(salt) ra ni gbogbo ara, ao bo(bury)

mole laaye, a o lowu ni ojo keji, yio yi ku, a o ju sinu ape ijogun, aofi odidi atare kan jo papo, ao lo Kunna
daada, gbere mesan si ori fun okunrin, gbere meje si Ori fun obinrin, ti enikeni bafe sa ogun buruku siwa,
tabi o n peri wa laida, ara tita ni yopa onitoun, ti kosi ni eero. Opolopo eyan lelo ninu ebu yi. Asiri ni, ko
nawa to#500. Sope apa ota koni kami.

IKILO PATAKI:- RIDAJU WIPE O FI COMMENT RE SE ADURA TOBA WU E FUNMI, TI O BAFE KOSISE FUN
O(LIKE COMMENT AND SHARE. MASE AFOJUDI OO KOLEJE FUN OO)

IWO TI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE ABI TI O MA BI OSE FESE MOLE SE FUN YIN PE
NUMBER MI TOWA NISALE ABI KO MESSAGE MI LORI WHATSAPP.

LATI OWO OLUDASILE YARA IRANLOWO NIPA LILO EWE ATI EGBO FUN IWOSAN ATI FUN ONA ABAYO
(((OMO ORISA)))

FUN IBEERE ABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI OUN DOJUKO CALL OR WHATSAPP TI O BANI
IGBAGBO ((08103405255))

También podría gustarte