Está en la página 1de 14

Ope Pataki lowo olohun Toni ki ase aseyori Lori IWE AKOKO EIYE AIYE ope Pataki lowo

oremi ogboni ors ifayemi omo ari IFA NLA jogun nilu ijebu
Mowa ki gbogbo omo iyami ninu tewe tegbo wipe yoma juse funwa oooooo ase
.
.
TABLE OF CONTENT

OGUN OGBE INU (ULCEr


ATUDE
IMULE ADO META
IMULE EYE WONU EYE
ATUDE ELEYE
BULLET PROOF
BANTE OLOJU MEJE TANSISE MEJE
AKABA
OSOLE TUTU OLODUN MEWA
AKESU 5.000 LOJO
ONIPANSA OWERE
OSOLE ALAPOTI
OWIWI GBEJOMIRO
AGBOJO 100.000
OKIGBE
MALU
ASANYAN
AROBI TINPOTA LOJO
AWURE CONTRACT GBIGBA
ILEKE ADODUN..FAMILY PLAN.....KERUKE
..TONIC
OSO INU.
ASE I
OSO IFA
MAYEHUN
ASE TANPA IGI LOJO
ORUKO Y00h
BANTE OLOJU MEJE TANSISE MEJE
hmmmm
ope pataki lowo oluwo of igberin land ohun lo koko komini bante yi kotowa diwipe mose alaba
pade re ninu iwe baba tobimi .
wahala bante yipo sugbon maro iwo omo iyami mafi sere.
.
awon ise meje tanse ni
alupa
foban
owo
kojumaribi
okigbe
bi eyan na ibon sie lasan tobayi ikan lara awon molebi re lopa
ase
.
awo dudu legbe otun funfun legbe osi pupa larin
inkan tafise okun bante na
aja ti motor pa awa mu die ninu ifunre tole ka idiwa agbe sinu aso funfun awa loran lawo funfun
ohun lamaran awon awo meteta yimo tio dabi sharp bante
n
awa lori mole sinu sare oku obinrin fun ojo meje tokunrin na fun ojo meje leyin eleyi atise awon
etoyi kale
ti awon ojoyen batin pe taloyo amulo odo onisan na won ra awon kiniyi mo
Eku eliri kan akibo inu epo atare awe ni ikonbere
Irun ori eniti oni bante ajopo pelu odidi atare kan aro sinu ado ijamo afi ig osunsun de aran ni awo
dudu amafi miko .
Abaweku adieakuku todo dada amati owo coward tikoluju kanbo pelu atare eyokan awe ni aso
funfun aran ni awo funfun
.
Iwo etu kan ewe odundun ajo ati eyokan aro sinu iwo etu avi awo ijimere dilenu aran lawo dudu

Atare odidi kan ao fi awo dudu pa asese wa palawo ijimere


Omonle kan avisinu owu tutu aweni owu pupa apani awo pupa
Omonle kan avisinu ile atare avi eyo atare kan si aweni owu dudu ati funfun
.apani awo ijimere
Ideri oti 33 meji avi eyo atare meje ati werenjeje meje aweni owu dudu ati funfun

leyin tanba ran mo tan awagbe sinu oru adepa agbelo orita meta arimole nibe fun ojo meta leyin ojo
keta odi lilo inu oru yi niyo magbe ibiti asigbe oru yisi ama pa eje akuko adie round oru yen ni kato
lelo bante yen

oruka yahoo
ori ejo oka tutu toni ase lenu ako oruka ide merin si lenu ati ewe esisi pelu odidi atare kan akibo
lenu odi inu ape jijo po afi ebu e singbere si orun owo mejeji round amafi oruka yen bowo ati ese
oju meji osi gbodo ri oruka yen mo
Ogun ulcer,ewe tomato aofi omi osan we we gbo ao ma min diedie

[: OGUN OGBE INU (ULCER)


ALOMU GIDI, OGI FUNFUN, Ẹ FUN OLOSA OKO, ELUBO I Ṣ U GIDI, OORI, AO L Ọ
GBOGBO RẸ PAPỌ, SÍBI ỌMỌDÉ NI YIO MA FI MUN PELU EKO GBÍGBÓNÁ.

[: OGUN OGBENU/ULCER:KUKU AGBADO ORI AKITAN,AO SA TI YIO PO DADAA,AO FI


ODIWON ATARE ATI IYERE SINU RE AO JO PAPO,ENI NAA YIO MAA FIMU EKO TUTU

*OSE ATUDE Eleye


1. Oga gbigbe 4
2. opolo gbigbe 4
3. Asin gbigbe 4
4. Ako alangb 4
5. Epo obo
6.Epo igi nla
7.Ewe orijin
8.ewe mafiowokanmomi funfun ati dudu
9.Afomo apata
10.egbo tude
11.ewe afeloru
12.oronro malu
13.ose dudu
14.ologbo dudu
Sisere......ao gun gbogbo awon ki ni yan po, ao fi oronro malu se omi re , ao po papo, ao ko si inu
ibi kan , ao pa ologbo dudu yan le lori..ao tun po mo ose ao ko sinu ike tabi igba..
N:b...Ale lao maa lo pelu omi to gbona...Hmmmm

: Ìlékè tí obìnrin fi ngba owo lọ́wọ́ ọkùnrin


èwe omisinmisin gogoro tútù èwe emin ilẹ̀ tútù àsè ọkà werepe ao lọ papọ sínú ike kan ao dá oyin
ìgò kan lè pẹlu ọ̀pọ̀l ọ òbúkọ omi peanaple adùn sugar onikoro mewa ao dá sí èwe awede pẹlu emo
ajá ao jo mejeji yìí loto ao dá ẹ̀bù díẹ̀ sínú oyin yìí ao wá ju ìlékè sínú rẹ fún òjò méje ao wá sá kí ó
gbé ao má fi sidi ẹ̀bù tí ó kú yẹn ao pò mọ oyin ìyẹn ni ao má fi pá iyamopo ìparí
.

IFONU FUN OBINRIN


Oyin gidi
Omi osan were
Oronro maalu oojo
Oti shinap
A o da die ninu agunmu oke yi si , mimu fun obinrin na ti o ba nse ode lowo
.
.

asanyan
.
igi agana ao ge die nibe ao wa omo atare igba 200 awa lu agana yen lara awa ko atare si ao wa sa
tio gbe dada awa gun tio kuna ao wa ma fifo nu ti nwo balu eniyen ti enia ko balu won pada olode
nio mu enina
taba feko mu afi kalu pada
.
.
AKABA
ao toju aba kan igi abo ewe bara ojo etu ibon igbe ewure ati agunta ao gun po pelu ogide omini die
ao wale mo ara igi abo ao wafi owu dudu ati funfun wemo ao waka aba molara
.
ofore
abo nibo ewure loju ti ewure fifi oju re ra ina abo nibo aguntan loju tifi ojure ra ina ohu ti ina baba
etu so ni etun gba ohun timo baba lagbaja so loniyi ni kogba

.
.
MALU TOGBONA
ao lora ado kekere eja aro atare aja kan ao la enu eja aro ao ki atare aja yen si ao fisile ti yo fi ku tan
awa jo ao ro sinu ado kekere yen afi igi kandi lenu ti ado yi banbe lara wa ti enikan luwa akan lo si
enu re kale ni ni ilele nio .
hmmmmm
.
.
IMULE ASINA OWIWI GBEJO MIRO
ori akala 1
odidi kowe olori dudu 1
eye owiwi 1
eye ologesa 1
iye agbe 11
iye aluko 11
ikonde ..11
obi ifin oloju merin 1
obi ipa oloju merin 1
ewe egele funfun
ewe afeloru
ewe oriji
jijo po ao teni osa meji ao pe ohun rese ao mafi fokomu ni agokan oru
ofore
gbogbo eiye ni gbejo ro fun owiwi ti ebo laiye ebo laiye ale ni akala ma ngbe losi ode oru bi oku
baku kowe ni tufo re ti ojumo bati umo loni bimo batifi owo otun gba owo be nikin mafi owo osi
gbowo oriji loni ki e fi gbogbo ore aiye jinmi [adua]

MAYEHUN TI JE TAARA.......
Ao to awon eroja Yi sinu iho malu Nla bi ati ko Yi
1,alakan kan
2,oga kan
3,opolo kan
4,adaripon kan
Ao ti Fi omi isa oku gun ewe atewogba mo ose dudu daada,ose Yi ni ao Fi Bo iwo malu Yi Lori
leyin ti ati ko awon eranko Yi si
Note:-gbogbo awon eranko Yi ooye nio,ao wa Fi aso pupa Bo Lori
Akiyesi:-ti a ba ti Fi aso pupa Yi Bo Lori ati Di eti re niyen,ti a ba Fe lo ao yo aso pupa Ori re ao
pe ohun re si,ao wa Fi ahon ba *3
........OHUN RE.........
Ase alakan ni akan Fi pomi si Ile re
Ase oga ni oga Fi pase fun orisa oke
Bi opolo ba dun ni ipado egbere ngba ni
Ase alamu ni fi duro lara ogiri
Gbogbo oun ti emi lagbaja omo lagbaja bawi loni ki o Di ase
Ose loni ki o se
Atewogba loni ki o gba
Igbe Nla ni ti malu o Di ase
Ero re:-ao ma la epo pupa leyin lilo...

ADE ESU 5000 lojo

Igun oyee,ao Wa yara NLA ti awanikan nsu,ao palemo gbogbo eru inu yara ye ao fi lgun yee
sibe,ao nifun lo nje ti oo ba di ojokeji ao lora lfun malu,ao mu laylon siga aoki lye owo tobahu
Wa boo inu re,but kogbodo ju 5000 loo,
Ao dale fun lgun yee koje,lari lseju die lgun yee mapo gbogbo ohun toje ye,
Ao gbe lgun ye ao lamole yio kun lekan na,ao gbe sinu Ape ljogun tuntun pelu atare kan,aojo ninu
yara na,
Aopo lose ninu lkoko Miran idi lkoko kini keji ye kogbodo kanle oooo,ao ko owo(money)ye
lemole,ao gbe Ose ye le orii lkaraba,ti afi gunle ni koro yara Wa,ldaniloju nipe ni ojojumo aiye ni o
maamako lye owo toko sori Ose na.
Ogbodo sii Ose yewo mo
N;B lwo ati lyawo re lesun yara na kosi ewu,sugbon Obirin kogbodo deebe lwo nikan loni anfani
re,

i: Ohun reee ti abako owo (money) ye le lse na Ao sope ajepo niti lgun 3time
Ti aba bo lkoko yetan aogbe owo le ao tusope Ajepo niti lgun eyiin tolaye ooooo,owo (money) mi
ti lgun jeyii ki oo mapo fun mi ni ojojumo

.OSO IFA TODAJU BIKU.


eyin adie ororo tomo daadaa 40 eiyele fun fun kan opolopo ewe Oyo obi ajopa 4 obi ifin 4 ao Jo
po ao da adin eyan mo epo pupa ori ao gbe kana tobayo ao da etu naa si ao yipo daadaa ao da si ona
meta ao fi apakan sinu lofinda ao ma fi para ao po apakan mo ose dudu awe apakan toku ao ma fi
mu eko gbigbona ni ojo alamisi ni ao ma lo meteta papo AKIYESI ojo alamisi naa ni ao se ise yi o
odaju

OGUN OWO OLODUN MEWA TODAJU-


.
Odidi igun kan,odidi aparo kan,odidi lekeleke kan,iye agbe 9,iye aluko 9,ibi omo
oojo(placenta),ewe ola topo,ewe aje,tannapowo,ewe ilufemika,aojo gbogbo re papo pelu odidi atare
9,ao lo tiyio kunna daada,ao mafifoko tutu mu lorita meta fun ojo mesan taodaju

pelu ohun re.OHUNRE-ero ona egbe owo temi wa funmi o,bi omo tuntun bawo ile aye a busi
ekun,bi agbe bake,agbe egbere a gbo,bi aluko bake,aluko egbere a dahun,eyin eroo aye ooo,egbe
owo temi wa ooo.Omo ti a lo ibi re yi yio ku ni ijo keta,sugbon eniti o lo iseyi yio ku leyin odun
mewa.ODAJU BIIKU NIO

.
.

OSO INU
aso Agba kan onfa oka onfa ere ifun ako okete odidi atare kan ao jopo ao to sinu ado ide
Lilo re
Aora eyele funfun kan ao jini aro layiti Soto siyan ao wani ihoho ao da wbuna si ona meta ao lo
apakan
Ao da eje eyele yen si Lori awa fi ika arin ro papo amaka owo seyin awa awa fi ahon LA emeta
lama nlo larin odun kan

.KERU KERU ADODUN TI AFINGBA OWO LOWO OLOLUFE WA


.
ikilo
Dakun OMO iyami mafi sere ooooooo
Okunrin ni abi obinrin ti abalo ise yifun odaju gbogbo inkan ti aba bere lowo re ni yose
.
.
Ori oka kan tolanu le ao fi yerepe kan bo lenu ati atare aja kan ao jopo ao fi Ori po abi oyin amafi
pa Abe wa

.
:
OSE OSOLE BASIRI OWO TODAJU. ALAPOTI

Omo Aja tiko laju aojo pelu Odindi Atare kan, ao ko sibi kan, Ileke Itun topo, Ileke Ifa topo, Abere
topo, Yanrin Okun ati Osa, Ori Odidere(3), Ori Agbe(3), Ori Aluko(3), Iye Agbe(3), Iye Aluko(3),
Ikode(3), aolo Awon won yi po aopa mejeji po mose aowa ko sinu Isasun titun Olomori, aosin Owo
Eyo ti o balu ju(101) ni Owu dudu ati funfun aogbe ko Isasun yi lorun ao wada Aso funfun bo lori
aose wa fi Omori re de. Aose Ose yi ni Ojo Saturday aose Sara Eran Obuko fun ni Ojo Sunday,
aoma bere si we ni Ojo Monday. INU apoti lama GBE ose yen si
.
.

OGUN FAMILY PLANNING. ODUN KAN ATI OSU MEJI LOMA LO LARA:
.
.
ESO IYALODE FUNFUN AO yo funfun inu e kan ama lo bi tablet ,to ba di ojo keta ti ati lo ama
mu agbo jejdijedi OMA bere ise ni ojo keta ko ni wahala kankan beniko si (repercussion) odunkan
leyi fin sise
.
Part 2
nigbati obinrin ba nse nkan osu,ao fi owu soju arawa moju ojo keji ao jeki owu yipo die,ao wa yo
laro ojo keji,ao wa ja ibi ti eje yen ba soak dada ninu owu yen,ao so iyi toku nu,ao wafi iyiti a ja yen
sinu efe owu miran,ao fi oko atare kan si legbe,ao di niko bere pelu owu dd ati ff,ao wa ju sinu igo
cream to de dada gan,ao wabu adin si ninu,loba pari ooo,hmmmmmmmm bi ogo ti nje ti Olorun
onitoun kole loyun.
ERO RE>ao shi igo adin yi,ao danu,ao yo ogun yi,ao tun ka sototo,ao ko danu,lehin eyi ti a ba
sunmo okunrin hmmmm,a nbo waje rice
.

OOGUN FETO SI OMO BIBI (family planning)


.
ao lo pa eepo oparun ni apa soke[ao pa eepo yi lati ile lo si oke] ao ni je ki o kanle mo ti aba ti paatan
ao loo pelu iyere ao fi se aseje pelu eja aro kan ao fi iru,epo ati isebe sii ao ni je ki idi isaasun yi kan
ile mo ti ao fi see tan ati ti o bati jinan ao soo si ori nkan ti o ba ti tutu obinrin yen yio je aseje yi ni
ori iduro NB:ti aba ti fe ba ise yi je ao lo pa eepo oparun yi ni apawale ao tun see be ao so aseje yi
si ileele obinrin nan yio joko sile jee
Ileke family planning
.
.
.
ao wa obuotoyo ati ileke eyikeyi ao lo si idi ako ibepe ao pani pansa ao ki ileke yi si ati obuotoyo
ao wada adin dudu le lori ao de pada ti obadi ojo keje aoloyo kuro obinrin yoo mafi sidi.Toba ti yo
ileke yen,ti won fi basun yio loyun ooo

.
.OKIGBE
IHA ide iha one iha baba ikoti ide ikoti baba ikoti one oruka ide oruka baba oruka oje ao pa isu igo
ni pansa ao ko gbogbo elo yen si ao yagbe so ao waloko ni ojo keje ao mafi sowo
.
.

.
Family planning fun obirin kan re to sure.obi lakiriboto.eku onigba ila.(Eku yen man ni ila lara)ebere
lodo awan lekuleja,gborigbo ako ibepe,iyere.or ata ijosi.elo gbogbo eroja yi po.efi se obe fun obirin
na je,lepo niyo.no maggi oo.NOTE ojo gangan ni aaro kutu hai ti obirin yen ba ti pari nkan osu re
ni yio se aseje yioo.tia ba wa fe loyun pada nko, a o lowa wa gborigbo abo ibepe ati obi alawe
merin.wan tun ma n pe eku yen ni eku ago,aotun fi se ASEJE lekeji.

.
.
Yio Mun 100,000 Wa Lonakona
.
.Eyele White Aola Laya Owo Eyo 16 Tikoluju Aokosi Owo Titun Eyikeyi Naira. Oga Aye Kan Atare
Kan Ao Ko Si Aya Eyeleyen Ao Fi Owu D Ati F We Daada. Ao Jo Pelu Atare Odidi Miran Aojo Ao
Ma Milk Lo Laro

.
.AWURE CONTRACTOR
.

Tagiiri nla kan,ako eye ega aaye kan,egungun ajiyo die,awo ekun die,odindi atare aja kan,a o da
taagiri ni PANSA a o wo egusi re jade,a o ko awon nkan yen si bi ase to soke yen a o ko iwonba
egusi ti awo jade toba gba sinu re,a o fi omori re de a o jo papo a o ma fi hoti loo.
.
..

.
.
APA OTA RUN-
.
.EDUN ARA OJUDA,AOBU DIE NIBE,AOJOPO MO ORI AWONRIWON KAN,ORI OGA
KAN,ORI APAJE,SOSO EYIN OPE,OKO ATARE KAN,AOJOPO AOLOPO AOFISIN GBERE
21 SI ORI WA,TI ORI BATINSE BI ENIWIPE OUNFO WA,AOMA FOWO GBA ORI WA
LEMETA AOMA SE EPE FUN AWON OTA WA

.
.
.
.
Abaoojo To Yara Mun Mali Gidiwa,,
.
,oga Aye Iye Agbe3 Iye Aluko3 Iye Osin3 Owo Nla Kan Ao We Gbogbo Mo Ara Oga Pelu Owu Dd
Ff Aojo Pelu Atare Kan Aofi Foko Mun Ninu Koko Yen Na Ao Lofo Kokoyen Mo Orita Meta,ikoko
Titun Nio Inure Na Lao Ti Lo Kun Idire Kogbodo Kanle.
:
.
.
NIPASAN_OWERE
Ori panduku AKO 1,
eye ologesa, 1
Oga gbigbe
1, ewe opoto topo,
atare odindi 1,
aojowanpo aolokunna aoteni ifa ejiogbe aope ofore si, aowa oruko kekere Kan aopa AOKO Gbogbo
nkan inure aoda Igo epo pupa Kan lelori ninu koto aobomale aoge eran to seku kekeke aodin pelu
epo pupa aokowan sinu igba eru aobu epo lelori aotunpe ohunresi aowagbelosi orita tabi ori Akitan.
Ofo-onipasan owere ni oruko tianpe ifa, oge tide Eiye ire ni oruko tianpe Eyin iyami osoronga
ebosode ilu elogba owo ode ilu wa Gbogbo abati alagemo bada ni orisa oke ngba Eyin iyami
osoronga akifi Odindi eniyan rubo komagba obuko yi Niki efise nkan bayibayi funmi loni ejiogbe
logbe owo temi wa funmi loni ase. Aomabu ebuyen se ipese died

.
AWORO POKIKI
ori elede tutu toojo,ewe aje aolokuna aofi ori ra gbogbo ara ori elede yii aowa fii ewe yi bolara
tikontyphoid
okojure sinu ile aobomole walahi ESE konida lodowa iba oooo
:
.
.Ogun typhoid,

ao si die lara epo ara igi mangoro, osan we we/ oronbo die, aogun lodo, ao da si inu kondoro, ao
ro omidie si, ao jin papo. Lilore: sibi meri ni emeta lojuman fun ojomeje. Alelo pelu Peak milk tabi
eyin adie agric/ Ibile.
.
: EBE AWON
SIOO
. Opolo 7 eku asin 7 oro agogo .a o Jo po. A o fi ose dudu ko .a o wa ko ose yi sinu igba olomori.
A o wa fi igbin nla kan gun ose yi Lori. A o gbe oseyi pamu fun ojo meje. A o ma fiwe ni aro tabi
ale odaju:
.

*ILEKE IFERAN*

_Ori pepeye, ao ju eyo atare kan si lenu, ao jopo, Ao da sinu agbon, ao re ileke sinu re fun ojo meje,
Ao mafi si idi wa_

JEDI.JEDI...
A o mu egusi bara meta ao be epo ara re kuro ao ge kekeke ti abati yo won omo inu re kuro. Ao
da sinu kegi kan ao da kinnifuru agbolo kan si ao wa da 7up si ao mamu cup kekere kan ni aro ati
ale ni ojo meta meta Odaju
.................
.IMULE AGBA META.................
Mofi olohun se eleri Ogun nbe , tio nawa lowo rara ti aye Wa yio ma rorun Lai se owo lofo Lori
Ogun sise...
Anfani imule Agba meta
1. Ti aba fedi Oso,aje tabi emere alagbara aye
2. Ti abafeki awon meteta Fi ara hanwa loju aye tabi loju orun
3. TI Oro badaru alafiwon se atonna Lori Oro naa
4. Ti abafe ran won nise lati logbe owo wa funwa
5. Fun eniti oba nwa okiki kaa kiri loju ona professional career re dakun danwo ..
wallahi wani okiki Koda ju awon egbe re lo loju ona ise ojore
6. Etc................
Imule gidi Yi Kona just N50 lo......
Aowa ogede omini topon daadaa aowa Fi epo pupa te EJIOGBE te ifa re si Ilele....
Ni oju ona ati wole wa. Aope gbolohun si ni ihoho ni ago kan 1am oru. Aowa Fi ogede omini eyo
kan je ni kiakia, aowa sare wo aso pada aolo sun..........
Eyiti oku odi oju orun ninu national Assembly lohun.............
Gbolohun re..................
Oso mokan 3x
Aje mokan 3x
Emere mokan 3x
Yeye topon tere tere awo Ile alara 3x
Omo pupa topon tere tere awo Ile Ajero 3x
Emu ni ekoko fi mule ni ojo kini ana Ile faamu.
Etun Fi ogunro mule ni elekeji Ile lofaamu
Epo ti efi mule ni ojo keta Ile kole faamu
Epo naa ni emi Wahab n Fi bayin mule loni ooooooooo.
Gbogbo oun ti moba dawole kin ma ni aseyori rere
Gbogbo oun ti mobade ejekio de
Gbogbo oun ti mode tu ejekie tu
Gbogbo oun ti mofe ki gbogbo eyin eleye se funmi
Gbogbo oun ti mobaro Kodi ase
Mofe ki efi ara hanmi Lalo
Mofe ki efi ara hanmi labo
Mofe ki gbogbo odawo leemi kio ma yorisi rere...
Mofe di .....................
(Oso dudu,Oso pupa tabi Oso funfun)
( Aje dudu, Aje pupa tabi Aje funfun)
(Emere dudu, Emere pupa , Emere funfun)
Epo loni kie ma polomi kaakiri fun gbogbo Omo araye
Epo loni kie fimi han kaakiri aye wipe emini momo ise .................
(Aowa doruko ise tin anse e.g Alfa, tailor, oniwasi, pastor, woli, baba alawo , doctor, any of our
professional career etc..:
.
.

IMULE IMULE IMULE AWON AGBA


!!! ti aye eniyan ba daru pata tikorojutu re man,tio Ogun aiye Kofi lorun sile,promise and fail kojawo
Loro re,Amubo ba da lamu,ti aini owo lowo tun wafi odo re se ibugbe,esofun wipe moni kiose ise
yi tiobawase kio kiesi awon ayipada tobari lasiko toba nlo ise na lowo atigba tobalotan, Ewe iyalode
aoja kopo Dada but kiatoja aoki ewe na ni oriki re dada,aojo pelu odidi atare kan,aolokuna Dada
aote IFA osameji osa eleye si,aope ofore si: Eran ti kekere petu 3x,ewure doke yapaluga 3x,oba
jegijegi,oba jomijomi,oba kujekuje,oba jegijegi ni oruko tanpe Iwo obaluaye,oba kujekuje loruko
tanpe Iwo esu odara,oba jomijomi loruko tanpe eyin iyami osoronga,ojoti etikole orun bowasi ikole
aye,eni teba de ile aye tan riro ni aoro,nigbati e de ile aye tan,eni kinbayin wa nkan alejo wa,mofuyin
ni omobirin asese banile,mofuyin ni omokurin asese ropon(ropon penis),eha mi lapa eran,moni emi
kije apa eran,ehami ledo eran mini emikije Edo eran,eni iru eran kini emije?,moni eran ebe ni,ewani
to base beni kin niso nidi igi ewe aye,moni latilose kini?,eni ibe latifi osameji mule,eni ise
tobaranyin simi laburu,eyin konije,ise ti moba beyin ni eyin yioje,eni gbogbo eni tobalo IFA osameji
yi,agbara aje,oso kan kogbodo ka man.adura........! ao manfi foko tutu mu tabi epo pupa ni ale ale,
IMULE ADO WONU ADO

ALE IJOTI ABAKOKOLO ISEYII GANGAN NIYIOBERE SINI SE ISETI ARAN,OBINRIN


KOGBODO LO ISEYIOO WALAI ASE OLOHUN OBA ALLAH NI,
#ISENARE_ EYELE FF KAN, IKODE EYOKAN, ODIDI ATARE KAN, ADO IJAMO MEJI,
ILAJI OPA ASO FF,
#SISERE_ AOLE EYELENA MOLETIYIOKU PATAPATA, AOWAKI IKODEBO LOJU OTUN
TIYIOJADE LOJU ISIRE, AOWAFI ILAJI OPA ASO FF NA WE DADA, AOLORIMOLE,
AOLOWUPADA NI OJO KEJI NI DEDE IYE AGO TI ARIMOLE NI ANA,BI 12Pm oni 12Pm
OLA NI AMALOWU OO, AOWAGBESINU IKOKO IJONKAN PELU ODIDI ATARE KAN,
AOJOPAPO, TI OBATIJOTAN AOLOKUNA DADA, AOWARO SINU ADOKAN, AOTUNGBE
SINU APE AOTUNJO TOBATIJOTAN AOLOKUNNA AOROSINU ADO KEJI, IDIRE
KOGBODO KANLE OO, AOMOLO PELU OMI LASAN LALALE PELU OFORE BAIPE
#OFORE_ EYE WONU EYE, ADO WONU ADO, ENIYAN WONU ENIYAN, BI EYEBAWONU
EYE,EYE ARINU EYE, BI ADO BAWONU ADO, ADO ARINU ADO, BI ENIYAN BAWONU
ENIYAN, ENIYAN ARINU ENIYAN, EMI L OMO L TIWONUYIN LONI, EJEKI ONASI
FUNMI, ADUA,ALALE LAOMOPE OFORE SIOO

SIGLET AWO TELE IBON...ao wa pandoro tutu ao la si meji dogbadogba ao wo inure kuro ao ki
siglet tuntun ti ko luho sinu re ao lo bo mo ori akitan fun ojo meje ao wa lo wu leyin ijo keje ao sa
siglet yen sinu yara ti o ba gbe ao ma wo jade amo ao gbodo fo siglet yen mo laelae..
.
.
...AYETA IBON....obi abata oloju meta eyokan owo eyo tiko luho eyokan aso sango die ao gbe ile
lorita meta lale ao so obi yen sinu koto yen ao wa pe gbolohun yi si....eyin aye ooo 3 emi lagbaja
omo lagbaja mowa bayin mule loni ki esi ma dami ti eo ba dami emina o ni dayin laelae ti eobawa
dami ti emina wa dayin lati aleyi lo gbogbo nkan ti nje iran ibon kogbodo wole simi lara......ao ka
gbogbo nkanti a fesi yepe ti a wa jade ninu koto yen ao bu die sinu aso sango yen pelu owo eyo yen
ao ta ni koko ao ran ni awo pupa ao ma fi si ara wa jade ao da yepe bo obi yen mole......

.
Awure owo NLA:-
A o wa itanna tanna powo 80,ITU wooro 80,Eyo Atare 80,a o lo po sinu isasun kan,a o ge Igbin
eyoka to ba pinu si ona 80,Lenin re a o se ni epo sugbon ko gbodo ni iyo rara,a o fi OSU te IFA
Ofun si owo otun,a o fi efun Ado te IFA ofun si owo osi, sugbon enu ona abawole wa la o ti lo
ise yi oo,ti a ba ti te IFA yi si ile Pepe a o wa da obe yen le Lori a o wa pe gbolohun re si bayi:-
Asokuntoku topa Aje,bo sode ilu ki o lo ba ogorun-oke-owo wa fun emi---omo-----,Ajiwapola bo
sode ilu ki o lo pa egberun-oke-owo wa fun emi ---- omo--. Ninu ilu yi ati origun mereerin gbogbo
agbaye. Ajilowuro kutukutu gbokun oro mun, ko bo sode ilu ki o lo pa egbe-gberun aimoye wa fun
mi,ewe tannapowo kii tanna ola tire ki o mo Jo,kiakia ni ki emi---- omo----maa GBA owo lowo
okunnrin,obinrin, omode,Agba, olowo,oloro, borokinni. Iru loni kPUPO
maa RU owo yin wa fun emi ---- omo--- loni,efun Loni ki e wa fun mi ni owo owo yin,osun loni ki
e wa fi owo owo yin sunmo mi,enu ni igbin fi n ko IFA ile woPUPO
AWORO POKIKI
.
.

KOWE DUDU 1
ODIDI OKETE EYIKEYI 1
AKO ALANGBA 16
ABO ALANGBA 16
EWE OLA ABO KONGO KAN
AWEREPEPE TO PO DADA TOOJO
EWURO TOPO TOOJO
ATARE TOTOBI DADA 3
SISE RE : AO FUN OKETE YEN LORUN PA AOFI TELE APE, AO GBE KOWE SILEGBE, AO
DA AWON ALANGBA YEN LOLORI PELU ATARE YEN AO DA EWE OLA LELORI AOTUN
WA DA GBOGBO EWE YEN LELORI. AO FI EPO PUPA YI IDI ARO KA. ODI JIJO. TABANJO
LOWO OSESE KI ALEJO TABI AWON OMO KEKE KORAWON WA BAWAPE KINI ANSE?
AOSOFUN PE OWO NLANLA NI ANWA. AO FUN AWON OMODEYI LOWOPE KIWON
LOFI RA PAPANU JE. TOBAJE ALEJO NI AO SE ENINA LALEJO BI AGBARA BASEMO.
ALE RA SOFT DRINK FUN TABI OTI. SUGBON TI AOBARI ENIKENI IGBATI ANJO LOWO
TABAJO TAN AO LOFI OWO ATI NKAN JIJE BI BISCUIT, AKARA TABI ONJE SE ITORE
ANU FUN AWON ONIBARA. AO LO KUNNA DADA AO PIN SI MEJI AO PO IDAKAN MO
OSE AO MAFI OTI LO IDAKEJI, LEHIN IWE. OPO ENIYAN LELO.
IKILO PATAKI. ISEYI AMA FA OPOLOPO OBINRIN WA TABI OKUNRIN WA. SUGBON
AOGBODO MABA WON SUN. OLEWU PUPO.
AKIESI TABA BA WON SUN TABI SE AGBERE ONITOUN YIO BARI OWO SUGBON
AKONI NI AKOJO, GBESE YIO WA PO FUN ONITOU.
AMO TABA TELE IKILO. ASIKO TABA NLO ISEYI AO MA NA OWO BI OLE NI. ODAJU
PUPO
.
.
ASE TON PAGI LOJO TODAJU BI IKU.
.
ori oga ojoo kan ori ako alangba kan ori oka tutu ojoo kan ewe ina ojoo ewe esisi ojoo ao gun po
mo ose dudu ao ko si inu Iwo igala oje oro agogo ni ao fipo ki a to kosi iho igala ao wa ma kan oje
oro so titi ojo meje yio fipe ao mafi ahon kan soro ti aba to lo tan ti ao bati lo epo yio ma sise lo
odaju

También podría gustarte