Documentos de Académico
Documentos de Profesional
Documentos de Cultura
Òyèkú Méjì A
' pé
Ifá ' òun pé ire fun eléyìun; Yóó là láyé è. Òún ó sì bá a tún nnkan
` è se. Ifá pé òun ò
' ' ' ó gùn.
níí je kí baba. Omo, ègbón àti àbúrò ení ó dá Ifá yìí ó yàn kú. Èmíi wón
' ' ' ' ' ' ' '
Òye n´ làá bò lókè
Mo se bójúmó ' ní n´ mó
A díá fún Òyè'
'
Èyí tí yóò gbóju' ' òrun là bí Oba eréke
' ' ' '
Òún le là báyìí? '
Wón ní ó rúbo
Wón' ní òyee rè ' ó móo là
' rúbo
Ó bá ' ''
Òyee rè bá là '
Ayé ye' é
N ní wá ' 'n´ jó ní wá n´ yò
Ni n´ yin àwon Babaláwo '
Àwon Babaláwo ' n´ yin Ifá
'
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òye n´ 'làá' bò 'lókè
Mo se bójúmó ' ní n´ mó
A díá ' fún Òyè '
' '
Èyí tí yóò gbóju òrun là bí Oba eréke
Ìwo ò yè ' ' ' ' '
'
Èmi ò yè '
Òyé di púpò '
' ' opón kún
Ojú ' tétéété
' ' ' ' '
Òyèkú Méjì A
' desea
Ifá ' bien a esta persona. Él sería rico en su vida. Ifá remendarían
` su vida para él y
no le permitirían ver muerte prematura de sus parientes. Todos ellos habrían tener larga
vida.
Ifadowole
1
Ifadowole
Usted no se cambia
Yo no me cambio
Òyè se vuelve un par
Y la bandeja se pone muy llena.
Òyèkú Méjì B
' pé
Ifá ' eléyìun ó mùú nnkan
` bò làti enu isée rè. Nnkan
` tí ò sì lérò` pé yóó dowó, yóó
dowó mó o lówó. ' ' ''' '
' ' ' '
Ìgbá nlá
´ abìdí yèkú
Mo lárúgbó emi' lóko
Oori abìdí gbàdàgì '
Apá aborí pétékí
Níí fón omoo ' 'rè ká inú igbó
''
A díá' fún ' Ònyagbè
Èyí ti n´ lo rèé báwon ' múlè légàn
Àwon mú' nnkan ` tó' dáa bò' lóko?
'
'
Wón bá to Òrúnmìlà lo '
'
Òrúnmìlà ' ní' kí wón ó rúbo
'
'Wón bá rúbo ' '
Wón' ní kí wón ' ó lòó gbin èpà
Wón bá korí 'sí oko' '
' '
Wón' gbin 'èpà
´ '
Ngbàa wón' ó móo kórè èpà
Ìrúbo tí ón ' se ' ' '
Ebó 'pé ' '
' '
Béèyàn bá tí rí omo èpà
Yóó rò pé iyùn 'ni ' ' '
Ayé ye Ònyagbè tó múlè légàn
N ní wá ' n´ jó ní wá ' n´ yò ' '
Ní n´ yin àwon Babaláwo '
Àwon Babaláwo ' n´ yin Ifá
'
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
'' '
Ìgbá nlá
´ abìdí yèkú
Mo lárúgbó emi' lóko
Oori abìdí gbàdàgì '
Apá aborí pétékí
Níí fón omoo ' 'rè ká inú igbó
' ' `'
A díá' fún Ònyagbè
Tí n´ lo rèé bá won' múlè légàn
Kín níí' múni? ' ' '
Oko níí múni
Àjùbà èpà
'
Níí múni kéyìn lóko
Àjùbà èpà '
Àjùbà èpà' ni mo gbìn
Mo wáá' yinyùn wánú ilé
Ire gbogbo tó mí lówó porongodo
' '
Ifadowole
2
Ifadowole
Òyèkú Méjì B
' dice
Ifá ' que esta persona devolvería la riqueza de su lugar o trabajo. El artículo que no
había tenido ninguna esperanza de ser vuelto valioso se volvería a la riqueza.
Ifadowole
3
Ifadowole
Òyèkú Ogbè A
' pé
Ifá ' ire tí n´ bò wáá béléyìun ò níí já sonù. Ebo ni kó rú.
' ' ' '
Òyèkú ló logbè
' '
Kankaankan bíiná eyín
A díá fún Òrúnmìlà'
Níjó ti Ifá n'´ rebi àjítòròo sègi
` ' òún le dáa báyìí? ' '
Nnkan
Ó wúlò Òfún nlé ´ ayé?
Nnkan
` òún tòrò?
Kò já sonù mó òun lówó?
Wón ní' kó rúbo ' ' '
' '
Wón ní kó rú òwúùrù eyelé
Kó' sì rú òpòlopò owò ' '
Òrúnmìlà' bá' rúbo ' '
'Ajé bá dé '
Ó dì mó Òrúnmìlà
Kò já ' '
Aya náà dì mó o
Kò já ' '
Ire gbogbo ò já
Ayé ye Òrúnmìlà
N ní wa ' 'n´ jó ní wá n´ yò
Ní n´ yin àwon Babaláwo '
'
Àwon Babaláwo n´ yin Ifá
Ó ní' béè làwon Babaláwo tòún wí
Òyèkú' ló ' logbè '
' '
Akankaankan bíiná eyín
A díá fún Òrúnmìlà '
Níjó ti Ifá n'´ rebi àjítòròo sègi
Wón ' ní ó sá kale ó sebo ' '
' gbébo' nbé
Òrúnmìlà ´ '' '
'Ó rúbo ' '
` ajé' wo mó ni mó jàá
Njé
Wonkoko ' '
Nìtàá woó méyìn
Wonkoko '
Ayá wo mó mi mó jàá
Wonkoko ' '
Nìtàá woó méyìn
Wonkoko '
Omo wo mó mi mó jàá
' '
Wonkoko ' '
Nìtàá woó méyìn
Wonkoko '
Ire gbogbó wo mó mi mó jàá
Wonkoko ' '
Nìtàá woó méyìn
Wonkoko '
Ifadowole
4
Ifadowole
Òyèkú Ogbè A
' dice
Ifá ' no se perderían las fortunas que vienen a esta persona. Él debe sólo realizar
sacrificio.
Ifadowole
5
Ifadowole
Òyèkú Ogbè B
' póun
Ifá ' pé ire fún wa. Nìbùjokòó eléyìun niré ó mo wáá bá a. Ebo ni kó rú dáadáa.
' ' '
Òyèkú logbè lábárà
A' díá
' fún Awónwón ´
Awo won lóko' '
' '
Lóko ni Awónwón tíí sawo
´
Wón ní ìwo 'Awónwón '´ ' rúbo
'
Ní ibùjokòó re nire ó ti móo' wáá bá o
' '
Ó bá korí síbùjokòó ' rè ' ' '
'
Iré bèrè síí wolé tò ó '
N ní wá ' n´ jó ní ' wí' n´' yò
Ní n´ yin àwon Babaláwo '
'
Àwon Babaláwo n´ yin Ifá
Ó ní' béè làwon Babaláwo tòún wí
Òyèkú' logbè' ' lábárà
A' díá
' fún Awónwón ´
Awo won lóko ' '
Awónwón ' pèlé o
´
Awo oko'
' ' '
Wón ní o wáá joyè o wá nlé ´
'
Òyèkú Ogbè B
' desea
Ifá ' bien a esta persona. Está en la morada que sus fortunas vendrían a
encontrársele. Él debe ofrecer sacrificio bien.
Ifadowole
6
Ifadowole
Òyèkú Ìwòrì A
' póun
Ifá ' pé ire ajé fún eléyìun. Ifá pé kó rúbo. Ayé ó ye é.
' ' '
Iná jókùn won a dìkán
Iná jó réfe tán ' ló bá n´ defun
Ilè níí jòtòtò èèyàn lérù'
A' díá fún' ' Wáléolá
'
Èyí tíí somo Àsànléèyere '
' '
Ayé le ye òun délè báyìí? '
Wòn ní kó ' rú òpòlopò ' ebo
'
Wáléolá omo Àsànléèyere ' ' ' ' ' ' bá deboó lè
Ló bá' rúbo ' ' ' ' '' '
'
Ló rúbo tán layé bá ye é
À á séé' mo Wáléolá ' '
N làá pe Èèbó ' '
Ayé ye é
N ní wá ' 'n´ jó ní wá n´ yò
Ní n´ yin àwon Babaláwo ''
Àwon Babaláwo ' n´ yin Ifá
'
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
' ' won
Iná jókùn ' a dìkán
'
Iná jó réfe tán ló bá n´ defun
Ilè níí jòtòtò èèyàn lérù '
A' díá fún' ' Wáléolá
' èyí tíí somo Àsànléèyere
Baba enìkan ò là làà là kée' téèbó
' ' mó
'
'
Èèbó dé ò abolà reberebe '
'
Owó minimini lèèbó n´ lò ' ' ' '
Òyèkú Ìwòrì A
' le
Ifá ' desea la fortuna de riqueza a esta persona. Él debe ofrecer sacrificio. La vida lo
agradaría.
Ifadowole
7
Ifadowole
Òyèkú Ìwòrì B
' pé
Ifá ' kí eléyìun ó rúbo torí ayé ó ye é
' ' '
Òyèkú pòòrì síhìín
' ' pòòrì sóhùún
Òyèkú
'Ojú' Opón kún 'téteété
' Eégún' tí' 'n´ 'tórun bò wálé ayé
A díá' fún
Wón ní kó rúbo ' '
Ayé' le ye òun báyìí? '
'
Wón ní ayé ó ye Eégún
Ebo' ni kó rú '
' ' bá rúbo
Eégún
Okàan rè balè'
Ó nísinmi ' '
Ní bá n´ dá bírà
Ó ní Òyèkú pòòrì sìhiín
Òyèkú' pòòrì
' sóhùún
'Ojú' Opón kún 'téteété
A díá' fún
' Eégún' tí' 'n´ 'tórun bò wálé ayé
Wón ní ó sá káalè ó sebo '
'
Eégún gbébo nbè ´ ' ' '
Ó rúbo ' ' '
Rírú ebo' èèrù àtùkèsù
'
E wáá bá ' wa ní màrínrín ' ire
'
Màrínrín ire làá bá ni lèsè oba Òrìsà
' ' ' '
Òyèkú Ìwòrì B
' le
Ifá ' pide a esta persona que ofrezca el sacrificio para que la vida habría de agradarle.
Ifadowole
8
Ifadowole
Ifadowole
9
Ifadowole
Òyèkú Òdí A
' póun
Ifá ' pé ire, yóó la. Òkìkíi rè yòò sì kàn lo láyé
' '
Òyé kúndí kundi
A' díá
' fún Ayílórùlé Òjòpò òrà
Èyí tí ó rà ràà rà '
Tí ó rerú méfà lóòjó
'
Tí gbogbo ' okó 'fí n´ sonriín ko
eye
'
Ayé le ye òun' báyìí?
'
Wón ní kí' Ayílórùlé Òjòpò òrà ó rúbo
Wón' ní òpòlopò owó lebo ' '
'
Ayílórùlé' bá ' 'rúbo' '
Ó bá béré síí là '
'
Ayé ye' é
'
Okàan rè' balè
'Ó nísinmi ' '
N ní wá n´ jó ní wá n´ yò
Ní n´ yin àwon Babaláwo '
Àwon babaláwo ' n´ yin Ifá
'
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òyè kúndí' ' kundi '
'A díá
' fún Ayílórùlé Òjòpò òrà
Èyí tí ó rà ràà rà '
Tí ó rerú méfà lóòjó
' ' okó 'fí n´ soriín ko
Tí gbogbo eye
Awo rere mòmò ' ' ni '
' '
Ayílórùlé Òjòpò òrà
Awo rere mòmò ni '
' '
Adábà bá n´ kígbee rè kiri
' òrà
Ní n´ pÁyílórùlé Òjòpò
Ayílórùlé Òjòpò òrà '
'
Òyèkú Òdí A
' dice
Ifá ' que él desea bien a esta persona. Él se haría rico y popular.
Ifadowole
10
Ifadowole
Òyèkú Òdí B
' póun
Ifá ' pé ire ení ó dá Odù yìí. Ipáa rè ó kàá nnkan
` láyé. Sùgbón kó rúbo, kó sì móo
sòótó. ' ' ' ' ' ''
'
Lèselèse lá n fé
' ' '
Òòsà mó jèé á dáwó lé n táà leè se
' ' '' ' '
A díá fún Òdùyè
Òdùyè tíí sòré Oba ' lóde Òyó
' ' ' ' ' '
Lèselèse lá n´ fé
' ' '
Òòsà mó jèé á dáwó lé n táà leè se
' ' '' ' '
A díá fún Àáyá Onírù mérìndílógún
Èyí tí n´ gbóguún ti Oba '
Àáyá Onírù mérìndílógún ' ni n gbóguún ti Oba
' '
Ó kó lele mó Oba
Òún wáá le 'mú' Àáyá Onírù mérìndílógún báyìí?
Òdùyè tíí sòré Oba lóde Òyó bá ' mú Oba loòdò àwon Lèselèse là n´ fé
Àwon' Lèselèse ' ' ' là n´ fé ní 'kí 'Oba ó to ' Ògún' 'lo ' ' ' ' '
' '
Oba bá to Ògún lo ' ' ' ' '
'
Ògún lóun ' ó mùú' Àáyá òhún
Ògún náà bá to Òrúnmìlà' lo
Òrúnmìlà ní kí' Ògún ' ó rúbo'
' ní kí Ògún ó rú apó
Ó '
Kó rú ofà
Kó sì rú ' oorun
Ó ní kí Ògún ó rú orín àrùkù
Kó sì rú èèrí
Ó ní kí Ògún ó dira
Ojú ònà sì ni àwon àáyá yìí í rìn
'
Láti orí onírù kan'
Tée dórí onìrú mérìndílógún tí n gbóguún toba
Wón ní kí Ògún ó' korí sí ijù '
' '
Kó mú apóo rè
Kée rorí '
'
Kó mú Ofá
Kée ro esè '
' ' '
Kó mú orín àrùkù àti èèrí
Kó gbé e kègbé
' '
Ifadowole
11
Ifadowole
Ifadowole
12
Ifadowole
Òyèkú Òdí A
' ' persona superaría muchos obstáculos en la vida. Él es exhortado a ser honrado
Esta
Ifadowole
13
Ifadowole
Ifadowole
14
Ifadowole
Ifadowole
15
Ifadowole
Òyèkú Ìrosùn A
' pé
Ifá ' ire fún eléyìun ti bá n´ dá èésù, Ifá tó dá èésù sílè nìyì. Eléyìun ó nísinmi láyé, yóó
sì di Olowo. ´ '
Òyè rùsùrùsù
A' díá' fún won lÉgbàá Èésù
Níbi wón gbé ' n´ kórí
' ajée jo
Wón ní' kí wón´ ó rúbo '
' '
Wón ní òpòlopò owó lebo '
'
Òwúùrù ' ' 'lebo ' '
'eyelé
Wón níre fún' ' won ' '
Wón ' bá rúbo '
' ni wón
Egbàá ' sì n´ dá
'´ '
Ngbà ó pé wón bá kówó
Wón nísinmi ' '
'
Okàan wón balè
Ayée wón' dáa '
N ni wón' wá n´ jó ni won n´ yò
Wón n´ 'yin àwon Babaláwo
Àwón' Babaláwo ' n´ yin Ifá
Wón' ní béè làwon Babaláwo tàwón wí
Òyè ' rùsùrùsù'' ' '
A' díá' fún won lÉgbàá Èsù
Níbi wón gbé ' n´ 'kórí ajée jo
'
Taa ló rúbo báwònyí beere?
Òyè rùsùrùsù ' ' '' '
'Àwon ' ló rúbo báwònyí beere
Òyè rùsùrùsù
' '
Òyèkú Ìrosùn A
' desea
Ifá ' ´ Ifá lo exhorta formar un grupo dinero-contribuyendo
bien a esta persona.
´
llamado 'Èésú'. Éste es el verso de Ifá que estableció Èésú. Esta persona tendría
descanso y se volvería un hombre rico.
Òyè rùsùrùsù
Adivinación lanzada para Egbàá Èésú
Donde ellos estaban agregando los conceptos de riqueza
Les pidieron que realizaran sacrificio
Ellos les dijeron que mucho dinero es el Sacrificio requerido
Una paloma madurada es el sacrificio
Ellos les desearon la fortuna de riqueza
Las personas de Egbàá Èésú realizaron el sacrificio entonces
Entretanto ellos contribuyen sólo cinco peniques (centavos)
Después de un periodo largo de tiempo, ellos compartieron sus contribuciones
Ellos tenían paz
Ellos también tenían descanso de mente
Sus vidas se pusieron finas
Era entonces que ellos empezaron bailando y regocijando
Ellos estaban alabando su Babaláwo
Ifadowole
16
Ifadowole
Òyèkú Ìrosùn B
' pé
Ifá ' kí eléyìun ó mó Sahún o. Ti ón bá tí n´ mutí tan ni kí wón ó fègbé ìgò lélè. Kó
' àmì èèyàn kán
móo ra otí se àlejò torí ' n´ bò ´tí ón féràn oti. ' ' ' '
'' ' ' ' ' ' '
Ipín lawo òdómodé
Àwàlànfà ' ' Àgagò '
` lawo
Ayé n´ re Ife Awo sóko
Adíá fún Òyè ' Ògòsùn
Èyí tí ó muú 'Ogóji dun Sàngó
'
Sàngó ní n´ kójáá lo lójo kan
Otí sì n´ wù ú mu ' ' '
Ó' ti dé gbogbo ibi tó ti lè rí díè
Kò rí fi sara rindin '
Ló bá rí àwon ti n´ muú
Tí ón gbé ègùn ' dúó
'
Otí sì ti tán nnú' ´ ègùn
'
Sango bá koja lo'
Ó rosè bíi kí' wón ' ó pè é kó wáá mu
Kò gbó ' kí wón 'pe òun padà
Kó si mò ' pé 'otí ti tán nnú ´ ègùn ni won ò fi pe òun
'
Sango bá padà ' ' '
Ló bá bínú sí won
Àrìrá bá fedùn yo ' lapo
Ló bá yo iná ' lára' gbogboo won
'
Ipín lawo òdómodé '
Àwàlànfà ' ' Àgagò'
` lawo
Ayé n´ re Ifè awo sóko
A díá fún Òyè ' Ògòsùn
Èyí tí ó muú Ogóji' ' dun Sàngó
Sàngó bá bo síbi oti
Yóó mu èyí' tó kù' lágbè
Ó gbénu è sókè bíi kíkankan ó mó le kán sílè
'
Àfi báfó ' ' '
Otí ti tán
Sàngó ní kín lo gbégùn duó se?
Òyè Ògòsùn '
' ' tótí tán
Ìgbà
Kín lo' gbégùn dúó se?
Òyè Ògòsùn ' '
' '
Ifadowole
17
Ifadowole
Òyèkú Ìrosùn B
' manda
Ifá ' ´ no ser avarienta. Cualquier vez que él bebe vino, él
a esta persona para
´
siempre debe poner el recipiente que queda por su lado en la tierra que él termina
inmediatamente su contenido. Le proponen que sirva a los visitantes con vino porque
una espiritualmente marcada persona que disfruta vino lo visitaría.
Ifadowole
18
Ifadowole
Òyèkú Òwónrín A
' pé
Ifá ' kí' eléyìun
' `
ó rúbo kí wón ó mó le gba nnkan baba è tí n´ be nílè; eboo rè ó sì dà .
Ifá pé eni nlá
´ leléyìun. ' ' ' ' ' ' ' '' '
'
Òyè wónrin mì
' ' wónrin
Òyè ' je
'Òyè' soni ' pàkàpàkà ' gbé mì
A' díá
' 'fún Òni wàkàwàkà
Èyí tí n´ be 'níbú Ìrágìjí
Ibúu babaa ' re
Àwon òtá bá 'n´ yí i po
Wón' láwon ' ó gba ibú lówó è
Wón ní kí' Òni ó rúbo ' ' '
'
Wón' ní kò 'séni tí ó gba ' ibúu baba è lówó é
Bó' bá ti rúbo' ' '
Wón ní bó opón bá téjú '
'
Gìrìpá òrúko ' lebo ' è '
Bí ò bá téjú ' ' ' '
Àkùko adìe ' méta lebo
'
Kó sì rú òpòlopò ' ' owó ' ' pèlú è
Òní rúbo' ' ' ' '
Gbogbo nnkan ' tí ón láwon ó gbà lówó è
`
Kò séni ó le gbodò ' lówó' Òni mó ' ' '
'
Yóó nawó nasè lódóo ' baba
' ' rè ni
Ayé ye Òni ' ' '
N ní wá ' 'n´ jó ní wá n´ yò
Ni n´ yin àwon Babaláwo '
Àwon Babaláwo ' n´ yin Ifá
'
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òyè wónrin '' '
mì
'Òyè' wónrin' je
' ' soni
Òyè ' pàkàpàkà ' gbé mì
'A díá
' 'fún Òni wàkàwàkà
Èyí tí n´ be 'níbú Ìrágìjí
Ibúu babaa ' re
Taa ní ó gbodò ' lówó Òni
Òni wàkàwàkà baba ' ' è' ló nibú
'Taa ní ó gbodò lówó 'Òni
' ' '
Òyèkú Òwónrín A
' le
Ifá ' pide
' a' esta persona que realice sacrificio.
` Su sacrificio demostraría eficacia. Su
abuelo (forefather’s = abuelo, antepasado) de justa posesión que existe presentemente
habría, no ser tomado de él. Ifá dice que él es una persona grande.
Òyè wónrin mì
Òyè wónrin je
Òyè soni pàkàpàkà gbé mì
Adivinación lanzada para el cocodrilo magnánimo
Uno que vive en las aguas profundas de Ìragbìjí
Su padre de aguas profundas,
Ifadowole
19
Ifadowole
Òyèkú Òwónrín B
' pé
Ifá ' kí' eléyìun
' ` Nnkan
ó rúbo toríi bírà kan tí n´ bò wá. ` ´ kan n´ bó wá fún wa.
Ìmòràn
Nínú nnkan '
ìmòràn òhún, kí tiwa ó gbayì nnú ' ' '
` ´ è ni ká rúbo sí.
' ' ' '
Òyè wónrin mì
' ' wónrin
Òyè ' je
'Òyè' soni' pàkàpàkà ' gbé mì
A' díá
' fún
' Ajíbówú
Èyí tíí salágbède Ògèlé
Wón ní ó rubo' '
'
Olódùmarè ló' kó gbogbo àwon Alagbède tí n ´be nlé
´ ayé jo
' ' '
Wón ní kí wón ó móo ro nnkan ` '
'
Gbogbo nnkan ' ' '
tí wón bá lè ronú kàn
`
Ó lóun féé wo teni tí' ó gbayì jù
Àwon kán ' ' ro tàkúté'
'
Ìlu ò níye '
Èwòn n´ be nbè ´
'Àdá' ò gbéyìn
Gbogbo nnkan '` téèyán le fi irin dá n´ bírà
Gbogbo è ni ón ti ro
Alágbède' Ògèlé ' bá' to àwon Babaláwo è lo
' ' ' ' ' '
Ifadowole
20
Ifadowole
E gbàun!
'`
Nnkan tí ón ní kí àwón ó ro yìí
' fún òun!' '
Ó di ìmoràn
'
Àwon Òyè wónrin mì ní kó pèsè fún àwon ayé
Àwon ' àgbàlagbà
' ' ' '
‘ Àwón ' ní ó fònà hàn ó’
'
Ajíbówú bá rúbo ' '
Ó pèsè fún àwon' Àgbàlagbà
Ni ón bá fún Ajíbówú ' ní Osù
Wón ' ní kó ro ó '
' '
Kó wáá gbé e sínú igbá àdému '
Fèrè tó bá sí
Yó ' 'móo sún ' díèdíè
Wón ó pèé osù ' lé '
' '
'
Díèdíè tí yée 'dijó keèédógún tí gbogbo ojú è ó sìí sílè
' '
Yóó ti kún inú igbá ' 'tán '' ' '
´
Ngbà ó bá tún yá
Yóó tùún móo bò ó
Bó bá tún ku' 'ibi tíínrín
Wón ó tùún móo pé osú lé lónìí
N ní' wá n´ jó ní' wá ' n´ yò
Ní n´ yin àwon Babaláwo '
Àwon Babaláwo ' n´ yin Ifá
'
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òyè wónrin '' '
mì
'Òyè' wónrin ' je
'Òyè' soni ' pàkàpàkà ' gbé mì
A' díá' 'fún ' Ajíbówú
Èyí tíí salágbède Ògèlé
Ebo n wón ní' ó se '
'Ó sì' gbébo ' nbè
´ '
Ó rúbo ' ' '
'
E mó jèé á mú ro agogo
' táa
Irin ' ' mú ' ro osù '
E mó jèé á mú ro agogo ' '
' ' '' '
Òyèkú Òwónrín B
' le
Ifá ' pide
' a' esta persona que sacrifique antes de un hecho maravilloso que viene a su
camino, tal que su propia sumisión se aceptaría ampliamente.
Òyè wónrin mì
Òyè wónrin je
Òyè soni pàkàpàkà gbé mì
Adivinación lanzada para Ajíbówú
El herrero de ciudad de Ògèlé
Le pidieron que realizara sacrificio
Olódùmarè había congregado a todos los herreros en el mundo entero
Él les dijo que hicieran tipos diferentes de cosas
Todas las cosas sobre que ellos podrían pensar
Ifadowole
21
Ifadowole
Él dijo que él quiso ver a la persona cuyo trabajo aventajara (superar, sobresalir,
distinguirse)
Algunos hicieron trampas
Algunos hicieron cuchillos
Los punzones eran incontables
Las cadenas no se omitieron
Los machetes no se dejaron atrás
El hecho entero maravilloso que el hombre pudiera formar usando hierro
Todos habían sido hechos
El herrero de Ògèlè fue entonces a sus Babálawos
'Por favor ayúdeme', él suplico
'Estas cosas que Olódùmarè nos pidió que formáramos'
'Ha transcendido mi conocimiento realmente'
Los sacerdotes Òyé wónrin mì le pidieron que mantuviera (proveer, suministrar,
abastecer) a las brujas
El Anciano
'Ellos le mostrarían la manera', ellos dijeron
Ajíbówú hizo como dijeron.
Él mantuvo a las brujas
Ellos (las brujas) entonces le dieron la luna
Ellos le dijeron que lo tallara
Él debe ponerlo en una calabaza llamada 'àdému'
Inmediatamente él lo abre
Él movería la tapa despacio
Las personas dirían la luna creciente había aparecido
Poco a poco, hasta el decimosexto día cuando la calabaza entera se destaparía
La luna habría llenado la calabaza entera
Después de un período de tiempo
Él lo cubriría lentamente de nuevo
Cuando sólo la luna creciente que podría verse
Las personas dirían la luna creciente había aparecido de nuevo
Él estaba bailando y estaba regocijando
Él estaba alabando sus Babálawos
Sus Babálawos estaban alabando Ifá
Él dijo que era exactamente como sus Babálawos habían dicho
Òyè wónrin mì
Òyè wónrin je
Òyè soni pàkàpàkà gbé mì
Adivinación lanzada para Ajíbówú
El herrero de ciudad de Ògèlé
Le pidieron que realizara sacrificio
Él oyó hablar del sacrificio
Y él lo realizó
Nunca permítanos usar tallando el gong,
El hierro empleado formando la luna
Nunca permítanos usar formando el gong
Ifadowole
22
Ifadowole
Òyèkú Òbàrà A
' póun
Ifá ' 'pé ire pé a kò ní dáyé se; tòun tèèyàn ní ó jo móo se ilé ayé. Ire n´ bo
wáá dúó tì í. Eléyìun n´ bèère ire' ni; Ire náà ó sì wáá 'jókòó
' ' tì.
' '
Ifadowole
23
Ifadowole
Òyèkú Òbàrà B
' póun
Ifá ' 'pé ire fún eléyìun. Eboo kó mó le jìyà ni kó rú.
' '' '
Òyèkú pàlàbà pàlàbà i pàbó
' '
Babaláwo Esin ló díá fún Esin
' ' Òrun bò wálé' ayé
Esín n´ tìkòlé '
'Wón
' ní kó' rúbo ' kó tóó
' móo lo
Esín' dé ilé ayé 'wón tún ní' ó' rúbo
'
' ' ní yóó gbayì'
Wón '
'
Yóó gbèye
Sùgbón' kó' rúbo ìyà
' iyì
Ebo ' àtèye ni' Esín rú
' 'rú àtòòrì
Kò ' ',mérìndílógún
'' tí ón ní ó fí rúbo ìyà
' ' '
Ifadowole
24
Ifadowole
Òyèkú Òbàrà B
' desea
Ifá ' ' bien a esta persona. Él se exhorta realizar sacrificio que lo prevendría de
sufrir.
Ifadowole
25
Ifadowole
Ifadowole
26
Ifadowole
Òyèkú Òkànràn A
' póun
Ifá ' ' pé ´ire fún ení ó dá odù yí. Ifá póun gba eran ahùwo lówó è. Òun ó ba tún nnkan
`
è se. Ipá ayé ò níí ká' a, won ò sì níí lè da nnkan
` è' rú. ' ' '
' ' ' '
Awáwa
Awáwa
Awàwa n` wawà
Ota pété pètè pèté ni wón fí n´ wawà nIfè ´
'A díá 'fún
' Òrúnmìlà
' ' ' ' ' '
'
Ifá ó gberan ahùwo wànwà ` lówó akápòo rè
Òrúnmìlà ló ní kí akápò òun 'ó tóyú
' ' eran abìwo
' `
wànwà
'Kí ayée rè ó lè dáa ' '
Akápò bá' tójú eran abìwo wànwà `
'
Ó fi bòkè ìpòrí è '
Ni nnkan è bá ' n´' dáa
`
Ayé bá ye é
Okàan rè 'balè '
'Ló nísinmi' '
Ó ní Awáwa
Awáwa
Awàwa n` wawà
Ota pété pètè pèté ni wón fí n wawà nIfè
A' díá 'fún
' Òrúnmìlà
' ' ' ' ' '
'
Ifá ó gberan ahùwo wànwà ` lówó akápòo rè
'
Eran abìwo wànwà ' ' Akápò rè'
` tIfá gbà lówó
' fi tún tí Akápòo rè se ni ' '
Ifá '
' '
Òyèkú Òkànràn A
' desea
Ifá ' ' bien
´ a esta persona. Ifá acepta un animal con cuernos grandes de él para Ifá
`
remendar su vida para él; Sus enemigos nunca podrían agobiarlo. Y ellos no podrían
destruir su arreglo (instalación, equipo, organización, estructuración).
Awáwa
Awáwa
Awàwa n wawà
Ota pété pètè pèté ni wón fí n wawà nIfè
Adivinación lanzada para Òrúnmìlà
Ifá acepta un animal con los cuernos extendidos de su Akápò
Òrúnmìlà le había dicho a su Akápò que preparara un animal encornado salvaje
Tal que su (Akápò) vida sería buena
Akápò preparó el animal entonces
Él lo sacrificó a Ifá
Después, las cosas de Akápò se pusieron buenas
La vida lo agradó así
Él tenía paz de mente
Y también descansó
Él dijo Awáwa
Awáwa
Awàwa n wawà
Ota pété pètè pèté ni wón fí n wawà nIfè
Ifadowole
27
Ifadowole
Òyèkú Òkànràn B
' pé
Ifá ' kí' eléyìun
´ ó rúbo nipaa sísóra pelú obìnrin; kí obìnrin ó mó kòó bá a. kò gbodò
`
yan òré ìyànkuyàn. ' ' '' ' ' ' '
' '
Sìgìdì ni ò yírùn padà
A díá fún Mégbàgbéolá
Omo a se lenle pàdé 'àlè lónà
' ' ní ' ó rúbo
Wón '
'
Kó sì sóra lódó Obìnrin '
''
Mégbàgbéolá ' 'ò gbóràn
' '
Ilé Obìnrin tíí móo lo
Obìnrin òhún sì ti' 'kó' kùó nlé ´ oko è
' ' '
Ó ti kó lo ilée baba è
Ibi tí ilé 'gbé se yabuge ' léyìn ni ón lù ú pa sí
Ifá pé ki eléyìun ó sóra' '
' '
Kó sì mó déjàá ''
' '
Ó nó Sìgìdì ni ò yínrùn padà
A díá fún Mégbàgbéolá
Omo a se lenle pàdé 'àlè lónà
' ' ní' ó sá káalè kó jàre
Wón
Ebo' ní ó se '
'Kó ' mó baà ' bóbìnrin lo
'
Mégbàgbéolá gbébo '
Bèé ni ò rúbo ' ' '
''
Mégbàgbéolá ' ìwo lòó seun
'
Ìwo lòó sèèyàn ' '
E bí' ón ní ' o rúbo kó mó baà bóbinrin lo?
'
Ìwo lo se lenle pàdé ' àlè' lónà
' ' '
Òyèkú Òkànràn B
' le
Ifá ' pide
' a´esta persona que ofrezca el sacrificio siendo cuidadoso con las mujeres;
` tal
que las mujeres no le darían lejos. Él no debe hacer mal a los amigos.
Ifadowole
28
Ifadowole
Ifadowole
29
Ifadowole
Òyèkú Ògúndá A
' '
Ifá pé ki eléyìun ó rúboo káyé ó ye é. Kó sì só òrò tí ó móo so kí àwon èèyàn ó mó baà
'' ' ' ' ' ' ' '' ' '
ká òrò tí ò dáa mó o lénu; Kí wón ó mó baà tìràn mó o. Ifá pé kó móo tún ebí se, kó sì
' ' ' ' ' ' ' '' ' '
móo se dáadáa nínú ebí kí àwon èèyàn ó mó ti ibi pàlàkà tó yanu ba ebí è jé.
' '' ' ' ' ' ' '
Òyèkú Ògúndá A
' '
Ifá le pide a esta persona que ofrezca sacrificio para que la vida lo agrade (complasca,
satisfacer). Él debe estar atento de sus pronunciaciones tal que las personas no habría a
través de un discurso descuidado, embaucarlo en el. Ifá le pide que remiende
(componga, repare, corriga, enmiende) las equivocaiones en su familia más grande. Él
debe comportarse bien dentro del circulo familia tal que las personas no habrían
descubrir faltas que destruyan su familia.
Ifadowole
30
Ifadowole
Òyèkú Ògúndá B
' '
Ifá pé emí eléyìun ó gùn. Àbá burúkú ò níí se lé e lórí; ebo ni kó rú.
' '' ' '
Òyèkú Ògúndá B
' '
Ifá dice que esta persona tendría vida larga. Nada malo le ocurriría, pero él debe realizar
sacrificio.
Es la orina de la media noche que produce las burbujas grandes en la suciedad (tierra,
estercol)
Ifadowole
31
Ifadowole
Ifadowole
32
Ifadowole
Òyèkú Òsá A
' pé
Ifá ' eléyìun
' ó ségun láyé è. Eboo kó le ségun ni kó rú. Ògún ò níí mú u. Gìrìpá òrúko
lebo. '' ' ' '' '' '
' '
Eye kan ní n´ fò I léérémi léérémi
Ó '
' fapá òtún nalè
'
Ó ró gbonrangandan ' bí okó
Eye kan' ní n´ fò I léérémi' léérémi '
'Ó fapá
' òtún nalè
'
Ó ró gbònràngàndàn ' bí àdá
'
Ogun ò dúó ní kòtò odò mó
Ogún dúó ní gegele sáále sáále '
A díá fún Òrúnmìlà
Wón ní kí 'Baba ó rúbo
Kó' le fÀjìjà wó won mólè ' fíínfíín
' ' '
Òrúnmìlà ní n´ bèèrè pé ogun tí ón gbé ti òun yìí
' '
Òún ségun nbè ´
' ' '
Wón ní gbogbo ogun òhún ní ó run
Wón' ní Àjìjà owóò rè 'ní ó móo fi nalè
'
Òrúnmìlà bá rúbo ' '' ' ''
'
Òrúnmìlà bá lé gbogbo' ogun lo
'Ayé bá n´ dára '
Òrúnmìlà lóun ò níí jógun ó mú won nlé ´ ayé
' ón bá rúbo
Bí '
N ní' wá n´ jó 'ní wá n´ yò
Ní n´ yin àwon Babaláwo '
'
Àwon Babaláwo n´ yin Ifá
Ó ní' béè làwon Babaláwo tòún wí
Eye kan ' ' ní n´ 'fò I léérémi léérémi
Ó' fapá
' òtún nalè
'
Ó ró gbonrangandan ' bí okó
'
Eye kan ní n´ fò I léérémi' léérémi '
'
'Ó fapá òtún nalè
'
Ó ró gbònràngàndàn ' bí àdá
Ogun ò 'dúó ní kòtò odò mó
Ogún dúó ní gegele sáále sáále '
A díá fún Òrúnmìlà
Wón ní kí Baba ' ó rúbo
Kó' le fÀjìjà wó won mólè ' fíínfín
Babá gbébo nbè ' ' '
´
Ó rúbo ' '
Mo ló' fÀjìjà wó won mólè
Gbonrangandan ' ' '
Babá ' ti fÀjìjà wógun mólè
Gbonrangandan ' '
Àjìjà' ti wógun mólè
Gbonrangandan ' '
'
Ifadowole
33
Ifadowole
Òyèkú Òsá A
' dice
Ifá ' ' esta persona habría ganar en la vida. Él debe ofrecer sacrificio para hacerle
que
ganar. Ifá lo desea bien y que ninguna guerra lo arrestaría. Un macho cabrío maduro es
el sacrificio.
Ifadowole
34
Ifadowole
Òyèkú Òsá B
' pé
Ifá ' kí' eléyìun ó rúbo kí ire ó lè ba à wolé.
' '
Atéérété orí àsá
Enì' 'ó 'gun' àsá yò
A díá fún Kúrúnrú '
Omo abímo ní pupa ní pupa
Ó' bí' gbogbo ' omo è tí ón rí bélénjé ´
' ' ' '
Wón ní ó rúbo bí àwon omo è ó se' wo ilée rere ' '
Kí 'ònà ó là fún ' won ' ' ' ' ' '
'
Ti ire ó móo se gégée won '
Kí wón ó mó ' ' 'dìí òná ' ' fún won
Kúkúnrú ní ‘Tóun' tí bí omo' lópòlopò’
' '
‘Ó di dandan kí wón ó móo ' ' ràyè
' ' wolé
' ' nbii
´ wón bá de’
À á séé mo Kúkúnrú ' omo' abímo
' ní pupa? '
N làá pé Àgbàrá ' ' ' '
Eníkan ò jé jé ó wo inú ilé
' Àgbàrá 'bá' ti lóun
Bí ' ó kòólé èèyàn báyìí
Wón ó móo pé kó móo lo
Kó' móo lo' ' '' '
Yóó bàá ' ' móo' lo
Àyìn éyìn ni' ' Àgbàrá ' n´ yin àwon Babaláwo è
'
Ó ní Atéérété orí àsá ' '
' '
Enì ó gun àsá yo ' '
A díá fún kúkúnrú ' Omo abímo ní pupa ní pupa
Kúkúnrú Omo abímo ' ní' pupa 'ní pupa làá pàgbàrá
'
Mó jèé iré ó nù mí dákun ' '
''
Èlààsòdè
Ifá mó jèé iré ó nù wá dákun
Èlààsòdè ' ''
'
Òyèkú Òsá B
' le
Ifá ' pide
' a esta persona realizar el sacrificio tal que sus buenas fortunas entrarían bajo
su tejado.
Ifadowole
35
Ifadowole
Ifadowole
36
Ifadowole
Òyèkú Ìká A
' póun
Ifá ' pé ire fún eléyìun. Ire ó to lówó, sùgbón kó rúbo, kó sì bo Orí e. kó móo bèèrè
nnkan
` `
tí Oríi rè ó gbà. Nnkan ' bá
tí Oríi rè ' 'gbà ni
' kó fún un.
' ' ' ''
' '
Gúnnugún bà lórùlé
Ojúu re a tólé
Ojúu re' a móo tóko
' Sànìyàn ''
A díá fún
Sànìyàn tíí serú ìpín lórun
Wón ní ó rúbo '' '
' '
Oníkálúkú ló ti yan ìpín tí òún ó jèé nnú ´ ìyá è
´
Ngba tí n´ bò látòde òrun ''
´
Ngbà ó dé ilé ' ayé '
N´ wá n´ bèèrè pé bóo lòun ó ti se
Wón ‘ní o ó pé bóo ni’? '
'
Ebo lÒrúnmìlà mò
' ' ' nnkan
Gbogbo téé' bá yàn tí ò bá dáa
`
Òun ní ó móo báa ' ' tín fi ebo gbé e sójú ònà
Wón ní kó lòó ' ' bo Orì è ' ' ' '
' '
Wón lórí móoó bá won jà ' ' '
Wón ' ó móo' pé ' ' Ifá ni '
'
Ló bá rúbo ' '
Ayé ye wón '
'
Wón bóójú ònà '
Wón ' ní béè 'làwon Babaláwo tàwón wí
'
Gúnnugún ' ' bà lórùlé ' '
Ojúu re a tólé
Ojúu re' a móo tóko
A díá fún ' Sànìyàn ''
Sànìyàn tíí serú ìpín lórun
Wón ní ó sá' 'kàalè ó jàre '
Ebo ' ní ó se '
'Won ' nÍfá' ni
'
Sànìyàn
BÒrí bá n´ bá woón jà
Won a nÍfá ni ' '
'
Sànìyàn
Àsé Orí ní n´ bá woón jà làyé?
' ''
Òyèkú Ìká A
' desea
Ifá ' bien a esta persona. Las buenas fortunas tocarían su mano pero él debe
ofrecer sacrificio. Ifá le pide que ofrezca sacrificio a su Orí; y también pregunta de lo
que su Orí aceptaría. Es esa cosa deseada por su Orí que él debe ofrecer. Sus cosas no se
pondrían estropear (echar a perder).
Ifadowole
37
Ifadowole
Òyèkú Ìká B
' pé
Ifá ' a kò gbòdò kórira, a ò sì gbodò hùwa Ilara sí omonìkejì ntórí owó tàbí ipò.
´
' ' ' ' ' '
Oníse won ò fiseé lé rebi
Ìgbín ' ní 'n´ ràjò to file è serù rù
Òjììji lègè ' ''
' '
Òjììji lògò
Òjììji ò níí fOlúwa rè sílè
Kó sá wo inú omi lòó ' gbé '
A díá fún Òyé' ' '
Níjó tí n´ sawoó' ' ròde Ìká
'
Wón ní ó rúbo
Òyè ' ní n´ sawó' ròde Ìká
'Ìká' sì tí n´ be níbè tí n´ sawo
´
Ngbà Òyé dóhùún
Ó bèrè' sí 'Ifáa' se lóde Ìká
Ká sì ' rí
' kéré ká' je kéré
Ká rí wòmù ká je' wòmù
´ '
Ìká nsòótó ' '
Bí ebó bá' gba òké méjo
' ' ' ' ' '
Ifadowole
38
Ifadowole
Los perpetradores malos no dejarían su maldad en la casa y viaja en alguna otra parte
El caracol estaba siguiendo un viaje y llevó su concha como carga
Òjììji lègè
Òjììji lògò
La sombra no habría salir es su asunto
Para vivir en las aguas profundas
Adivinación lanzada para Òyé
Un sacerdocio aventurando en la ciudad de Ìká
Le pidieron que realizara sacrificio
Ifadowole
39
Ifadowole
Ifadowole
40
Ifadowole
Òyèkú Òtúrúpòn A
' póun
Ifá ' ' un. Eléyìun n´ póun bù kù; yóó gbayì lájo. Ebo ni kó rú.
pé ire fún
' ' '
Eékún ni sébúké
Èdò ni pàránkàtá' '
A' díá
' fún Dùndún tí ón n´ pé lÁàfin òsán gangan
Dùndún ni ò ti réni pè' é '
Kò gbayì '
Enìkan ò mò ó télè rí
'
Dùndún ' ' àwon
bá to ' ' Eékún ni sébúké lo
Ó loòdò àwon Èdò ' ' n ni pàránkàtá` ' ' '
E ye' ' òun' lóókan
' ' ìbò ' wò
'Wón' ní kí Dùndún ó rúbo
Wón' ní Òwúùrù eyelé lebo '
Wón' níre lópòlopò ' 'fún ' Dùndún
' '
'
Dùndún bá rúbo ' ' ' '
Ló bá di àbàadì'
Ni ón bá ránsé pé wón n´ pè é lÁàfin
Òun' náà? ' ' '
Tóun tí n´ be láì rénìkan bá seré
N ní wa n´ jó' ní wán ' yò '
Ní n´ yin awon Babaláwo '
Àwon Babaláwo ' n´ yin Ifá
'
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Eékún' ni ' sébúké'
Èdò ni pàránkàtá' ' '
'Díá' fún Dùndún tí ón n´ pé lÁàfin òsán gangan
Ebo n wón ní ó se ' '
'Dùndún
' 'wáá gbébo ' nbè
Ó rúbo ' ' '
'
Mo mò ti sebo Òyèkúbàtúrúpòn
'
Ire gbogbo 'wòmù!
' ' ' '
Ayée wá tutù '
Ayé nini
Òyèkú Òtúrúpòn A
' ' persona está' quejándose del retraso de éxito de sus aspiraciones. Ifá dice que él se
Esta
honrará en la vida. Pero debe realizar el sacrificio.
Eékún ni sébúké
Èdò ni pàránkàtá
Adivinación Lanzada para Dùndún el tambor que se envió inesperadamente para el
palacio
Dùndún nunca había visto antes cualquiera para invitarlo
Él no era importante
Nadie prestó alguna atención a él
Dùndún fue entonces al sacerdote 'Eékún ni sébúké'
El sacerdote 'Èdò n ni pàránkàtá'
Por favor lance adivinación usando Ìbò para mí
Ellos le dijeron a Dùndún que ofreciera el sacrificio
Ifadowole
41
Ifadowole
Òyèkú Òtúrúpòn B
' ' ìségun ni kí' eléyìun ó rú nítorí ikú, àrùn, òfò, ati gbogbo Ajogún pátá. Gìrìpá òrúko
Ebo
'lebo.' 'Ti' bá n gbébo loòdò Èsù, Ifá pé kó móo jó, kó sì móo yò ni. Torí wón yan èèyàn '
só ' o.
' ' ' '' ' ' '' '' ' '
' '
Gangatè
Gangatè Ganga
A díá fún Òrúnmìlà
Níjó tí n´ be' láàrin Òtá sángílítí
Ifá n´ be ségun ' àwon ' Ajogún
Òún ségun àwon Ajogún tó dí òun mólé yìí?
Wón 'ní ' kó rúbo'
Wón' ní ikú n´ só' o
' n´ só o ' '
Àrùn
Òfò n´ só 'o '
Gbogbo' Ajogún ' pátá ní n´ só o
Ó bá rúbo ' '
´
Ngbà '
tí ó móo gbébo lo fún Èsù
Wón ní kó móo ' ' dárin ' ' '
'
Kó sì móo jó ' '
Àwon tí sì ' ' n´ só o go sí kòrò légbèé ònà
' ' '
' nígbà
Wón n´ wó ó bò tí n´' gbé
' ' eboó ' ' lo
' fÉsù
'
Wón rí Òrúnmìlà tí n´ jó ' ' ' ' ' '
Ní 'n´ yò '
Ní n´ pé' jé n jó hàn ó
Gangatè ' '
Gangatè Ganga
Ikú je n jó hàn ó
' '
Ifadowole
42
Ifadowole
Gangatè
Gangatè Ganga
Àrùn jé n jó hàn ó
Gangatè ' '
Gangatè Ganga
Òfò jé n jó hàn ó
Gangatè' '
Gangatè Ganga
Òràn jé n jó hàn ó
'
Gangatè ' '
Gangatè Ganga
Ajogún jé n jó hàn ó
Gangatè ' '
Gangatè Ganga
Wón bá n´ wo Òrúnmìlà pèlú ìyanu
'
Òrúnmìlà bá gbébo' '
kalè níwájú Èsù
' bá bù nnú ´ è'
Èsù ' '
'
Ló fún Ikú '
Ikú je é
Ó fún' Àrùn
'
Àrùn je nnú ´ è
Ó fún Òfò ' '
Òfò náà je nbè ´
Gbogbo Ajogún ' ' pátá nikú fún
Gbogbo won ni ón je nnú è
´
Ngbà ó jé pé' Èsù' ni 'Baba àwon ' Ajogún
'
Òun níí páse fún won ' '
Bí gbogbo 'Ajogún' ' sì ti bá ni jeun
bá
Wón ò gbodò múni mó '
Wón ' ní Ikú ' è' é jeun eni ' kó pani
'
Wón ò bá le pa Òrúnmìlà mó ' '
Ifá' pé ayé ó ye eléyìun. ' '
'
Òyèkú Òtúrúpòn B
' ' persona debe
Esta ' ofrecer sacrificio. La vida lo agradaría, pero él debe ofrecer sacrificio
para superar muerte, enfermedad, pérdida, y hechizos malos. Una cabra madurada es el
sacrificio. Cuando él está tomando su sacrificio a Èsù, Ifá le pide que baile porque sus
enemigos están mirándolo para un resbalón.
Gangatè
Gangaatè Ganga
Adivinación lanzada para Òrúnmìlà
En el día que él estaba en medio de sus jurados enemigos
Ifá estaba en medio de los hechizos malos
'¿Habría yo superar todos estos hechizos que habían rodeado en mí '?
Ellos le dijeron a Òrúnmìlà que ofreciera sacrificio
Y esa Muerte está mirándolo
La enfermedad está mirándolo
La pérdida está mirándolo
Todos los hechizos malos están mirándolo
Ifadowole
43
Ifadowole
Él realizó sacrificio
Cuando él habría estar tomando su sacrificio a Èsù
Ellos le dijeron que cantara una canción
Y estubiera bailando
Pero aquéllos que estaban mirándolo han estado en su sendero
Ellos le vieron tomar su sacrificio a Èsù
Ellos vieron a Òrúnmìlà bailando
Él estaba regocijando
Él estaba cantando 'Permítame bailar a su admiración'
Gangatè
Gangaatè Ganga
Muerte, permítame bailar a su asombro
Gangatè
Gangaatè Ganga
Enfermedad permítame bailar a su asombro
Gangatè
Gangaatè Ganga
Pérdida permítame bailar a su admiración
Gangatè
Gangaatè Ganga
Dificultad permítame bailar a su admiración
Gangatè
Gangaatè Ganga
Ajogun, permítame bailar a su admiración
Gangatè
Gangaatè Ganga
Todos miraron a Òrúnmìlà con la sorpresa
Òrúnmìlà puso su sacrificio ante Èsù
Èsù sacó de él
Él dio a la Muerte
La muerte comió su porción
Él dio a la enfermedad
La enfermedad comió su porción
Èsù también dio a la pérdida
La pérdida comió su porción
Todos los Ajoguns fueron servidos sus porciones respectivas por Èsù
Todos ellos comieron sus porciones
Y desde que Èsù es el líder de todos los Ajoguns
He is the one that instructs and make provisions for them all
Ellos dijeron una vez que cualquier Ajogún come fuera de uno la comida
Sería imposible para ella desnudar sus colmillos en uno de nuevo
Ellos dijeron que la muerte no come la comida de uno y todavía mata uno
Ellos no podrían matar Òrúnmìlà de nuevo
Ifá dice que la vida agradaría a esta persona
Ifadowole
44
Ifadowole
Òyèkú Òtúá A
'Ifá ' pé ire fún eléyìun, sùgbón kò gbodò sahun pàápàá nítorí iyèfun èlùbó. Kò gbodò se
ahun sí Obìnrin rè. Kò ' gbodò ' fi oúnje
' 'dun
' èèyàn torí àwon èèyàn
' ' nbe
' oúnje je
tí ò rí '´ '
' ' ' '
nítòsí é. Tí ò bá ti sahún, yóó gàádùn ayé è. ' ' ' '
' ' '
Elélùbó etí àjà
A día fún ' Òyè
Èyí tíí soko' Òtúá '
Wón ní ó rúbo' '
Wón ' ní kò gbodó ' se ahun sí èèyàn
'
Wón ní kó móo foúnje ' ' ' toro
Òyé ' bá rúbo ' ' ' '
'Ní bá' n´ fi èlùbó ' toro
Gbogbo àwon iyá' arúgbó ' ' `
tí ò ti rí nnkan je
Yóó bu èlùbó ' fún won '
'
Ifá pé kí eléyìun ó mó foúnje dùùnyàn '
Òyé bá soko Òtúá dalé ' '
'Ayé' ye Òyè ' ' '
N ní wá ' 'n´ jó' ní wá n´ yò
Ní n´ yin àwon Babaláwo '
Àwon Babaláwo ' n´ yin Ifá
'
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Elélùbó' ' etí àjà '
A díá fún ' Òyè
Èyí tíí soko' Òtúá '
Ebo n wón ' ' ní ó se
' ' ' nbè´ '
Òyé gbébo
' ' ' ' '
Ó rúbo
'
Taa ní ó soko Òtúá fún wa?
Òyé ' '
' '
Òyé ní ó soko Òtúá fún wa
Òyé ' '
' '
Òyèkú Òtúá A
' desea
Ifá ' bien a esta persona. Él no debe ser sobre todo avariento encima de polvo del
ñame. Él no debe ser cerrando puños hacia su esposa: porque él vería mucha fortuna en
tierra. Él generalmente no debe hambrear a las personas porque allí está hambreando a
las personas cerca de él. Cuando él no es tacaño (avaro), él disfrutaría su vida.
Ifadowole
45
Ifadowole
Ifá le aconseja fuertemente a esta persona que no hambree a las personas con comida
Òyè se volvio el marido de Òtúá hasta el final
Vida agradable Òyè
Él estaba bailando entonces y estaba regocijado
Él estaba sublevando su Babaláwo
Su Babaláwo estaba alabando su Ifá
Él dijo que que era exactamente como su Babaláwo había dicho
Elélùbó etí àjà
Adivinación lanzada para Òyè
El que sería el marido de Òtúá
El sacrificio era el antídoto prescrito
Òyè oyeron hablar del sacrificio
Y lo realizó
¿Quién habría ser para nuestra causa el marido de Òtúá?
Òyè
Òyè habría ser para nuestra causa el marido de Òtúá
Òyè
Òyèkú Òtúá B
' póun
Ifá ' pé ire fún eléyìun. Kò níí sàárè. Kó si rúbo eni tí n´ be lókèèrè kí wón ó jo n´
araa won. ' ' ' ' ' '
'
Pákúdidi Pàkùdidi
Pákúdidi ló gbélé bí odún méta
Béè nio won ò fojú kan ' araa 'won
' '
Adíá fún Òyè ' '
' rèé
Níyó ti n´ lo ' kóbi lówó Òtúá
'
Wón ní kó rúbo ' '
Wón ' níre rè n´ bó'
' '
Wón ní ò níí rí àárè '
Ó no' Pákúdidi ló gbélé' bí odún méta
Béè ni won ò fojú kan araa' won '
' ' fún 'Òyè
Adíá '
' rèé
Níyó ti n´ lo ' kóbi lówó Òtúá
Bá ni kòbi wá dákun ' '
'
Òyé
' 'ni kòbi wá dákun
Bá
Òyé
' '
Òyèkú Òtúá B
' desea
Ifá ' bien a esta persona. Él no se caería enfermo. Él debe ofrecer sacrificio para un
socio o tal amigo que vive en el extranjero que habria ver cada uno vivo.
Pákúdidi Pàkùdidi
Pákúdidi vivió dentro de los mismos cuartos entre otro
Todavía no ve cara a cara
Adivinación lanzada para Òyè
En el día él iba traer kola de Òtúá,
Le pidieron que ofreciera sacrificio
Ifadowole
46
Ifadowole
Ifadowole
47
Ifadowole
Òyèkú Ìretè A
' pò
Ire ' fún 'eléyìun.
' Wón ó móo peléyìun ti dàgbà pé kò le bí omo mó. Ifá pé yóó bímo
láyé è. Ifá pé omo là n´' dá Ifá' sí.
' ' ' ' ' '
' ' '
Òpòkúretè
' ' esín
Eran ' 'kún mi lénu tétéété
'A díá 'fún ' Ìyálóde Òpò ' ' '' '
Ekún omo ní n´ sun
'
Òún le' bìmo ' láyé òun báyìí?
Wòn ní kó rúbo '
'
Wón níre ó to lówó '
Wón ' ní Àgbébò' adìe ' lebo
'
Eku, Eja lebo ' ' ' '
'
Ìyálóde Òpó bá rúbo ' '
Wón bòkè ìpòrí e fun '
'
Ìyálóde tí ón ti n´ pé ó dàgbà' '
Ló bá lóyún '
Ló bímo
Omo kún ' ilè
'Ìyálóde
' bá n´ jó ní n´ yò
Ní n´ yin àwon Babaláwo '
Àwon Babaláwo n´ yin Ifá '
Ó ní' béè làwon Babaláwo tòún wí
Òpòkúretè '' '
'Eran ' Esín ' ' kún mi lénu tétéété
A ' díá 'fún ' Ìyálóde Òpò ' ' '' '
Ekún omo ní n´ sun
'
Wón ní' ó ' sá kàalè ó jàre
'
Ebo ní ó se '
Ó ' gbébo
' '
nbè
Ó rúbo ' ' '
Taa ló' bímo báwònyí beere?
Ìyálóde Àgbà ' ' '' '
Ló bímo báwònyí beere
Ìyálóde' Àgbà' '' '
Òyèkú Ìretè A
' ' está en la necesidad de niños pero las personas dirían que es demasiado
' ' persona
Esta
tarde para sus niños debido a su edad.
Òpòkúretè
La carne de caballo llena mi boca al borde
Adivinación lanzada para Ìyálóde Òpò
Ella estaba llorando debido a los niños
'Yo podría tener niños en la tierra'? Ella preguntó
Ellos le dijeron que ofreciera sacrificio
Que la buena fortuna de niños vendría a ella
Una gallina madura es el sacrificio
Ratas, Peces son los objetos sacrificatorios, ellos dijeron
Ìyálóde Òpò obligó a los sacrificios
Ifadowole
48
Ifadowole
Òyèkú Ìretè B
' pé
Ifá ' '
' ki eléyìun ó rúbo, àwon méjì ni ón jó páwon n´ lo ibì kan. Kí wón ó rúbo kí ààyè ó
' mó 'jèé pé ààyè' ò níí
lé gba àwon méjèèjì; kó ' gba' enìkejì.
' Ifá pé ká fi àdá
' rúbo.'
' '' ' '
Òpòkúretè
' ' esín
Eran ' 'kún mi lénu tétéété
'A díá 'fún
' Èèsún òun ' Ìrèké' '' '
Níjóo wón n´ lo rèé bá won múlè lákùrò
Wón ' ' ní kí wón' rúbo ' ' '
' àti Ìrèké
Èèsún ' ni ón ' jó n lo Àkùrò
´
Èèsún ló kókó dé ibè ' ' '
Ló ti múlè ' ' '
Wón ní ìwo ' Èèsún rúbo kí ààyè ó le gbà ó
'
Èèsún ní taa ' ní ó wàá mú ' òun '
´
Ngbà ó yá àwon èèyán bá rí Ìrèké
Wón bá mú Ìrèké ' lo sí àkùò
Wòn' rí èèsún tó ti hù ' lo súà'
'
Wón ní ‘kín lèyí’? '
Wón' bámú àdá tí ón ní kí Èèsún ó rú lébo
Wón' fi gé Èèsún kúò ' ' '
Wón' fààyè gba Ìrèké
' ló rúbo
Ìrèké
N ní wá n´ jó' ní wá n´ yò
Ní n´ yin àwon Babaláwo '
'
Àwon Babaláwo n´ yin Ifá
Ó ní' béè làwon Babaláwo tòún wí
Òpòkúretè '' '
' ' esín
Eran ' 'kún mi lénu tétéété
' '' ' ' '' '
Ifadowole
49
Ifadowole
A díá fún Èèsún òun Ìrèké níjòo wón n´ lo rèé bá won múlè lákùrò
Ebo n wón ni kí wón ó se '' ' ' '' ' '
Taa ní n´ 'be léyìn tó' rúbo?
Ìrèké nìkàn' ' '
Ìrèké nìkàn ní n´ be léyìn tó rúbo
Ìrèké nìkàn ' ' '
Òyèkú Ìretè B
' pide' a 'esta persona que ofrezca sacrificio porque él y otra persona están planeando
' le
Ifá
un viaje en alguna parte. Ellos dos deben realizar sacrificio tal que se acomodarían los
dos; o tal que no habría resultar que únicamente de ellos habría ser acomodado al
expensas del otro. Ellos dos deben ofrecer un machete cada uno como sacrificio.
Òpòkúretè
La carne de caballo llena mi boca al borde
Adivinación lanzada para el césped Èèsún y la Caña de Azúcar
En el día que los dos iban a escoger una tierra en el pantano
Les dijeron que ofrecieran sacrificio
El césped Èèsún y la Caña de Azúcar estaban yendo al pantano
Èèsún llegó primero al pantano
Él había escogido un pedazo bueno de tierra
'Usted el césped de Èèsún, ofresca sacrificio tal que le permitieran crecer ' ellos dijeron
'Quién me empujará fuera de aquí '? Èèsún contestó
Después de algún tiempo, el hombre vio la Caña de Azúcar
Él lo tomó al pantano
Él vio césped de Èèsún que tiene el ceño en su multitud
'Que es esto '? el Hombre preguntó
El machete que se asignó el césped de Èèsún para sacrificar
Ellos usaron el mismo machete para cortarla de la tierra pantanosa
Y le permitió a la Caña de Azúcar crecer en la misma tierra
Es la Caña de Azúcar que ofreció el sacrificio
Él estaba bailando y estaba regocijando
Él estaba alabando sus Babaláwos
Los Babaláwos estaban alabando Ifá
Él dijo que era exactamente como sus Babaláwos habían dicho
Òpòkúretè
La carne de caballo llena mi boca al borde
Adivinación lanzada para el césped Èèsún y la Caña de Azúcar en el día ellos dos iban
al Pantano para escoger una tierra
Ellos les pidieron que realizaran sacrificio
¿Quién está a la espalda que ofreció el sacrificio?
La Caña de Azúcar exclusivamente
El es uno a espalda que ofreció el sacrificio
La Caña de Azúcar exclusivamente
Ifadowole
50
Ifadowole
Òyèkú Òsé A
' òun
Ifá pé ' pé
' ire fún eléyìun.
Ifadowole
51
Ifadowole
Òyèkú Òsé B
' '
Eléyìun 'n´ lo
' sí ibì kan. Ifá pé yóó di àrà nbè.
´
' '
Òyè kúsé kùsè kúsé
Á' díá
' fún' Àràbà' '
Èyí tí n´ lo rèé bá won múlè légàn
Òún le tóbi báyìí? ' ' '
Tóun ó borí àwon igi tó kù
Wón ní kí Àràbà' ó rúbo
' bá rúbo
Àràbà '
O dé inú egàn '
Ló bá ga ju ' gbogbo igi lo
Ni ón bá n´ pé igi kín níìí? '
'
Wón n´ pé Àràbà ni
Ifá' pé eléyìun ó lòóko rere láyé yìí
Òyè kúsé kùsè kúsé
Á' díá
' fún' Àràbà' '
Èyí tí n´ lo rèé bá won múlè légàn
Ebo n wón ní ó se ' ' '
'Araba
' ló' bá won' múlè légàn
Ó yorí ' ' '
Ó ju gbogboo won lo
' '
Òyèkú Òsé B
' dice
Ifá ' ' ' esta persona esta en alguna parte de viaje. Ifá dice que él se volvería una
que
persona de importancia allí.
Ifadowole
52
Ifadowole
Òyèkú Òfún A
' pé
Ifá ' òún pé ire fun eléyìun. Isu mérìndínlógún lebo. Kí àwon Babaláwo ó be èèpo isu
òhún sórí ebo è. ' ' ' ' ' ' '
' ' ' '
Pétótókótó Awo Olóríì
Adíá fún Èèyàn
Èèyàn tíí serú Ìpín lórun
Wón ní kó' 'fi isu rúbo '
'
Ó bá rúbo ' '
Oníkálukú ' bá n´ nísu lára
Ayée wón n´ dára '
Ifá pé okàn' eléyìun ó balè
Pétótókótó Awo Olóríì '
'
Adíá fún Èèyàn tíí serú Ìpín lórun
'
Ebo n wón ní ó se ' '
'Èèyàn
' gbébo ' nbé
´ '
Ó rúbo ' ' '
` '
Ìyànnyàn
E wá wosé Ìpín n´ se
' ` ''
Ìyànnyàn '
Ìpín mò n´ lájé
` '
Ìyànnyàn
E wá wosé Ìpín n´ se
' ` ''
Ìyànnyàn '
Ìpín sì n´ láya
`
Ìyànnyàn
E wá wosé Ìpín n´ se
' ` ''
Ìyànnyàn '
Ìpín sì n´ bímo
Ìyànnyàn '
`
E wá wosé Ìpín n´ se
' ` ''
Ìyànnyàn '
Gbogbo ire pátá nÌpín n´ ní o
`
Ìyànnyàn
E wá wosé Ìpín n´ se
' ` ''
Ìyànnyàn '
Òyèkú Òfún A
' ' persona debe ofrecer dieciséis tubérculos de ñame. El Babaláwo debe raspar las
Esta
cáscaras del ñame en el sacrificio
Ifadowole
53
Ifadowole
Adivinación lanzada para los seres Humanos los esclavos del destino en el cielo
Les pidieron que realizaran sacrificio
Los seres humanos oyeron hablar del sacrificio
Y lo realizaron
Ìyànnyàn
Venga y vea el trabajo del destino
Ìyànnyàn
El destino tiene la riqueza
Ìyànnyàn
Venga y vea el trabajo del destino
Ìyànnyàn
El destino tiene las esposas
Ìyànnyàn
Venga y vea el trabajo del destino
Ìyànnyàn
El destino también tiene los niños
Ìyànnyàn
Venga y vea el trabajo del destino
Ìyànnyàn
El destino tiene todas las cosas buenas de la vida
Ìyànnyàn
Venga y vea el trabajo del destino
Ìyànnyàn
Ifadowole
54
Ifadowole
Òyèkú Òfún B
' pé
Ifá ' òún pé ire fún eléyìun. Ayé ó ye é, sùgbón kó sóra fún aráyé o. Ifá pé kí àwon
' ' wón
omo ení ó dá Ifá yìí o mó yàájú sí babaa ' o. ' '
' ' ' ' '
Òyèkú yà fokùú
' 'fún Ìkà
Yà
Béèyàn ò bá yà fún Ìkà
Ìkà ó wulè tè é pa pátápátá ni
A díá fún ' Baálé
' '
A bù fún Omo
Wón ní kí' wón ' ó rúbo
Òkùràkùtà '
Babá mò n´ rìn nlè
'
Omo n´ gesin! '
Òkùràkùtà ''
Èyin ò mò páyé doníran ìran
' '
Òyèkú Òfún B
Ifá '
' desea bien a esta persona. La vida lo agradaría pero debería tener cuidado del
hombre y sus bufonadas. Los niños de esta persona nunca deben ser pomposos a su
padre.
Ifadowole
55
Ifadowole
Ifadowole
56
Ifadowole
Ifadowole
57