Está en la página 1de 1

*ATUDE ASINA IWE WEGUN WEPE*

Omumu ewe peregun 1


Egbo peregun
Efo yarin
Epo obo
Egbo tude
Erele oparun
Oko atare
A o gun gbogbo re po mose dudu a o ma fiwe lodo tinsan, ti a bawe tan aofi omi igbin para a o so igbin ye sodo
ti atiwe.

*ATUDE IWE ODO ASINA KIAKIA*


Efo yarin
Ewe imiesu,
Epo obo
A o gun pomose iwe ekan a o fi epo pupa para kato we lodo tinsan.

*ATUDE ASINA IWE ODO*


Igbe eyele
Eyo atare 9,fun okunrin, 7 fun obinrin
A o gun pomose dudu, a o fiwe lodo tinsan.

*ATUDE ASINA*
Koronfo eyin adie topa
Igbe gbigbe ti a ko mo eniti osu, a o lo po mose dudu, a o fiwe lodo tinsan, a o fi epo pupa para katowe.

*ATUDE ASINA IWE ODO*


Isu ogirisako
Egbo tude
Oko atare
A o gun po mose dudu, a o fiwe lodo tinsan.

*ATUDE ASINA IWE ODO*


Ewe ewuro
Ekolo
Epo obo
A o gun pomose dudu, a o fi epo pupa die si, a o fi we lodo tinsan.

*IKILO PATAKI*
Ti a bade odo, a o koju si ibi ti omi tin bo, a o ko eyin si ibi ti omi san lo.

También podría gustarte