Está en la página 1de 7

EBB DE ESTERA

OJUANI SHOBE

OJUANI SHE SHOBBE ACH M , ACH ADIE ,ACH ODDANI OMO OFO UNTORI.
OJUANI SHOBI TABAKOYU BAIN-BAIN IKU BAIN-BAIN LOBATI ADIFAFUN O UN AWO
MEDILOGUN TINLODIFA ILE OLOFIN

Con las palmas hacia arriba sobre la estera ,moviendo los dedos sobre la estera se canta:

OJUANI SHOGBE LER ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE


Coro: OJUANI SHOGBE LER ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE
OJUANI SHOGBE LER ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE
Coro: OJUANI SHOGBE LER ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE
OJUANI SHOGBE LER ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE
Coro: OJUANI SHOGBE LER ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE

EYIOKO

EYIOKO KINI OMO FAKO, NKA BURUK EGGN, ONA TEMI TAN TEMI LE SIKO TO LER KO LE
MIM ,UMBA LEKO
OYEKU MEJI, OYEKU MEJI, OYEKU MEJI LEEMETA. MO BE YIN, BI IKU BA SUNMO ITOSI KI E BAMI
YE OJO IKU FUN. SI EHIN OGUN TABI OGORUN ODUN, TABI BI IKU BA NBO KIE BAMI YEE SI EHIN
OGOFA. ODUN TIATIBI MI SINU AYE KI E BAMI YE OJO IKU FUN ARA MI ATI AWON OMO MI TI MO
BI. KIAMAKU NI KEKERE, KIAMAKU IKU INA, KIAMAKU IKU ORO, KIAMAKU IKU EJO, KIAMAKU
SINU OMI.
YY KE WA YO FUN (IRE) MI O. YY KE WA YO FUN (IRE) MI O. A MI Y NIL, A MI YO LJ.
YY AY E, YY.

EYIOKO TEMITA, TEMITA INCH TEMINNOLOKUN MOYUBA ASHE, MOYUGBA OLOKUN


EYIOKO TEMITA, TEMITA INCH TEMINNOLOKUN MOYUBA ASHE, MOYUGBA OLOKUN
EYIOKO TEMITA, TEMITA INCH TEMINNOLOKUN MOYUBA ASHE, MOYUGBA OLOKUN

OGUNDA

OGGUNDA IT OFERAYESUN, EBANSUN ELEM


OGUNDA AFARAYE, AFESUYE LESILOSUN
OGUNDA MEJI, OGUNDA MEJI, OGUNDA MEJI,
MO BE YIN, KIEDAI NIDE ARUN ILU EJO, EGBESE ATI BEEBEE, KI E D ARI IRE OWO, ISE ORO OMO
OLA EMIGIGUN, ARALILE ATI BEEBEE S ODO MI, KI E DA MI NI ABIYAMO TIYOO BIMO RERE TI
WON, YOO GBEHIN S I SINU AYE ATI BEEBEE. OGUNDA MEJI.

AKERE KONKO GBOGBO ONICH OLODDO.


ATARUM ATARUW ,KOS LEY LO KI LEYOO
Coro: ATARUM ATARUW ,KOS LEY KI LEYOO
ATARUM ATARUW ,KOS LEY LO KI LEYOO
Coro: ATARUM ATARUW ,KOS LEY KI LEYOO

ATARUM ATARUW ,KOS LEY LO KE IBBO


Coro: ATARUM ATARUW ,KOS LEY LO KE IBBO
ATARUM ATARUW ,KOS LEY LO KE IBBO
Coro: ATARUM ATARUW ,KOS LEY LO KE IBBO

OFUN-MAFUN

OFUN MAFUN YEYEDE ,OFUN SERO ,OFUN SAR OFUN FUN IK ,OFUN FUN ARO ,OFUN FUN INHA
,NKOL ECHU
OFUN MEJI OLOWO, OFUN MEJI OLOWO, OFUN MEJI OLOWO,
MO BE YIN, KI E FUN MI L OWO ATI OHUN RERE GBOGBO. EYIN LI E NFUN ALARA LOWO KI E FUN
EMI, NAA L OWO ATI OHUN RERE GBOGBO. EYIN LI E NFUN AJERO L OWO, KI E FUN EMI NAA L
OWO ATI OHUN RERE GBOGBO. EYIN LE E NFUN ORANGUN ILE ILA LOWO, KI E MASAI FUN EMI
NAA LOWO ATI OHUN RERE GBOGBO ATI BEEBEE TITI LO. OFUN MEJI OLOWO.
OFUN MAFUN KIMAFUN OFO, KIMAFUN ARUN, KIMAFUN ELLO, KIMAFUN GBOGBO ARAYE
KALEPA NIKU. OFUN MAFUN ARO MAFUN, MAFUN OFUN BREKETE OFUN SOLOYU,
WA MI KO MIO

OJORU JU-JU WA MI KO MO
OJORU JU-JU WA MI KO MO
Coro: OJORU JU-JU WA MI KO MO, OJORU JU-JU
EPA WA MI KO MIO.
Coro: OJORU JU-JU WA MI KO MO, OJORU JU-JU
WA MI KO MIO

IROSO

IROSSO IYALOCHA IT KIN KI EN ABB OFO, INHA ,IK IY OPO OMO LER OMO OLORUN IL
IYA ACH LEN
IROSUN MEJI, IROSUN MEJI, IROSUN MEJI,
MO BE YIN, KI E JEKI AWON OMO ARAYE GBURO, MI PE MO LOWO LOWO. PE MO NIYI, PE MO N
OLA, PE MO BIMO RERE ATI BEEBEE. KI E JEKI WON GBO IRO MI KAAKIRI AGBAYE, IROSUN MEJI.
EMI WON, EMI WON LE PA PNI. DR OR KI PA OR. EMI WON, EMI WON LE PA PNI.
AKUA MASHA, MASHA DIRE, KAFI KAPALENO AMBEBE KIN INAFUKUOSO, IROSO APATARITA
ABEBEKIN INAFUKUOSO KIN APANDEURE APALASHENU.

ABO NIRE KACHAR ABONIR, ABO NIRE


Coro: ABO NIRE KACHAR ABONIR, ABO NIRE
ABO NIRE KACHAR ABONIR, ABO NIRE
Coro: ABO NIRE KACHAR ABONIR, ABO NIRE
ABO NIRE KACHAR ABONIR, ABO NIRE
Coro: ABO NIRE KACHAR ABONIR, ABO NIRE

EYEUNLE

EYEUNL TEMI OMO SUNKUN, DEDE LA BOLU, DEDE LA BOSI, DEDE LA BALOSA , TOTO, TOTO
BA FIRENU, ODARA AKO, ALU BASHE ATI KO LER TO IBAN ARO, ARO TONU ALA BI SEN
EJIOGBE, EJIOGBE, EJIOGBE. MO BE YIN, KIEGBE MI KIMI NIYI, KI E EGBE MI, KIMI NOLA,
IFAKIFA KIINIYI KOJA EJIOGBE. EJIOGBE NI BABA GBOGBO WON. KI GBOGBO ENIYAN KAAKIRI
AGBAYE GBARAJO, KIWON MAA GBE MI NIJA, KIEGBE MI LEKE OTA. KI NLE KE ODI.
KIEMAA GBEMI NIJA KIEMAA GBE MI LEKE ISORO LOJO GBOGBO NI GBOGBO OJO AYE MI.
KIEMAA GBE IRE KO MI NIGBABOGBO TABI KIEMAAGBE FUN MI(O FUN NI IYAWO)
AY SRN TI DUN, O DUN JU OYIN L O. AY SRN TI DUN, O DUN JU OYIN L O.
RS J AY MI O DUN, ALYUN GBLYUN. RS J AY MI O DUN, ALYUN GBLYUN.
BI A BA BO OJU, BIA A BA BO IMU, ISALE AGBON NI A PARI RE. A DA FUN ORUNMILA NIGBATI O
NLO GBA ASE LOWO OLODUMARE. O RUBO OLODUMARE SI WA FI ASE FUN U. NIGBATI GBOGBO
AIYE GBO P O TI GBO ASE L OWO OLODUMARE NWON SI NWO T O O. GBOGBO EYITI O WI SI NSE.
LATI IGBANA WA NI A NWIPE

A LA MOIY ,ALA MOIY


Coro:ONA ENU KUA KUA IBBO
A LA MOIY ,ALA MOIY
Coro:ONA ENU KUA KUA IBBO
A LA MOIY ,ALA MOIY
Coro:ONA ENU KUA KUA IBBO

OBARA

OBBARA ENIBARA , EYEGBARA ,ELEGBARA KIKATE OMO KETE LAROFUN ECH JONJORO
YEYERO JONJORO, YOBI-YOBI LABB OBI OMA IL TO DEKOLE BAM OBARA MEYI ONIBARA
OLABARA EYEBARA KIKATE AWO KOMAKATO ARAYE KOMAKATE ARA ORUN ADAFUN BOGBE
EYEOKO OROFO LORUBO BOGBO TENUYEN KOKORO
OBARA MEJI, OBARA MEJI, OBARA MEJI,
MO BE YIN, KI E SINA AJE FUN ME, KI AWON OMO ARAYE WA MAA BAMI, RA OJA TI MO BA NIITA
WARAWARA, IPEKU ORUN E PEHINDA L ODO MI. IBARA MEJI DE AT BEEBEE OBARA, ONI BARA,
KIKATE IKU, KIKATE ARUN, KIKATE OFO, KIKATE ARAYE, TINSHE OMO OKUNI, KUALUJERO
OYANSO. AWN DE WA. AWN DR. OR IRE LAWUN NWE. ODN NBI, ODN NRE. ODN TI
ESELE IBD O. ODN TI ESELE IBD O.

OBBARA JI DUN DUN OBBARA JI DUN DUN.


Coro.......UM
OBBARA JI DUN DUN OBBARA JI DUN DUN.
Coro.......UM
OBBARA JI PIKUA; OBBARA JI PICUA.
coro........UM
OBBARA JI PIKUA; OBBARA JI PICUA.
coro........UM

TANI ONA OM FAO

OSA

OS GBOGBO ERIBO, ENIGBO ONATEM IK ,ARO ,OF INBAMTIN IL IYO IY ONIL


OSA NIKO, IWORIWO AWO, TANI FOKUN, AWO OWO SI KONKON OFADARA OSHORO.
OSA MEJI, OSA MEJI, OSA MEJI,
MO BE YIN, KI E JEKI NDI ARISA-INA, AKOTAGIRI EJO FUN AWON OTA, KIESO MI DI PUPO GUN
RERE, KIMI ROWO SAN OWO ORI, KIMI ROWO SAN AWIN ORUN MI ATI BEEBEE. OSA MEJI.

FUFULEKE FEFE IKU, OS MODA, MODA AFEFE IKU


Coro: ..........UM.
OS MODA, MODA AFEFE IKU
Coro: ..........UM
OS MODA, MODA IYANZA IKU
Coro: ..........UM.
OS MODA, MODA IYANZA IKU
Coro: ..........UM
ABO FIROLO, FIROLO BALE, ABO FIROLO, FIROLO BALE
Coro: ABO FIROLO, FIROLO BALE ABO FIROLO
FIROLO BALE
Coro: ABO FIROLO, FIROLO BALE ABO FIROLO
FIROLO BALE
ABO MURELE, MURELE GUALE, ABO MURELE, MURELE GUALE
Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE, ABO MURELE.
MURELE GUALE
Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE, ABO MURELE.
MURELE GUALE.

OSALO FOBEYO LAMINAGADDA TORI YAMPO BE LAMPE SHANGO KAWO


KABIESILE LAMINAGADDA ADIFAFUN ESHU YELU OBARONA OBA ESHU
YELU YENYE EWA NI OLOKUN ENI IFA ESHU YELU PIRITI OMODE
ALARA LAMPE SHANGO LAMINAGADDA.

ABO FIROLO, FIROLO BALE, ABO FIROLO, FIROLO BALE


Coro: ABO FIROLO, FIROLO BALE ABO FIROLO
FIROLO BALE
Coro: ABO FIROLO, FIROLO BALE ABO FIROLO
FIROLO BALE.
Coro: ABO FIROLO, FIROLO BALE ABO FIROLO
FIROLO BALE

ABO MURELE, MURELE GUALE, ABO MURELE, MURELE GUALE


Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE, ABO MURELE.
MURELE GUALE
Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE, ABO MURELE.
MURELE GUALE
Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE, ABO MURELE.
MURELE GUALE.

ODDI

ODD OCHA LOMAKO ,ELERIBB OCHA OMO IY AR OMOB IK, IK KODIMA ,EYO KODIMA
,OFO KODIMA. ODI, ASHAMA ARUMA, MAMA DINA KOYO DINA, ODI GAGA, ODI GOGO
OKURUJELE, ADIFAFUN OBATALA

ODI MEJI, ODI MEJI, ODI MEJI,


MO BE YIN, KI E BAMI DI ONA OFO, KI E BAMI DI ODO OFO, KI E BAMI DI ONA EJO, KI E BAMI DI
ONA IBI, KI E BAMI DI ONA ESHU, NI NRIDI JOKO PE NILE AYE. KIEMA JEKI NBA WON KU IKU
AJOKU. OKAN EWON KIIKE. KI E SE ODI AGBARA YI MI KA, KI OWO MI KAPA OMO ARAYE BI
OMO ODI TIIKALU.

Se canta:
TANI OBA LOWO MI ADD LOWO M, ADD LORISS
Coro: ADD LOWO M, ADD LORISS
ADD LOWO M, ADD LORISS
Coro: ADD LOWO M, ADD LORISS
ADD LOWO M, ADD LORISS
Coro: ADD LOWO M, ADD LORISS
ADD LOWO M, ADD LORISS
Coro: ADD LOWO M, ADD LORISS

OSHE

OSHE MULUKU, MULUKU SARA UNDE LEPELEPE, OCH PEL PEL , OCHE KALE ENI TULESHE
,OKO MALEK ,MALEK EN KODA, IGBA ACH ,LEGBA KOID FUN MI. IBA DE YEWA IYAKOIDE.
OSHE KULUKUSHE MULUKUSHE A WO, KULUKUSHE OMO.
OSE MEJI, OSE MEJI, OSE MEJI,
MO BE YIN, KI E FUN MI NI AGBARA, KI NSEGUN AWON OTA MI LONI ATI NI GBOGBO OJO AYE MI,
KIEMAA BAMI FI ISE SE GBOGBO AWON ENITI NWA IFARAPA ATI BEEBEE FUN MI. KI E JEKI NGBO
KI NTO KI NPA AWU SEHIN. OSE MEJI.

IFA DE YEWA FOUND; IFA DE YEWAOO I YAKOID


Coro: GBOGBO YEWA , IFADE YEWAOO IYAKOID
IFA DE YEWA FOUND; IFA DE YEWA I YAKOID
Coro: GBOGBO YEWA , IFADE YEWA OO IYAKOID

EYILA SHEVORA

EYILA SHEBORA AGANAGAYA, AGATIAFAYA INIRU KOCHETI IK ,KOCHE TI ARO


KI OMI TUTO TOKUN AINAEYILA SHEVORA KAWO KABIESILE OLUEKO ASI OSAIN INA RULU
BARA LU OLU KOSO BAMBIOYO.

Mientras se canta se aplaude:


E NI LU MAYO
Coro: Ee MAYO.
E NI LU MAYO
Coro: Ee MAYO.
E NI LU MAYO
Coro: Ee MAYO.

E NI LU MALU
Coro: Ee MALU.
E NI LU MALU
Coro: Ee MALU.
E NI LU MALU
Coro: Ee MALU.

Mientras se canta se llevan las manos a la estera y luego a la boca:


TANI ALADDO LEWAM. A LA DO BEGUANO
Coro: MOYE E MOFIY, EN ALADDO MOFIY
TANI ALADDO LEWAM. A LA DO BEGUANO
Coro: MOYE E MOFIY, EN ALADDO MOFIY
TANI ALADDO LEWAM. A LA DO BEGUANO
Coro: MOYE E MOFIY, EN ALADDO MOFIY

Mientras se canta se golpea el pecho con la mano izquierda:


GUARUOO AKUNAMB
AB AKUNAMB
GUARUOO AKUNAMB
AB AKUNAMB
GUARUOO AKUNAMB
AB AKUNAMB

----ALAFIN LEKEDDA

Se cambia de posisin y con la mano derecha en el caracol se canta:


LARILA FICHETE IBARAOTA.
LARILA FICHETE IBARAOTA
FICHETE IKU, FICHETE ARUN, FICHETE ELLO, FICHETE EGBA, FICHETE FITIBO, FICHETE AIINI EPO.
ORICHA FIFETO.....ARA GOGO 2 o 3 bis.
Se cambia nuevamente para la izquierda y se dice:
AS COMO CAMBIO DE MANO Y DE POSISIN CAMBIO OSOGBO PARA IR Y LO QUE LA MANO
DERECHA HIZO L IZQUIERDA NO LO PUEDA DESTRUIR

SE PROCEDE A PREGUNTAR QUE SE VA Y QUE SE QUEDA. DESPUS SE PREGUNTA SI CIERRA EL


EBBO Y SI ARUFI, ARUFI, ARUDDA, ARUDDA.

LUEGO SE PROCEDE A CERRAR EL EBBO CON EL EFUN Y OWO

El Iyabo levanta el ebb y lo deja caer encima del caracol (repite este acto tres veces) se recoje y se reza:

OKANA SA MOKESA BILARI AWA TETETE MOKESA BILARI IKU ARUN EYO OFO EGBA FITIBO
INYA..

Luego se pasa por encima de la cabeza 3 veces por encima de la cabeza de iyawo diciendo:
OKANA-SA BILARI ESHU BAWA TETETETE.
OKANA-SA BILARI ESHU BAWA TETETETE.
OKANA-SA BILARI ESHU BAWA TETETETE.

El Iyabo toma el ebb ,acompaado por la Oyugbona y lo deja el pie de Elegga.


cuando va a dejar el ebb se canta:

ODI FUMBO KARIDEFUN KARAWE DENDEFUN KARKO ELEGUA ESHU BAIKU NIWE INLE
MOWANILE ELEGUA ESHU ODARA OFUNDI ADIFAFUN ETBA AUN BATON LONI OBINI LELE EBEYI
AWO, ADIFAFUN AYE EYELE LEBO IDIFUN ADIFAFUN ESHU ANIRE LAWO OTAYEIBE ADIE
KOYOKO EYELE, BABALAYIKI AWO TENIYI AWO ELEGUARA SOKUN SOKUN LAYE OBUNDI
OFOJUDE ABURE ALODE EBBO , OBALU OGUN ODARABI AWO TENIYI OMO ELEGUARA ODI
FUMBO.
ECH O ,ELEGBARA , ECHU O ELEGBARA , ELEGBARA MOFORIBALE ,ELEGBARA AG

Cuando vuelve se agacha a besar la estera y el oriate le sopla efn por arriba de la cabeza.

Esta igba ashe orishas consistia en un guiro forrado con cuentas multicolores y
consagrada con los siguientes atributos:

1)Guacalote verde -representa el nacimiento(ibi).

2)Huesito de la pata del chivo representa a la muerte (iku)


3)El coral representa a sodorisha (jokosha)

4)El mate representa a osanyin

5)El ikin representa a orunmila

6)leri agboran (cabeza de muneca) representa los osobu

7)semilla de zapote representa a la enfermedad (arun)

8)Oro y plata representan los planetas

9)gbogbo ashe representa el ashe de olodumare

10)ileke gbogbo orishas (cuentas de los orishas) a los orishas

11)Igba (el guirito) representa el sacrificio (ebo).