Está en la página 1de 4

TEXTO YORUBA

¿De qué maneras podemos aclarar la aplicación de los textos bíblicos que leemos?


Àwọn ọ̀nà wo la lè gbà mú kí ìwúlò àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a kà ṣe kedere?
jw2019
Nos levantamos temprano y comenzamos el día en un tono espiritual analizando
un texto bíblico.
A máa ń jí lówùúrọ̀ kùtùkùtù, a óò sì fi ohun tẹ̀mí bẹ̀rẹ̀ ọjọ́ náà nípa ṣíṣàyẹ̀wò ẹsẹ
Bíbélì ti ọjọ́ náà.
jw2019
▪ Preparen juntos una breve presentación que incluya la lectura de un texto bíblico
y de un párrafo de una publicación.
▪ Ẹ jọ múra ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ ṣókí. Kí èyí dá lórí ẹsẹ Bíbélì tó wà nínú ìpínrọ̀ kan nínú
ìwé kan tá a fi ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́.
jw2019
Aún hoy existen fanáticos que responsabilizan a las mujeres de todos los males de
la humanidad y recurren a textos religiosos para explicar por qué creen que hay
que someterlas.
Kódà lóde òní, àwọn agbawèrèmẹ́sìn ṣì máa ń tọ́ka sí ọ̀rọ̀ inú ìwé ẹ̀sìn láti fi ṣe ẹ̀rí
pé ó bófin mu láti máa tẹ àwọn obìnrin lórí ba, torí wọ́n ní àwọn obìnrin ló fa àwọn
ìṣòro tó dé bá gbogbo aráyé.
jw2019
3) Lea los textos que aparecen en cursiva y, para ayudar a la persona a responder
con la Biblia a la pregunta en negrita, use otras preguntas bien pensadas.
(3) Ka àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a fi lẹ́tà wínníwínní kọ, kó o sì fi ọgbọ́n béèrè àwọn
ìbéèrè tó máa jẹ́ kí onílé rí bí Ìwé Mímọ́ ṣe dáhùn ìbéèrè tá a kọ nọ́ńbà sí náà.
jw2019
Aceptaban únicamente la autoridad del texto bíblico.
Wọ́n tẹ́wọ́ gba ẹsẹ ìwé Bibeli nìkan gẹ́gẹ́ bí ọlá àṣẹ wọn.
jw2019
Observe que la partícula condicional si aparece tres veces en el texto supracitado.
Kíyè sí ọ̀rọ̀ náà “bí” tó fara hàn nígbà mẹ́ta nínú ẹsẹ tó ń múni ronú jinlẹ̀ yìí.
jw2019
Antes de que los niños salgan para la escuela, dígales algo animador, analice con
ellos el texto del día o hagan juntos una oración.
Lójúmọ́ kọ̀ọ̀kan, kó tó di pé àwọn ọmọ máa lọ síléèwé, ẹ jọ jíròrò ẹsẹ Ìwé Mímọ́ , ẹ
sọ̀rọ̀ ìṣírí fún wọn tàbí kẹ́ ẹ gbàdúrà pa pọ̀.
jw2019
Por ejemplo, en su carta a los Hebreos citó un texto tras otro para probar que la
Ley era una sombra de las cosas buenas por venir (Hebreos 10:1-18).
Bí àpẹẹrẹ, nígbà tó ń kọ lẹ́tà sáwọn Hébérù, ó fa ọ̀pọ̀ ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yọ láti fi hàn
dájú pé Òfin Mósè jẹ́ òjìji àwọn ohun rere tó ń bọ̀.—Hébérù 10:1-18.
jw2019
Se cree que el texto de Mateo no se tradujo del latín ni del griego en el tiempo de
Shem-Tob, sino que es mucho más antiguo y que se redactó originalmente en
hebreo.
Ẹ̀rí wà pé, dípò kí ó jẹ́ pé a túmọ̀ rẹ̀ láti inú èdè Látínì tàbí Gíríìkì ní àkókò Shem-
Tob, ẹsẹ ìwé mímọ́ ti Mátíù yìí ti pẹ́, a sì ṣàkójọ rẹ̀ ní ìpilẹ̀ṣẹ̀ ní èdè Hébérù.
jw2019
Sin embargo, en años posteriores otras Biblias alemanas sí presentaron el nombre
en el texto de Éxodo 6:3.
Ní awọn ọdun diẹ lẹhin naa, bi o tiwu ki o ri, orukọ naa farahan ninu awọn Bibeli
miiran lede Germany ninu Exodus 6:3.
jw2019
b) ¿Qué debe tenerse presente en cuanto a los textos precedidos de la palabra
léase?
(b) Kí ló yẹ ká máa fi sọ́kàn nípa àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a kọ “ka” sí?
jw2019
Los buenos modales igualmente incluyen no conversar, enviar mensajes de texto,
comer o deambular por los pasillos mientras está en marcha el programa.
A tún ń hu ìwà tó bójú mu tí a kì í bá sọ̀rọ̀, fi ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ lórí fóònù, jẹun tàbí ká máa
rìn kiri láìnídìí nígbà tí ìpàdé bá ń lọ lọ́wọ́.
jw2019
Ni siquiera un texto bíblico dice que el Hijo sea igual al Padre en esos aspectos... y
si hubiera tal texto, no establecería una Trinidad, sino —a lo más— una “dualidad”.
Kò tilẹ sí iwe mimọ kanṣoṣo ti ó sọ pe Ọmọkunrin báradọ́gba pẹlu Baba ni awọn
ọna wọnyẹn—bi iru iwe mimọ kan bẹẹ bá sì wà, patapata yoo fidii “mejilọkan” mulẹ
kii ṣe Mẹtalọkan.
jw2019
La versión de Augustin Crampon, publicada originalmente en siete volúmenes
(1894-1904) y luego en uno solo (1904), fue la primera versión católica en francés
con base en los textos originales.
Ìtumọ̀ tí Augustin Crampon ṣe, tí a kọ́kọ́ tẹ̀ jáde ní ìdìpọ̀ méje (1894 sí 1904) àti
lẹ́yìn náà ní ìdìpọ̀ kan (1904), ni ìtumọ̀ àkọ́kọ́ ti Kátólíìkì ní èdè Faransé láti inú èdè tí
wọ́n fi kọ ọ́ ní ìpilẹ̀ṣẹ̀.
jw2019
En su afán por encontrar el verdadero significado de aquellos textos, comenzó a
estudiar minuciosamente la Biblia oficial de la Iglesia Católica, la Vulgata latina.
Torí náà, kó báa lè mọ ìtúmọ̀ àwọn ìwé tí wọ́n ti kọ tipẹ́tipẹ́, ó bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàyẹ̀wò
fínnífínní nínú Bíbélì Latin Vulgate tí Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì ń lò.
jw2019
A un nuevo o a un joven puede que le cueste mucho leer un texto bíblico u ofrecer
un comentario citando textualmente del párrafo, lo que muestra que emplea sus
facultades de manera encomiable.
Fun ẹni titun tabi ọ̀dọ́ kan lati yọnda lati ka ẹsẹ iwe mimọ tabi sọ ọ̀rọ̀ ilohunsi kan
ni awọn ọ̀rọ̀ ti o wà ninu ipinrọ lè gba isapa ńláǹlà, ti ń ṣagbeyọ lilo agbara rẹ̀ lọna
rere ti o sì yẹ fun igboriyin.
jw2019
1: El texto hebreo de las Santas Escrituras (quinta parte) (si-S págs.
1: Béèyàn Ṣe Lè ní Ojúlówó Ìfẹ́ (w03-YR 7/1 ojú ìwé 4 sí 7)
jw2019
Basándome en los consejos que ofrece uno de los libros de texto, Guía para la
Escuela del Ministerio Teocrático, hice todo lo posible por mejorar cualidades tales
como la afluencia, la pronunciación, el énfasis que comunica sentido y la
modulación.
Ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìdámọ̀ràn tí a fúnni nínú ọ̀kan lára àwọn ìwé ilé ẹ̀kọ́ náà, Iwe-
Amọna Ile Ẹkọ Iṣẹ Ojiṣẹ Ijọba Ọlọrun, mo ṣiṣẹ́ lórí irú àwọn ànímọ́ ọ̀rọ̀ sísọ bíi yíyọ̀
mọ́ni lẹ́nu ọ̀rọ̀, pípe ọ̀rọ̀, ìtẹnumọ́ òye ọ̀rọ̀, àti yíyí ohùn padà nínú ọ̀rọ̀ sísọ.
jw2019
Tras la lectura de una sección de un texto, pregúntese: “¿Cuál es el punto principal
de lo que acabo de leer?”.
Tó o bá ti ka díẹ̀ nínú ìwé náà, kí o bi ara rẹ léèrè pé, ‘Kí ni kókó pàtàkì inú ohun tí
mo kà tán yìí?’
jw2019
Utilizó textos bíblicos con bondad y claridad para demostrar la falsedad de las
enseñanzas eclesiásticas de que el alma humana es inmortal y de que Dios
atormenta a las almas humanas eternamente en el fuego del infierno.
Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, àmọ́ lọ́nà tó ṣe kedere ni Bàbá fi lo àwọn ẹsẹ Bíbélì láti já irọ́ àwọn ẹ̀kọ́
ṣọ́ọ̀ṣì pé ọkàn ènìyàn kì í kú àti pé Ọlọ́run yóò máa dá ọkàn àwọn ènìyàn lóró títí
láé nínú iná ọ̀run àpáàdì.
jw2019
Sin embargo, pudiera solicitar al auditorio que, durante la lectura, trate de
determinar qué consejos brinda el texto para afrontar la situación.
Àmọ́, o lè sọ fún àwùjọ pé nígbà tó o bá ń ka ẹsẹ náà, kí wọ́ n kíyè sí ìtọ́sọ́nà tó fún
wa nípa bí a ṣe lè yanjú ọ̀rọ̀ náà.
jw2019
Como se ha señalado, en el texto de su obra Studies in the Scriptures (Estudios de
las Escrituras), seis volúmenes que contienen unas tres mil páginas, no hizo ni una
sola mención a sí mismo.
Gẹ́gẹ́ bí a ti kíyèsí i dáradára, nínú kókó-ọ̀rọ̀-ìwé Studies in the Scriptures tí ó kọ,
ìdìpọ̀ ìwé mẹ́fà tí ó ní ojú-ewé bíi 3,000, kò tilẹ̀ tọ́ka sí araarẹ̀ lẹ́ẹ̀kanṣoṣo péré.
jw2019
Al igual que Aileen, yo también he escogido textos bíblicos que significan algo muy
especial para mí.
Gẹ́gẹ́ bíi ti Aileen, èmi náà ní àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó ní ìtumọ̀ pàtàkì sí mi.
jw2019
□ ¿Qué textos, entre otros, confirman nuestra esperanza de la resurrección
terrenal?
□ Àwọn ẹsẹ ìwé mímọ́ wo ni wọ́n ràn wá lọ́wọ́ láti fi ìdí ìrètí wa nínú àjíǹde ti ilẹ̀-ayé
múlẹ̀?
jw2019

También podría gustarte