oshanla ti awon eleyenlee bowa ti wonnpe igba opolopo ahemi Adifafun Orunmila ti ogabada lowo orisati ofi ghaalale owo awo eleye ifa dakunwa gba eneia omore kal lowo gbogbo ajogun
Encantamiento de oshe-tura
Akakanika akakanika alakakanika alapasapa
ijakalu Eye kan fo feerete o wole akakanika li aa pe ifa alakakanika li aape odu alapasapa ijakaluli aape esu odara eye kan feerete o wole li aape aje omo Olokun sande oba olubu omi ogo owoni esu odara iwo liote ilu yi do iwo nikiijeki obi kiopa alawo ilu iwo nikiijeki ebi kiopa unisegun ilu iwo nikiijwkiwbi kiopa adahuense ilu emi alawo ilu yi ree Emi unisegun ilu yi ree Emi adahunse ilu yi ree Esu odara majek ebi pa mi ati beebee ewe ita naa: ewe abamoda kan ebu cerupe agbede aro, efun ati osun ao te odu osetura lori erupe agbede tiabuwale, ao sa igede tiwa luke y I bi a ti pee sibiyi sori erupe ebu inaa kiadadd pomo efun li owo otun lati fi te odu ose Kiadaapomo osun li owo osi pelu erupe naa lati kote odu otura si ara ewe abamoda naa kiopa obi alawe merin tiodara fun ifa yi owo dudu ati funfun niki a papo ku soor soke ninu ile eyo ataare meje ati awe. Obi kan niki a maaje fin fun un nibiti a sooro sí ao maa fisa igede naa biatipee nibiyi lojo ojumo