Está en la página 1de 2

Olorun a de da, a se da Olodumare oba nila ti nfi oba je Oda da, to da gbogbo aye, ologo didan Oba a taye

ro bi agogo O gbi gba ti ngba alai lara Oka soso adaba ti nmi igbo kiji kiji Omi mon to mo iye awa eda to da Egbo lehin eni ada loro a ko ma ti ika Oba nla ti nfi ola wo ni bi aso Otiti nla ato fi ara ti bi oke Ounje nla ato fi bori ebi Baba mi, oro nla ojo nla tobori Ogbele Oba nti je emi ni lojo gbogbo Eru Jeje ti nbe leti okun pupa Oju kan nti wo igba aye Olorun ajulo, atobiju iba re Ogbamu gbamu oju re ko se gbamu Aye ka o won ko ri e ka Aye wa o titi wo ko ri o Won ba e nibi toju gbogbo aye lo Eni ti o se ohun ti o tobi, ti a ko le Ohun iyanu laini iye Oba aiku airi Orisun ogbon Olubukun julo Ologo julo iba re Olorun ti ki rin irin ajo oba ti ko si Okan naa loni, okan naa lana, oba titi Alfa Omiga, Ibere Ogbon, Opin Imo

lehin

se awari

ipo pada ayeraye

Traduao: Olorun a de da, a se da God the creator and maker of life Olodumare oba nila ti nfi oba je Almighty Kings who is a kingmaker Oda da, to da gbogbo aye, ologo didan The creator who created all things, The glorious one. Oba a taye ro bi agogo Not sure of this one. O gbi gba ti ngba alai lara The one who accepts the the forsaken? Oka soso adaba ti nmi igbo kiji kiji Haven't the foggiest.! Something about shaking the forest. Omi mon to mo iye awa eda to da The All-Knowing who knows how many humans he created Egbo lehin eni ada loro a ko ma ti ika lehin Haven't the foggiest. Oba nla ti nfi ola wo ni bi aso The great king who adorns us with honor like clothing Otiti nla ato fi ara ti bi oke Ounje nla ato fi bori ebi Baba mi, oro nla ojo nla tobori Ogbele Don't know those ones. Oba nti je emi ni lojo gbogbo The king who is always known as the I AM. Eru Jeje ti nbe leti okun pupa This one is something about the red sea? Ok I'll stop there for now. I am bored now....

Segunda parte: Kabiyesi o alade wura Oba adeda Aseda Ameda, Aweda Oba tinje emi ni emi ni Oba tinje emi ni mase beru Oba mimo, tin wo mimo Ti'nso mimo, tinje mimo O ranmo nise faya ti Olowo gbogboro tin gbo'mo re lofin Eleti gbaroye Awiiro alaafia Arugbo Ojo Adagba matepa ojo Adagba ma paro oye Oba nla tinf'oba je Oba ti kii ku Ato fara ti bi oke Oba to to to bi aro Eledumare, Eledumare Kabio masi Terceira Parte: Oyigiyigi,oba ogo -Oba Aterere kari aye -Atobiju oba iyanu -Ologo mimo julo. -Oba aseyi owu -Oba awimayehun,asoro ma tase -Ogbagba ti n'gba alailara -Oba ti n'gbe inu wundia sola -Oba ti n'gbe inu adelebo sewa -Oba to lohun gbogbo,to si le sohun gbogbo -Oro gbe'nu omo eniyan fohun -Oba to n'gbe orun s'ogo WOOW!!Is God blushing,or what?!All these "orikis" in this thread,just for him/he r! __________________ DS ON YOUTUBE. The Ultimate We Are Part And Parcel Of Everything We Are The Cosmos We Are Life We Are Love We Are All That Is We Are The Creator Of The Dance,As Well As The Dancer

También podría gustarte