Documentos de Académico
Documentos de Profesional
Documentos de Cultura
Qdoc - Tips Oju Osupa Apa Keji The Moonx27s Face 2
Qdoc - Tips Oju Osupa Apa Keji The Moonx27s Face 2
OJD °SUPA
APA KEJl
lati QWQ
OLADIPO YEMITAN
ati
OLAJIDE OGUNDELE
IBADAN
OXFORD UNIVERSITY PRESS
Oxford University Press
OXfORD LONDON GLASGOW NEW YORK
TORONTO MELBOURNE WELLINGTON CAPE TOWN
DELHI BOMBAY CALCUlTA MADRAS KARACHI LAHORE DACCA
KUALA LUMPUR SJNGAPORE JAKARTA HONG KONG TOKYO
NAIROBl DAR ES SALAAM LUSAKA ADDIS ABABA
lDADAN ZARlA ACCRA BEIRUT
ISBN 0 19 575219 8
1. K. OYE
OjuEwe
Irdmi vii
Oro Akps(> viii
ITAN
v
tRANTt
A se iwe yI ni iranti
AKfNPSU} OLOWOJOLU
A-R'6GUN-10-BEL~U
vii
ORO AKOSO
Gege bi ti Apa Kinni iwc yl, eleyi na
tun j~ itesiwaju ninu ilAkaka wa lati sa
awon itan inu odu Ifa jo.
A ko ~i tenume Q wipe .bi O$Upa ti mQl~ yl
gbogbo aiye ka b~ g~g~ni Ifa riran kedere ri
gbogbo ohun ti 0 $apamQ fun ~ ni aiye yI.
AWQn Yoruba a maa SQ pe, 'Ira ti fa
gbogbo nkan tan'. Bi ~ ni, bi ~ ko,
enyin papa yio tube ri oye r~ ninu Apa
Keji yI.
Oladipo Yemitan
Eko, Naijiria
1st July, '1969.
viii
1 Oni 1'6 ni ibu
Awo 0 so l'oko,
Bf ni bOra 0 fa I'dj«:
Gun /'d di/df'(Jni gbvnkall-gbvnkan
Ti i s'oko fun wpn n'/gM lragbeji.
Qni gbvnkan-gb9nkan,
lw{) 1'0 ni ibU,
lw{) I'~ ni /gM lragbeji.
Baba tani fiR gb' odo /pwp Oni-
On; gb9nkan-gb9nkan.
Gbogbo awon eja inu omi=Isin, arQ, okodo, akura, ojiji-
gbogbo won patapata ni nwon k6 ara won Jc. ti nwon ndit~
si Qni.
NWQn ni bawo ni enikan ti se le wa ti yi6 maa pase inu
ibu, ti yi6 tun maa SQpe oun l'oun ni igb6 Inigbeji! NWQn ni
eyi ko le bosi i rara, ki awon gba Qkan pada ninu r~ tabi ki
awon kuku gba a~ ibi mejeeji IQwQQni.
Ot~ yl kii se kekere, 6 si PQ t6b~ tiQn1 fi dide, t'6 to awon
alawo r~ IQ. AWQn alawo r~ na t'6 tQ IQ ni a npe ni 'Awo-o-
so-1'6ko' ati 'Bara-6-fa-I'aja'. AWQn alawo Qni SQfun un pe
yi6 segun Qta, ebo ni k'6 ru.
Ni kukuru, Qni rubQ gege bi nwon ti SQpe k'6 se. Ara awon
nkan ti nwon ka fun un pe k'6 fi rubo ni lkoko agbo nla
k~r~~t~ kan. NWQn ni ki 6 IQ gbe lkoko nla na ju sinu ibu
nla; eyi ni yi6 duro fun un gege bi apejuwe ti nwon ba bi i
lare bi 6 ti se ni ibu, Oni se b~ gege,
<)t~ yi t6 pari sugbon ko pari. Igbati 6 si ti j~ pe QrQ ti a ha
pari ta~ ile tl, di ile oba; ni nwon ha k6 ~jQ yf IQ QdQ oba.
Oba ni ki olukuluku won wa ro ti enu r~.
On1 ni 6 kQkQ rojQ. () se alaye bi 6 ti sejepe oun l'ounni ibu
omi, nitoripe nwon yi6 ba lkoko ar6 nla iya oun nibe, 0 ni
~ri t'6 daju ti oun ni niyen, ati wipe ohun ti oun si le fi ~pe-
juwe bi orQ oun ko ti j~ irQ.t6 niyen,
1
2 OJU OSUPA
Alaye Orq
(llan yl je eyi ti a y(> lati inu Ogbe Egiln)
Thinrawo
Maye Orq
(..4 npe odu tlltcin yl yp ninu re nl lrete ..4ddn)
Ewht-c}rc}; lpaoJe buruku
AAGBA-ori~i itakun kan ti a nlo gC;g~bi okun
N~Rl ARAMQ-tc;ramQ; wonkoko mQ
OKUNELETE-bi a ti ripe apa ibikan nl okun Atlaotlkl ni Ek6.
6 j~ apejuwe ebute kan nibe
~HANNA-janduku;jA~dijAgan
GB.bQol-gM lati se enia l'e~e; gM lati se QmQ enia ni lU. AWQn
Yoruba mi a maa pe QtQ yi ni 'gbAbc}de'
K1 OruL~ OA-ki ojU QjQmQ: ki i1~mQ
OAwQN-iN~ki enia fi enu ~e 'won-In' lati fi lblnu tabi Aika-enia&si
han, AWQn Yoruba a maa SQpe, 'wQn-in'l'ebU agM'
FeeReFe-3.f~mQjumQ; nkan agogo merln si mefa oWlirQ
AOUNRUNMQ-siSQpe enia ~ nkan ti ko~; titi c}rAnmQ enia lQrUn;
plpuro mQ enia pe 6 se nkan tf ko se
KANTAN-KANTAN-laimuQghQDdaDt; c}rQpalapala
KANMa6-bi imu ti se ri; apejuwe bl imu ti ri
HUwA GBQoQ-GBQoQ-huwA ~l~p~l~
K6BO-KOBo-kantan-kAntan; lSQkusQ; c}rc}jatijati
JUBAEHoRo-sare bi ehoro, nitori ehoro 1'6 ni ere-slsa IQwQ; mu
ere sa
AJfGBEoA4ni ti ngbC ida oba danl; oruko oye kan t[ oba maa
nfi enia je
TtrU4ni ti m~ on enia tl oba ha nl ki nwon pa
Danrawo
Alaye Qrq
(ltan yl wa lati inu odu Ejl-Ogbe)
12 OJU~UPA
Danrawo
I. Tani iya t'o bl Oylnbo ?
2. Tani itan yi so pe 0 kqk{l bi Oyinb6 l'aiye yi?
3. Ahiro Jasan 1'6 IQ tUfQ Ol6kun fun QmQ r~.
Kini oruko ohiware ?
4. 'Emi a de'~ ma beel'e wo,
Emi a de'~ ma beere wo,
lku t'o p'Ol6kun
Emi a de'b~ ma beerc wo'.
Kini da orin yi sile 1
5. Tumo gb616hUn QrQ wonyi:
(a) Ore) agba, bl ko ta egun yio ta lk6k6ro.
(b) Ki nwon j~ ki enia pitu inu r~.
A -gbpn-bi-ako,
A -gp-bE-ako
Ako gbvn, gbpn, gbpll,
B~ ni 0 !Vdgun s'ile;
Ako gp, gV, gp,
B~ ni 0 gbe s'egbe.
K' 6nELe6 hilwa gbpdpgbpdp
K' 6 se pelePflf,
K'djVji 6 md baa fi ile e ~e'tefun un:
L'6 dlfd f'Aresa Ajeje,
Eyf t'6 ti I'hbd wpn 11dja il~ ri.
Arrsa Ajeje,
Md tun bd wpn nd'ja ile mp,
T'oju PP9n ni 0 mda bd wpn nd kuuruku.
Okunrin kan wit ti oruko r~ nj~ Ar~sa Ajeje. Onile, QIQna, ni
Ar~sit Ajeje. Oja il~ ni 6 nna.
Nigbati 6 se, oju beresi i pon Ar~sa Ajeje. Oju owo PQn (;>0
t6b~ ti 6 fi f~r~ le ri imi adie n'ile ki 6 pe e 1'6w6. Ko si i~~ti
ko danwo tan; bi 6 ti nroko ni 6 tun nsona: 6 dan agbon-
hihun wo pelu sugbon 6 dabi eni pe aWQko ka oju ilu. Nigbati
6 tile ya, 6 dan eja-plpa wo sugbon kaki ki 6 re;, lara ewe
agoon, lile ni 6 tun rile koko si i.
Nikehln, Ar~sa Ajeje to awon alawo ~ IQ, nigbati ko mo
eyi ti it tun I se, 6 wadl pe kini orn le se ki oun t6 le la. NWQD
fUD un ni imoran pe ki 6 ma ba won na'ja il~ mo, t'6ju QPQn
ni ki 6 maa na kuru-kuru. NWQn ni igbana ni yi6 1'6w6, ti yi6
ko ile mo'Ie.
Ki a ma da eena p'enu, bi Ar~sa Ajeje ti se te ifa niyi; 6 te
ifa tan, 6 di eni ti nso apo kQ kifa kakiri, Bi eni pe kini Ar~sa
Ajej6 t~fa yI tan si ni, nse ni 6 nri se w~r~-w~r~; 6 f~r~
ma si alawo t'6 rise bi tir~ mQ. Gbogbo awon 1'6 ha lenu r~ ni
6 ti gbe ju sehin. OWQr~ beresi i ji, b~ni ow6 rirogun si i IQwQ
t6b~ ti 6 fi Je pe bl 6 ti nkQle ni 6 nkan aas~. Bi nwon ni nkan
13
14· OJU O$UPA
Alaye Qrq
(Lati inu odu Ejl-Ogbe ni itan yl papa ti wa)
AKo-c)wa <',>P<rogl.irc)
GUN S'JLE-tQ tabi p~ l'ara He ti a ha fi kQ
EGBE-egbe dabi ikan ti a fi nra ile, <r0U ikan ko ran egbe b'o ti ran
ako. Egbe tQ l'ara ile ju ako IQ nitoripe enu ikan k6 ran an
mNA QJAOJ0 QPQN-ki enia maa ter Ifa, ki 0 si j<r babalawo; kf
enia maa gbe apo Ifa kO se i$~ a'NO kakiri
OJA ILt-i~oko-riro tabi agbe-stse
KUURUKU-didun oju QPQn Ifa ni eleyi n~pejuwe
A-GB<)N-Bi-AKo--~ni gbon g~g~ bii aka. ('Aka' ni Qwa
QP~ 6gurQ.)
A-GQ-Bt-AK~ni gQ g~g~ bii aka.
Danrawo
Alaye QrQ
(Okdn Osa-a ni a npe odU If itdn yl ti inu re jade)
Danr8wo
ASjNwfN-8$iwere.
AKQStBAJ{lDUNRuN-mimQ i rln se kong~ Qja tl nwon nta ti a
si nj~ ere ~dunriln 16jukanna
{lDUNRUN-kQbQ kan perc
Tf '0 R'66KAN AM(1NA-ti ko ri ow6 ~YQkansoso ti 6 ti1~le mu fi ra
nkan
AGBtD~ BAMU-BAMU-ag~d~ t'6 nCQ QkQ ati ad!, yatQ si ag~d~
gOIi1 .
~GBfrA-kQbQ meji
~GB~RuN-tQrQ
AFORf,AFQRUN-dandangbQ'n
Danrawo
Ah\ye Qrq
(ltan ati inuodu lr~t~ Okdnran ni Itan yT)
ADEGBOSAGI-dide igb6 sa tabi Iu igi lati mo hi 6 ti lagbara t6
ATc)NASAY~rt-dide oju Qna gba erUN io Iati te odu if a sinu r~
E1.ENMQ~ni ti 6 le, tl ko se f'QwQ pa idll r~ 16ju
onr ~UPA 27
01 GAGA,Dl oooo=di gbogbo eru dani, ki gbogbo r~ ri gangan-
gUngUn
ALAB~-enia-kenia
KAN'oo--de ado
Danrawo
Maye Orq
(item yl wa lati inu odu Ogbe JY9nu)
QPAT'A A GBE LE'KA-Qpa ti a gbe le ejika
OKO AiLEREQDUN~ko ti ko nmu ere wa l'am{>dun
IGBE ARAMu-igbe iranu; igbe ti ko ni ltumo .
J;FON-eepo ehln <)wa <)~, ti a la si w~w~ lati fi hun agbon
QWA TABl QHA-{ka igi Q~
ARiRAN~ni ti 6 ni ~bun lati me ohun ti yio ~I~; onlwose
ARlRA-~ang6
~GBURU-iho t'6 wa ninu aja ile
ADODo-aka tabi ahere ti agb~ tlk6re re Jo si ninu lati fi pamo
Danrawo
1. I~ kini Obagede kQkQ D~e ni igbesi-aiye r~ 7
2. AWQn irll kini a le so mQ eekan?
3. Bawo ni Obagede se rl inigbln gbln 7
4. Ona wo ni QWQ Obagede fi te eiye ti ko j~ ki 6 pokunso?
S. Obagede 1'6 da a~ eiye-sinsln sil~. SQ bi 6 ti se da a sil~.
6. Nj~ otito ni alubata ki I darin 7.
7. Se alAye gb616hiln wonyi:
(a) Id enia ri ow6 ~e
(b) Id ~ se
(d) igbe aramu
(e) Id enia tepele mQ i~.
8. tkQ wo ni itan yikQ enia 7
9 Lasigbo <)g~g~
Agbonmi ni i wole eja,
Apajuba nf f wo/e aparo;
OIUgb6ngbo bUlitku l'a fi i $~gulI Ogll!Ui!tU:
L 0 difd fun Ldsigbo Og~g~
TI nw,m m9 ile r~tdn l'diye
T'o tun npil~ t'ode-orun.
A ni ki f wole vrun nu
Ki ~ tun t'aiye m{J,
Envin agbOgirija.
Lasigb« <)g~g~ la, 6 lu lQPQlQPQ;bi 6 ti .nkQle, b~ 1'6 nkan
aas~. Ohun lni r~ ko se i kil. Esin PQ ni eekiln. Qla ati Qla. r~
PQ ti 6 fi j~ pe oun ni awon ara Uu fi j~ olori onisowo ilu.
Iyi r~ ni ipo oye yI PQ to~ ~i enikeni ki i da ase r~ koja, k6da
titi fi kan oba Ilu, Ohunkohun tl 6 M ti SQtabi ti 6 ba pa lase
ni abe ge. IIu ti Laslgbo ngbe yI, t'6 si joye ninu r~, a maa
j~ Oke tg~ti. .
Laslgbo <)g~g~ ko fi iWODle ara r~ sugbon 0 beresi i Ie aiye
aj~~usara. Ibi ti 0 ti b~r~ ni ki 6 maa fi iya j~ aWQDara Uu r~,
lalsepe oun ni oba. ~e bi aiye ha nyeni iwa ibaje l'a i hu, oun
A.I~ fu_n...a._rakunrinijQsi ti ody-iho agilinti YQ!..Qrun-ala1ceji!
v\ tu inu Lasigbo p'egbeje; irQ QWQ r~ p'~gb~fa. Bi nwon
gunyan fun won l'ode ilu tg~ti, Laslgbo <)g~g~a gba a, a fi je!
Bi nwon roka fun won l'ode ilu Ig~ti, Laslgbo Og~g~ a gba a,
a fi j~ bakanna l Bi nwon gbevawo fun enia l'ode ilu tg~ti,
Laslgbo ni yio gba a fi s'aya. 11e kiko, agaga-hi ile ohun ba
ti dara ju ti Laslgbo IQ die, nse ni jagunlabi yio gba aIQWQ
won fi se tir~. Eni t'6 si to i bi i lere, nwon ko ti ibi oluware l
~ na ti ri o'u ~kun i ti 0 6 SQ e ran ry b sonu!
Ni QjQ kan ~a, Laslgbo Og~g~ sun, 0 la ilIa. Inu ala t1 6-Ia--
yI ni 6 ti ranti pe iku mbe. Nigbati 6 ji, 0 pinnu pe bi ikU ha
tile IDb~, ohm} ti a i se ku: oun yi6 wa Qna kQ ile ti oun yi6
maa gbe bi oun ba de Qh1ln.
32
OJU O~UPA 33
Ko ju QjQ melokan IQ l~hjD ti 6 pinnu bayi tan ni 6 SQ pe
ki nWQDba oun pile ile ti orun nibi ti oun yi6 maa gbe bi
oun ha kujan. () so ni okan ara r~ pe, bi oun ti 1'6w6 t6
l'aiye yI, kc y~ ki oun ku tan Id oun tun maa gbe ile jati-jilti
l'Qrun; eewQ niyen, UsigbO Og~g~ ti gbagbe pe orl ko mQl
ib?su~ ~tar' ko mo ~b~~be~ ori iba IDQibu~u~ a tU~b~ ~. ,.,/
NI ukuru, nwon kQ ile yi fun un g<:g~bi aafin oba, Koda,
galu ni nwon fi kQ Q pelu,
Nigbati awon ara llu r~ ri eyi, nwon beresi i kehln si i.
NWQn rikim sinu pe enikan ie. 6 y6 tan, 6 fi gbogbo ile aiye
yl kQle, slbe ko t6 0, 6 tun wa ripile t'ode orun; nibi ti baba
elomiran ko ti i ri aka kQ! Nje eleyi kb ni i SQ gbogbo awon
di Itru ara r~ tan bayi.
Pelu iberu yl l'Qkim ni awon ara llu ha to alawo IQ lati mo
ohun ti awon le se lati f~ LasigboOgege ku n'ilu ..Bi babalawo
a
ti gbe if Iule, 6 ki odu 1'6 YQbayi:
Agbonmi ni i waie eja, apajuba ni i wale aparo; o[ugb6fz·
gb6 bUluku l' afi f $tgun ogUluntu: l' 6 difd fun Ldsigbo 9g~gf,
ti nw(m mo ile r~ tan /' aiye, tl nwpn tun npile t' ode 9run.
Njt! k' ~ f wale prun nu, k' ~ f tun i' aiye mp, enyin agbo girija.
Babalawo ki odu yl tan, 6 SQ fun won pe C(bQni ki nwon
6 ru ki nwon ba le ri isegun. () ni, 'Tani oluware t'6 kole
t'aiye tan, t'6 tun ripile t'orun?' NWQn dahun pe, 'Laslgbo
Og~g~ ma ni o!' Babalawo ni 'Paga, kini e wa ti nwo lati QjQ
yi wa? Ebo ni ki C(yara ru'.
AWQn ara ilu Oke.lg~ti gba, nwon rubo gege bi babalawo
ti SQfun won. Babalawo se kinni yI fun won tan, nwon beresi
i 106 g<:gC(bi 6ti se SQpe ki nwon maa sa a.
a
Nigbati yio fi t6 QjQmeta ti nwon ti nsa bi ologun ti juwe
fun won, ariwo ta lala ni ar~mQjumQ ojo kan. Nje kini de?
Nwon ni Laslgbo ma ni. Kini se e1 NWQn ni oun ni nwon
ko ri! Nje, 6 ku ni tabi 6 sonu ni 1 Ere ni, awftdft ni, bi nwon
ti se f~ Laslgbo <)g~g~ ku niyi!
NWQn ko mo wipe awon eran osln re, ti it npe ni agbo
girlja ni nwon le e WQ igb6 nla klji-kiji IQ, ti nwon si IQ kan
an pa mo ibe. O sun, 6 ji; ki 6 bo si ehinkule lati to ni 6 wi,
QWQ awon agbo glrija ni 6 bO si; nwon beresi I kan an. 6
kigbe pe oun ni, oun ni, ki nwon ma kan oun pa; sugbon
34
awon eran Qsin r~ wonyi ko gbo, 6 gbiyanju lati sa WQ inu
ile IQ sugbon nwon ko fun un l'aye: ni 6 ba fi ori le ona inu
igbo, ti 6 nsalo, AWQneran gba, nwon fi ya a-nwQn ko kuku
gbo 'kai' mo ! NWQn le e de inu igbo kiji-kiji kan ki QWQwon
t6 i ha a, ibe ni nwon si kan an pa si!
AWQn ebi Laslgbo Og~g~ beresi i wa a kiri. NWQn wa a de
oko, nwon wa a de odo, nwon ko ri eni t'6 ic Q. NWQn fe ki
awon tile ri oku tabi aaye r~ gbe IQ sin sinu ile r~ orun ti 6 ti
ko sile pe ibe ni oun yio sun ti oun ba ku, sugbon nwon ko
ri oku atiaaye re. Igun pelu akalamagbo I' 0 fi oku r~ je.
Ah\ye Qre)
Danrawo
Danrawo
Maye Qrq
(ltan y( YV ninu odU lwoTl OYfkU)
Danrawo
1. Iru lgba wo ill awon obinrin Ilublnrin maa ngbe agQ egungun wQ?
2. S<?iyato 1'0 wa larin ~ku egungun ti awon obinrin Ilubinrin
rigbewo l'aiye ijoun ati eyi ti egungun nWQ nisisiyi.
3. Ow6 wo ill 'owo awon baba wa lailai'?
4. Ogbon wo ni awon okunrin Ilubinrin da ti apa won fi kli awon
obinrin won Co ti nfi iya j~ won?
5. Lo awon gbolohun wonyi mo QrQ lati fihan pe 0 mo iturno won:
(a) di p~-~-n'-tiika
(b) nkan babara,
6. S9 ~kQ ti ltan yi kQ wa.
13 Eni ti koi ti i setan iku
Igbehtn aiye I> jump
L' <5 dlfd fun Eni-ti-koi-setdn-iku;
Eni-ti-kot-se-tdn-iku dlfd fun wQn ni lhib_inri/l
Nlbi aj~;i godogba ti npa.$~ai/ora:
L' ($ dlfa fun aj~jl gOdogbo
T' 0 nlQ ree bd w9n mu' l~ ibitdo
Nibi ibU oluwert.
'Ire ow<5ni n' ont, tani mo?
Tanf le mo 'gbfhin aiye mi!
Ire Qmr ni n' 0 bl, tanl ma?
Tani le mo 'gbehin aiye mi!
Ire aya ni 11' 0 If, tani mo?
Tan! le fI'Io 'gbehin aiye mi!
Ire He ni n' <5 ko, tan! mo?
Tan! le n1{> 'gbfhin aiye mi!'
. Okunrin kan wa ti ow6 r~ buyaarl teleri, 6 ni owo yl tob~ tl
eni ha SQpe tire bawo ni il6 won, oluware nsu imi ehin ni. lie
r~ PQ jQjQ; esin r~ ko n'iye l'ekan. Sugbon nigbati 6 ya, obiri
yi fun un, ko rise UUlra mo, Gbogbo He 1'6 ti kQ 1'6 ta: esin r~
ti ko l'6itka I'ekan tele, a 0 ri ikankan ninu won mo. h~r~ yl
PQ tob~ g~ 1'6 fi tun di atoroje Qsan gangan.
AWQn enia t1 nwon ti mQ Q teleri nigbati nkan ridan fun un,
ti nwon si tun ri i ninu Ipo t'o wc\ nisisiyi, ni nwon gba a nimo-
ran pe k'o se bi omokunrin ti i se b'6 ha buru tan. Sugbon,
'ako igi ki i se oje' ni okunrin yI j~ nitofi esl ti imaa fun won ni
pe oun koi ti i setan iku. Beni nwon k6k6 se fi ndapani pe
'eni ti koi ti i setan iku', ti oruko yJ si fi mQ Q lori.
Eni-ti-koi-setan-iku kQ lati pokunso nitori igba 1'0 yipada
yI, bi 0 tile jy pe nwon fi-enu tl i de oj6 k'6le pa ara r~ danu.
Kclka ~ nse ni 016ro n'iret! t'6 daju pe b'6un 0 ba ti i ku, oun
yio ~i tun da nkankan-ohun ti yio da nikan ni kc me. Pelu
ireti r~ yI l'Qkan, 6 beresi i sagbe kakiri lati abule kan s'ekeji,
SO
OJU~UPA 51
awon alaanu a si maa ta a l(>r<l-Qr<low6, onje, aso, ati orisirisi
nkan gege bi agbara olukuluku ba ti t6.
Nigbati 6 pe, iyan nla kan ~sil~ n'Ilii ti .Eni-ti-kol-setan-iku
ngbe gangan. Iyan yI PQ tobe g~ ti awon ara 11uf~r~ le ri irni
e
eran n'Ile ki nwon pe l'owo, Gbogbo nkan 1'6 won n'ilti:
ko s'owo, ko s'onje; ojo kQ ko fQ mo, isu p'eyin ko ta, agbado
taN ko gb6! K'a wi, k'a fQ, awon omode kekeke ilu beresi
i ~hlsan fun aid onje Je-
Se alaiye ko sa ni i ie ki aiye 6 baj~. Nigbati QrQ rl bayi,
awon agbaagba llu wa ~apejQ lati wewe lori ohun ti 6 sele yl.
Nigbehin, nwon to alawo IQ lad le ri ldi OtQ.
Oruko alawo ti nwon to IQ a maa j~ Igbehin-aiye-o-jumo.
Alawo gbe ifa kale, odu t' 0 YQ n'ijo na l(>hl1n ni odu Ogbe-
wehln. 6 ki i bayi:
Igbehin aiye 0 jum(J: /'6 difd f'eni tf koi.setan iku; eni ti
koi seton ika difa fun w(>nni llubinrin nibi ajoji godogbO
ti npa$f! aUara: 1'6 dfja fun ajoji godogbo t'6 nlo re ( bd
w{Jn mu'/f ibUd6 n'fbU oluweri.
Nie, ire ow6 ni ng 6 nl, tani mo? Tani le mQ 'gbehln aiye mi!
Ire QmQ ni ng 6 bI, tani mQ? Tani le mQ 'gbehin aiye mil
Ire aya ni ng 6 f~, tani mQ? Tani le mQ 'gbehin aiye mi!
Ire He ni ng 6 kQ, tani mQ? Tani le m.Q'gbehln aiye mi 1
Babalawo na SQfun won l'(>jQna IQhiln pe bi nwon ba m~
ki ilu won torO-id ow6 de, ki onj~ PQjaburata n'i!-u-ekute ile
ni nwon yio fi rubo, Enia 1'6 oj~ b~ l'aiye ojoun. Ko wa ku ibi
ti nwon yio ti rl odidi QmQ enia fi rubo! A gbo pe ayangbe aja
dun, sugbon Id a wa t6 yan an k'6 t6 i gbe nkQ! Tani j~ fi QmQ
tir~ sile ki nwon fi rubo fun ilu!
AWQn agba wa ronu wo, nwon dete kan: nWQr1ni ibO ni
awon yio di 16rl QrQ Da; ki olukuluku maa wa daruko QmQ
tir~, eni ti Ibo ba mu ni awon yio fi se lrubo na. Babalawo ti
kQ won pe bi nwon ba ti ri 'ekute-ile' na, ki nwon kan an
m(>'nu p6si l'oy~, Id nwon si gbe p6si yijus'6do, k'6do ghee IQ.
NitotQ, nwon beresi ibO i ill. NWQn beresi i daruko: QmQ
lagb~rci ni k'ciw n mu Iati fi rilhQ nd; aWQD ~CL~_ta_n6~
bi. ilu r ~u, ow6 de, onj<l WQilu? Nigbati ifa yio ba dahun a
wipe ko D~ OUD. OmQ raka~gbeni 1 6 ti, oun kQ. Tabi QmQ
52 eN! rt Koi rt i $ETAN IKU
tam~u ni? 11>0a tun kQ! Bi nwon ti se le gbogbo awon omode
kekeke Ilu tan niyi t'o j~ pe ko si eni ti ibo mu ninu won.
AWQn agbaagba llu tun beresi i le ara won wo I'QkQQkan;
nwon tun le iyawo won pelu, sugbon 11>0ko mu enikankan
ninu won.
Ni gbogbo igba yI wa, nwon ti gbagbe Eni-ti-kol-setan-iku
lati le wo. Nigbati 6 p~ ti nwon ti npete-pero lori QrQ yI ni
enikan ninu won s'enuforo, t'6 SQpe, '6 ~iku Eni-ti-kol-setan-iku
ki nwon le wo ; ~j~ ki a le e wo boya oun ni eni nil'. Binwon ti
ju lbo si i bayi, ponkan ni ibo gba a mu: ifa ni oun ni! Ko wa
i ku ibi ti nwon yio ti ri Eni-ti-kol-setan-iku; eni ti 6 j~ pe
kadara tire 1'6 mba yi kakiri, ti ko fi ibikan se ile; eni t'6 ie pe
k'a ri 'ni ni igbara loni, k'a si tun gburo eni ni igboro lola ni
o mM kakiri-t'o nse agbe lati abule kan s'ikeji!
Nigbati ko si ona miran fun won mQ lati gba, nwon beresi
i wa Bni-ti-kol-setan-iku kiri. NWQn wa a kiri titi; bi nwon ti
nkuro ni ileto kan ni nwon mbQ si ikeji sugbon nWQDko ri
eni ic Q. Igbati 6 p~, pe, pe, ti nwon ti wa lori hila-hilo yI ni
nwon IQ kan 016ro ni abu1e kekere kan nibi ti 6 ti nsagbe,
NWQn pe e WOboya oun ni tabi oun kQ, 'Eni-tl-kol-setan-iku!'
6 ta girl, 6 ni, 'Hen'. NWQn ni iWQti awon ti nwa kakiri lati
iye QjQ yI wa, t'awon 0 sun, t'awon 0 wo! 6 ni, 'Kini ~
nwa mi kakiri funj B 0 mQ pe ng 0 le se ki m' ma se i~ oojQ
mi ni T NWQn ni irohin aYQ nla kan ni awon wa mu fun un.
Eni-ti-kol-setan-iku da won lohun pe kini irohin aYQ na? Ki
nwon 50 Q fun oun k'6un gbo, NWQn ni oba ti waja lati QjQt'6
ti p~, nigbati awon si difa ni llu lati mo erii ti oba tQ si, oun ni
if a mu pe k'awon fi joba; nitorina ni awon se nwa a kiri.
Eni-ti-kol-setan-iku ni, 'e wi i, abi 6 be)! Iyen ni pe ng 0 b~
kuro IQwQi~~ t'6 n~ mi yl!' Inu r~ ti dun de'dl,
Ni kukuru, bi nwon ti se fi ogboogbon, ~r~~rQ, tan eni-ti-
kci-setan-iku j~ niyi, ti nwon mu u pada wa si ilu r~-laimQ
pe nwon ti kan p6si ti nwon yio gbe oun ju si sile.
Bi nwon ti nrmi u wQ'lu, nwon ko f'Qkan se meji, aa:fin oba
ni nwon mu u gba IQ. B'6 ti de aafin ni nwon ba di i raka~au,
ti OWQOgbe e jit sinu p6si nwon fi omori r~ kan an pa, oba si
pase pe ki nwon IQ gbe e ju sinu odo. NWQn dapara pe inu
p6si yen ni yio ti mQ bi oun setan iku tabi oun koi ti I setan.
om O$UPA 53
Odo gbe p6si IQ raurau!
Kini nwon se eyi tan si ni, ilu beresi i r6ju.llu ti ko ti s'6nj~
teleri, ODj~pc) ti nWQDf~r~ le maa fi QWOgba a n'i1~. Ow6 tun
ya wQ'Iu bi omi bakanna; DWQDtun beresi I kO il6 alara-
rltbara kakiri gbogbo Ilu.
:eni-ti-koi-~tan ikU ni tir~ kal setan iku nit~to; dipo kt6 kU,
nse 1'6 rinna ko ire IOna. Akoko ti nwon ghe e ju s'6mi t'oun
ti p6si yI gangan ni 6 pe bi o$il merin ti oba llu kan ti a iipe ni
llubinrin ti waja. AWQn ara Ihibinrin si nwa eni ti nwon yio
fi joba.
Babalawo t'6 dafa -oba fun won l'ojo na. lohun ti SQ fun
won peeni ti nwon yio fi joba, oju omi ni yio ti wa, inu edldl
ni yio si wa pelu; bi nwon ba kQkQ ri i, iliya won-yio ja, sugbon
kl nwon mase kominu, ki nwon 6 tu nkan na. ti a di l'edldi wo
nitori ire 1'6 mbe nibe.
Lati ijQ ti babalawo ti SQ bayi fun awon ara Ilublnrin ni
nwon ko ti ni igba i~ meji: bi nwon ba ti ji 1'6wurQ, nwon a
beresi I IQ maa $Q oju omi nigbati nwon ti SQfun won pe oju
omi ni oba titun ti yio j~ yio ti wa. NWQn $0 odo titi-ti, nwon 0
ri nkankan titi O$Ukinni fi koja; O$Ukeji le.bakannaj osuketa,
Mifo-ni nwon ba se ara wuy~, nwon ni iro ni alawo awon pa
tan awon je.
() ti ~, ~, p~; nwon tile ti gbagbeki 6 t6 di QjQ ti ado ghe
p6si YQsi Ilubinrin! Enikan lasan ni 6 IQ si eti ado lati ponrni;
titajukan t'6 tajUUn ni 6 ri nkan na. t'6 tiyi ridi-ridi be) 16ju
omi 10kankan. Were, 6 ti fi igbe ta pe kini mbo 16jU omi
lokankan yI? Oju oun nikan kO ni yio ri eleyi. Igbati nwon yio
sunmo kini na. 1'6 di p6si! Aiya WQDja pe tani ku ti nwon gbe
ju sinu p6si SQs'6mi! NWQn beresi I bi ara won lere sugbon ko
s'eni SQpe oun me) nipa r~.
Ni awon llgba ba SQ pe ki nwon IQ y~ ~ wo, ki nwon mo
ohun t'6 wa ninu r~ k'awon wo 6 na. NWQn yi p6si ju si bebe
odo; hi nwon ti $i i wo bayi ni nwon ba Eni-ti-kol-setan-iku
ninu r~! () fi QWQbQ oju bQorobQ bayi, 6 ni nibo ni oun YQ si
vl ~w~!
Eyi ti a ti tiwi yI ti ~, ni nwon ba ghe e dlgba-digba, 6 di ile.
Ori 1'6 YQ c$ ti kai ti i ku4rni kansoso 1'6 ku l'~nu re.
NWQn
gbe e de'le tan, nwon w~ fun un; nWQDfun un l'onie. nwon si
54 ~N1 rt Koi rt i ~ETAN IKU
Danrawo
Dlinrawo
1. Ini ~a wo ni h6ke) ati Araba j~ t~l~ld ltan to so pe nwon di igi'l
2. SQ ohun ti 6 me) nipa iwa Ir(lko ati ti Araba.
OJU O~UPA 61
3. Kini fa Ija larin Arab! ati Ir6ko?
4. Lehin ti awon ara lIu ti pari Ija yi ti, kini OWQO se?
5. Tani awon onija meji wonyi gba oro si l'enu?
6. SQ nipa Isesi awon ilu ni QjQti Arab! nfi ihi sile.
7. Kini mu lroko pinnu lati parada di igi ?
8. SQ bi awon QmQ araiye se yaneyi ti nwon yio maa fi kQle ni nu
igi Arab! ati lr6ko.
9. ltao yi fihan pe awon Yoruba ko gba pe enikan tun wa t'6
lagbara t6 Olorun, LQna wo 1,
10, Lo awon gb616hun wonyi me> QrQ:
(a) QrQ Qg~d~ ni QrQ yi
(b) 6 ti gbin nkan s'ikun
(d) f'enu pitobo.
11. Se;>~kQ ti MD yI kQ 'ni.
LjLlr~
15 A-ku-ma-ku-tan
, v ~_
,_rJ,?
. . I :58
ldt
at PI-. f , • f(
Era pl-i.
Oblnrin ku n'i/i oko,
6 gb'ile ale ree ji.
B'o 0 ko'ld, 0 ko'ld;
B'o 0 gbeni, 0 gbeni-
Ewo l'ab9r9 wo'ju ()19)a1'9ja Ejigbo!
A/wo 6-
Ojll oktil'b 1iwo nni.
Ni 19b8. anjo, awon ara aiye Id i gbfl~ sin okU. NWQn kol ti
1jagbQn oku-sisin nigbana; ohun ti nwon maa nse ni pe nwon
yio gbe oku ju sinu igb6 tabi ki nwon gbe e sinu iho igi kan ninu
igb6.
Ni Ak6ko ti a nwi yI, okunrin kan ati iyawo r~ wA ti iMgbepQ
won ko rogbo IQ titi. Nitori idi eyi, obinrin yI f~ ko QkQr~ sil~
ki 6 sl lo f~ elomiran, tdi ni oruko obinrin ti a nwi yI, Qrunmlla
si ni QkQ r~.
Ni kukuru, ldi ri QkQ miran t'6 f~ f~, oun pelu QkQ titun yl
si ti Jo se adehun fif~. Ko wa ku bi yio ti se ko QkQr~, QrunmllA,
sile! QrunmUA niyi, idA r~ ko se i fi QWQra 16ju; ko gba gb~r~
rara, ko si ie gba ki obinrin yI ko oun sn~ IQ f~ elomiran.
Qrunmila ko tile le ki Idi ya oun lesekan: b'6 rilo oko, oun
pelu r~ ni; bi Idi si nlo odo, Orunmlla yio gba tele e. 6 wa
dabi eni pe Qna fif~ okunrin miran ti pin fun idi.
Jgbagbogbo ni Idi pelu Orunmlla maa nja. Bi nwon ba si ti
nja ni Idi maa nSQpe, 'Ng 6 wul~ ku si Q lQrun'. Orunmlla ko
si fura si eyi, a maa da a 16bun pe k'6 kn; b'6 ku oun yio
gbe e ju s'ig~.
Nigbati QrQ na pin obinrin yl l'eml, 6 ba QkQ t'6 $~$~ nfe f~
yI di i pe oun yio dibon pe oun kU, ki QkQ ar~sQna yI maa
murasile lati wa mu oun I~hin ti nwon ba ti gbe oun ju sinu
igbo tan.
A kl i ku sire ni ~,gbo, sugbon bi ti Idi yI k6. 6 kQ okunrin
62
OIU O$UPA 63
M~om\ yI pe k'6 mura g~g~ bi ode, Id 6 si duro ninu igb6 bi
eni ng~gim ~Qeranko ni Qjo bayi-bayi, Bi 6 ba ~e~, yio le ri
ogangan ibi ti nwon ha gbe 'oku' oun ju si gan-an, Bi awon
t'6 gbe oun wa ba ti IQ tan, ti Qjo si bora tan, k'6 wa tu oun
Id oun le maa ba a IQ ile.
A-wi-~-~e-~ ni obinrin yI nitoto, Ni ijQ kan ni oun pelu
QkQ r~, OrunmiIa, jijo se gbolohim aSQ kan. OrQ ti ko to ibinu
ni Idi taku herihe le. t'6 binu gbe ara sanle, t'6 diju, t'6 s~
emi, t'6 se bi eni ku. NWQIl,ro pe 6 ku toto ni; Orunmila si ni
ki .nwon IQ gbe e sonu,
Ariwo gba ildugbo kan pe 'Idi ku'. NWQn beresi i se QfQ.
Eni nsunkun, ariwo 1'6 ripa, eni gbe'le 1'6 risin oku: ibi ti awon
kan ti rike ni awon kan ti ritun un se, ti nwon si gbe e IQ si ibi
ti nwon maa nSQ eni ha ku n'ihl ibe si.
Se aSQt~l~ nl ij~ QmQ mi gb'ena: QkQ tuntun wa ni ibi ti 6
gegun si ni gbogbo igba ti nwon gbe Idi yI wa. Okunrin yI Je
ki gbogbo nwon IQ tan Id 6 t6 rora sQkal~ wa ha Idi. Were, 6
e
ti tu aso ti nwon fi di.i kuro. 6 pe lem~ta, 'id!, Idi, ter. Iyen
dahun, 6 ni, 'Hen-en!' Didide ti 6 dide, ko tun $OPO 'DU u
gba ilu IQ mo; nse ni nwon gbe ara won sa IQ si ilu· kan bayi
ti a npe ni Ejlgbo.
Lehin ak6ko die ti nwon ti de ilu yI, awon na di onile. B'6
ha di ale, Idi a maa IQ na Qja ale g~g~ bi awon obinrin yoku
IIa ni 6 ngbe IQ s'ojil IQ la lalaale.
6 ti pe, p~, p~, lehin eyi; QrQ 'iku' obinrin yI ti kuregbe-
kuregbe, enikeni ko si ranti r~ mo, Ni ijo kan ni okunrin kan
ti ilu QkQ akoko obinrin yI IQ si Ejigbo, t'6 si IQ ha Idi pade
ni Qja Ejigbo ale ni ibi ti 6 gbe ti rita ila. 6 wo 6 titi, 6 ni,
"Idi niyi; ab'oun ni, ab'oun k07 Eni ti 6 ti ku, kini iba tun
gbe e de ibiyl?'
6 sunmo QdQ obinrin yi, 0 si b~r~si i YQw6ila, laini ila i ra.
B'6 ti nYQw6 Qja ni 6 riwo 6ju obinrin onila yJ. Obinrin
onila nfi oju pamo k'6 ma fi ri oju oun, sugbon b'okunrin
yI ti rifi oju kan YQw6 Ha 1'6 nfi oju keji y~ obinrin onila yI wo,
t'6 nSQ pe ila k6, k'6 paarQ r~ f'6un. Igbati Idi fojupamo
titi, ti ara r~ ko gba cl mo, 6 jagbe mo okunrin na pe, 'B'6 6
ko 'la 0 k6 'la, b'6 6. gbeni 0 gbenl, ewo l'abQrQ wo oju
Qloja l' oja EjigbO 7 Alw« 6, oju oku 1'0 nwo nnl!'
64 A-KU-MA.-KtJ'-T..\N
Okunrin yI yara kuro niwaju r~. Pipada C6 pada de ilu won,
ile Qrunmihl, QkQ obinrin yI tele, 1'6 gba IQ taanlta, C6 si SQ
gbogbo QrQ na fun un pe oun ri ldi I'Qja Ejigbo nibi ti 6 gbe
uta ila!
Orunrnila ko koko gbagbo, sugbon nigbati 6 p~ t! iyen ti nso
Danrawo
Danrawo
1. Tani awon Yoruba npe ni Ajatorun?
2. Kini k6k6 isoro t'6 wa fun oba ilu enia lati ri Erin 10 fi bori?
3. Bawo ni Ijapa ~e 'dira' n'ij6 ti 6 nlo mu Erin wa?
4. A~~wo ni Ijapa pa fun won n'Ilii ki 6 t6 kuro n'Ile ?
S. Ibo gan-an ni Ijapa wa Erin IQ?
6. Ki orlki Erin.
7. NWQn kol fi Erin joba, Ijapa ti ripe e ni 'Kabiyesi'.
Kini eyi fihan nipa a~ Qba-jij~ n'il~ Yoruba?
8. Kini idi r~ ti ara fi nfu Erin ~e boya iro ni Ijapa npa fun oun?
9. Ona wo ni Ijapa gba fi okan Erin bal~ p; 'otitc' ni oun nSQ fun
un?
10. Lo awon gb616him wonyi mo QrQ IOna ti yio fihan pe 0 mo
itumo won:
(a) l~mQ~o-l~mQ~O,16midan-16midan
(b) QrQ na pa mi l' Qda
(d) fi ohun sil~
(e) ara r~ bu m'asc,
11. ~k6 wo ni ltan yi k6 enia?
17 Ogun Q1QYQati Ewf Ad6
Ogun QI9Y9 ati Ewf A(I£)
Apd eranld thbe Ir,5W9 Ldnlose,
Ag" mariwo rhbr 1r,51Vr,5Laruba.
Mo f'ogo,
Mo r'ogo,
Mo \\"0 'gbehin "rim bi yio ti suna, sun« si.
Enti \vo 'gbehin "ran suna, suna:
VD difaf''oba I'Ew; Ado.
Ologose, awo wcm rOde Aged;
Arerekosun, awo Oke Ijero;
EbUrfNgi-Ngi, awo orun ebe,
An'o imi poro aka:
L'o difo f''oba I'Arode 0)'r,5.
O'd'igba klnni,
Oba 1'0y(5 hgbogun r'Ode £11'1:
Qw{5 do-doo-do I' (} $an 1(1.
o d'tgba keji,
os« I'(JY9 ngb6gun r'Ode EwE:
QW{1do-doo-do l' 6 san If).
A.isinfJe OI6gboj£g(>l(J
Nwon wa de orl Elewt m'akoto.
oiu« I'Ol6gbiJ n$awo,
Ol6gbiJjigplp l'awo Ew{ Ado;
Otitr,5 I'Ol6gbo n~awo,
<5 wd d'016gbojigplp l'awo l' Arode Oyp-l/e,
Olitp I'Oiogbi> lifawo.
Awo Ewi Ado ni OlogbojigQlQ i se teletele ri; sugbon 6 tun wa
pada di awo l'arode OYQ. Ogun jija ajaku-akata 1'6 mu ki
eyi ri be.
Ni igba atijo, Oba Ewi Ado ati OIQY~ j~ awon oba t'o ni
eru PUPQ. Oko ni nwon maa nfi awon eru ti nwon ba ri k6
l'6gun ro,
70
om~UPA 71
Oni-oni, bi oba Elewl ha k6 eru nibikan, awon emewa
a
QIQy{l a gba IQwQ re; ola-ola, bi QIQy{l papa na ba k6 eru,
awon ~m~wa Elewl a gba a; titi, 6 di ogun.
Alagbara meji pade ara won ni QrQ awon oba mejeeji yl
je. Nkan t'6 wa nibe ni pe agbara ti Oba QIQy{lPQ ju ti ~wi
Ad6 IQ; nipa b~, ilu Elewl fer~ tu tan nibi ti nwon nk6 won
l'~ru lojoojumo laisimi.
Nigbati QrQ ki a gbogun-ti-tni, kl nwon mu-omo-eni-l'eru.
yI ~~ npoju, -oba Elewl to awon alawo r~ IQ. 6 si beere pe
kini oun le se ti oun yio fi bo ninu ogun QIQy{l?
Ol6gbOjigQIQ, t'6 dafa yI fun Ewl Ad6, ki odu t'6 wa
fun un. J;.bQ ti 6 ni lati TU, nwon ka a, ile kun=-k! 6 le tu, ki
6 le ba, Id nwon ma le ko won I'em mo.
Laisiyemeji, nwon rubo. Lehin ti nwon rubo tan ni nwon
wa ka eewQ ibe fun won pe ki awon ara ilu Ad6 inA j~ obi,
ki nwon ma si se l'aya meji tabi fe a.lejo I'aya. Ol6gbojigQIQ
fi QWQsQya fun won pe, l'Akoko t'oun yI, ogun QIQYQ ko
tun le ri won gbe ee mo,
Lehin eyi, Ol6gbojigQIQ ya aworan meji fun won; 6 se
i~e ifA s'ara aworan mejeeji wonyi, 6 si gbe won si igun ile
ninu yarA r~. Aworan mejeeji 1'6 ni eewQ: ekinni ko gbodo
j~ ~j~ aja, ekeji ko gbodo Ie akuko adie pelu iYQQ~.
016gbojigQIQ SQ fun EI~wI Ad6 pe, l'QjQ-kQjQ ti QIQYQ ha
ti tun ngbogun r~ bQ, ki nwon tete wa SQfun oun. 6 ti gbo-
kanle awon aworan ere t'6 gbe kale ni igun yarA r~ yI. Bi
ogun ha ti ku ola, bi nwon ba pe awon ere wonyi ni oruko
t1 nwon nje, awon ere na a parada di enia, nwon a IQ pade
ogun loju ona, nwon a si pa won IQ ni ipaknpa.
OtQ-ntQ, 6 di 19ba kinni, oba QIQYQ gbe ogun r'Ode Ewi
sugbon QWQdo-doe-do 1'6 san IQ. 6 tun di lgba keji, bakanna;
eketa papa ko yato si meji t'6 ~AAju.
Nwon pa awon ara QyQ yanna-yanna bi ejo aijy m oori
~~m~t~~ta t6b~ ti ilu QYQfi joro; ti enia ko si fi ~ PQ ni llu mo,
Nigbati QrQ ri bayi, QIQYQni kini oun ri yi k~? tIu ti awon ti
nko ni eiye-ko-soka! NWQn ma ri oogim pa se gan-an ni Ad6 o.
Were, QIQy{l papa ranse IQ ~a-~a-~ si QdQ awon alawo
r~-awQn bi Odidere, Ar~r~kosun, ati Ebure Jegl-jegi,
Nigbati nwon de, QIQy{lSQfun won De omi ma ti b'ehln YQ 0;
72 OGUN QLQY{I An ewi AD6
D8DraWO
A'aye Qrq
(!tan yl wa lati inu odU OW9nrin t'oun btura)
rt A f NA TI A Ki i BQ$t-Qja
N'IBI ti a ki i tete be} bi a ha IQ n4.a
oKuTA~aiti Qja
~GBA_:'sisi,kobo mefa
KO TA EDOLO-ko ta rara ninu Qjil r~
Yow6 A-yo-i-LtJMC)-YQw6 nl iYQkuYQ, laisimi; YQw6 fun lgba pipe
80 OJU ~UPA
Danrawo
I. Tani Oluwo AtamajObara?
2. Nibo ni Atamajfibara ti nta QkQ ti QkQ r~ ha rQ?
3. Bawo ni E~use se aya ah\g~d~ l'oore?
4. Kini idi r~ ti awon ero Qja ko fi le YQw6 Qk(i IQwQ E~u'?
5. 'Gbogbo ara Qja, ~ jowo gba mi 0; ~ru baba mi t'6 ti sa IQ ni mo
ri yi o. E j<;>wQha mi mu u k'6 ma tun sal<;>m<, mi l'(iw(i 0.'
Kini fa gbolohun yi wa?
6. Kini itan yi fihan wa nipa iru eni ti E~itati Aje i se?
7. Kini 0 me) nipa ori~a E}u ati Aje ?
8. ~ni melo ni Aje k6 wa s'Qja n'ijQ ti Atamajubara mu u l'~ru'?
9. Se alaye gbolohun wonyi:
(a) QTQ ko pariwo
(b) onisowo na ko la edolo
(d) okuta lu Qja mo 9 16r!.
19 Seyida t'o ki ara r~ m'ebo
Ogbon agbVngb9ntall
Oro ni i ko'ni;
r
Aobe im9 nil ta ara 1'0#:
A difd fun $eyidd, ()m() Wonhl«
Ti yi6 ki ara ~ m'~b().
Baba $eyida yi j~ babalawo. Oruko baba r~ na si ni WQnnle.
Nigbati $eyida gbQnju daadaa tan, baba r~ mu u s'odo lati
maa ko Q ni i~~babalawo. $eyida kQ ifa, ko ko Q tan 1'6 fi SQ
pe oun ti mo i~~ t6! Baba r~ SQ fun un pe k'o tubo mu siiru,
k'6 kQ i~~ die si i sugbon $eyida gbonri pe oun ti mo Q to, Ni
baba r~, WQnnle, ba dak~ t'6 riwo,
Laipe r~ n§. ni $cyida so apo ifa kQ ejika, t'6 doriko Qna pe
oun rise i$~ awo IQ. 6 de ilLIkinni, 6 yiwopada gege bi babalawo.
Eni ti ori ko ti t1fQnibe t~I~, ori beresi i fQ Q; eni ti inu kl irun
tele, imi rirun un; eni ti ~dQ ki i dun tf;l~ di eni ti ~dQ ririn.
Gbogbo awon ti nkan nse wonyi beresi i wa s'odo babalawo
alejo yl, 6 si nse oogim fun won, ara won riya. Lehin ti 6 ti ri
owo se nibe tan, 6 tun gba Qna ilu keji IQ. 6 tun nse e bakanna;
b~' 1'6 se titi t'6 fi de ilu kan ti a ripe ni Ajeji-o-gbQdQ-wQ.
tj~nj~ ana dun mo ehoro ni babalawo yl se ni lIu Ajeji-o-
gbodo-wo. 6 yi QWQpada IQdQ won, orisirisi arun si beresi
won $e. Bi ori ti rifQwon ni aiya ridun won. 'A ko ri iru eleyi ri',
ni nwon rike. NWQn a sare to Seyida, alawo 1'6 ~~$~ WQi1u won .
yl, IQ pe k'6 gba awon. Oun na a se egbogi fun won, ara
won a si ya. NWQn a dupe IQwQr~.
Nigbati 6 ti to ijQ meta tl nkan wonyi ti n~~I~ ni awon
agbaagba lIu A.jeji-o-gbQdQ-wQ ha pe apejQ pe QrQ na ti to
y~wO. Kini 6 ti j~? Iru eIeyi ko $~I~ ni llu awon ri! Tani fa
alsan WQlIu awon wa? lbi ti Of un ti riwo 6, ti Iworl riwo 6,
nibe ni agba kan ti mu imoran wa pe ki awon k6 obi f''osika,
ki oslka 0 f'enu ara r~ wure: babalawo alejo t'6 wa n'ilil awon
Vi, ki awon pe e k'o difa fun awon nipa alsan t'6 ripo ni i1u
81
82 OlU O~UPA
awon yl.
Gbogbo won 1'6 SQ pe imoran agba yI dara t6tQ; nitorina
nwon ranse pe Seyida, NWQn fi eejl kun eeta, nwon ni ki
Seyida ba awon se ayewo QrQ na.
Bi babalawo yI ti da QP~I~wai bayi, 6 mi ori, 6 SQfun won pe
ohun ti odu t'6 YQwi ni pe ki nwon fi ajoji t'6 ha wa ni ilu won
rubo, gbogbo aisan wonyi yio si kasenile.
Seyida ko mo pe ara oun ni oun ki m'ebo yI nitori ko si
ajeji miran ni ilu yi ju oun nikansoso IQ. Se Ajeji-o-gbOdQ-wQ
ni oruko ilu yl, Seyida nikan ni ko mo t'6 fi wo ibe wa.
Ko si sise ko si alse nibe, awon agba ilu ~ju si ara W9n pc
Seyida ni ki awon mu fi se ebo na. NW9n ta ika si i fun awon
geride pe ki nwon ra a l'okun, ki nwon si fi pamo ki 9jQ ebo na
fi pe.
Ni ile ibi ti Seyida ti jade, baba r~ Wonnle ko dekun didafa
wO nigbagbogbo. B'6 ha gbe QP~l~Ioni, a beere nipa QmQ r~ yI
pe se nkankan ko se e, ifa a si fesi pe alafia 1'6 wa. IjQ karun-
karun ni baba Seyida nse bayi.
Ni ijQ kan saa, WQnnle difa wo, 6 ri ire owo. Okan r~ bale,
inu re si dun. Sugbon nigbati ile ojQ keji mo, ara beresi i fu
babalawo yi; okan r~ ko bale, b~ kori nkankan, Nigbati ara
yl ko ye i fu U, 6 ni ohun ti a 1 se ku, 6 tun na'wo gbe QP~le re;
ko si le duro de ijQ karun ti i maa difa wo mo. B'6 ti gbe QP~I~
$anl~ ni 6 ri ewu iku!
Eru ba a. 6 ronu ~a-~aa-$a pe kini oun le se o? Nikehin, ero
kan S9 si i ninu pe ki 6 maa wa Seyida IQ. Were, 6 gbe apo ifa
r~ kQ ejika, 6 si beresi i wa QmQ re IQ.
6 de ilu kinni, ko ri eni ic Seyida, 6 de ilu keji, bakanna
Ibi ti 6 gbe nlo lati ilu kan de ikeji yi 1'6 YQ si ilu Ajeji-o-
gbodo-wo ni osan gangan. 6 si wa j~ pe QjQnil ni awon enia
ilu ibe pejo s'ehin-odi ilu lati fi Seyida nibo ki ilu won le roju.
Bi WQnnle ti YQlokankan ni Seyida ti ri i pe baba oun ni.
ni 6 SQfun awon agba t'6 pejQ pe, 'llu yl ma se ori're 0,
J;::sC(kCfSC(
agba awo kan 1'6 YQlQQkan yl, oun ni ki ~ pe k'6 ha nyin ki
odu t'6 YQnil'.
NWQn ki WQnnle k'6 maa wole, ki 6 maa rora tan, 6 f~
j6k6, ni nwon SQfun un pe ki 6 mase joko. NWQn ni odu t'6 Y9
ni awon pejo lati rnbo r~ yJ, ki 6 ha awon ki odu na.
83
Dainrawo
1. Tani bi Seyida?
2. Nj~ Seyida kQ~~ye kooro?
3. Kini oruko llu cl Seyida ti Id ara r~ m'~bQ?
~EYioAT'6 Kt AAA R$ M'tDQ 85
4. Bawo ni ajeji se pc} t6 ni nu AjejieO-gbQdQ-wc} nf Ak6ko tf
Seyida wa nibe?
5. QjQ wo ni Seyida tun fojukan baba r~ lehin ti () ti kuro n'ile?
6. Kini se ti awon Agba Hu Ajejl-o-gbQdc}-wQ fi tun pe baba SeyldA
Id () ha awon ki odu na nigbati () j~ pe t'QIDQ ti baba ni awon
alawo mejeeji je?
7. Dlpo iku, ua ni Seylda tun k{) ni QjQ ti nwon tife pa a W~.
LQna wo?
8. Adura ojoojumo dara. Bawo ni itan yI ~ jeri si c}re}yI?
9. Kini ~kQ ti enia le ri kQ ninu itAn yI?
20 Otito-inu 1'6 pe
Bi oklti, bi akete,
Ko ntdn n'idl QPf-
A 11'0 AbfY(JY?
L'6 difdfiln Ab£Y(JY?
AbZv?Y(J 1'6 dlfafu« Ori,
L' 6 dEJa fun Orun
c» difafun Behe,
L'6 difa fun Orunmilb
L'(Jjr; t'al\"(J1I m~rffrin nsawo lo ree bd Olofin.
E.JlGBA.
i~Kt-il~k~ gigun ti oba nfi s'orun
KuiPA iDf-kijipa idi oba; bitnt~ ti oba ns{m
Danrawo
1. Tani babalawo t'6 difa fun AbiYQYQ1
2. AWQn wo ni AbiYQYQj~ alawo fun 1
3. Iru il~k~ wo ni a npe ni ejlgba il~k~ 1
4. Qgbon wo ni Qba QIQfin dei fi san ~san fun Qrunrnila ti ko
hilw! c}kanjuwil 1
5. SQ ohun ti aWQD iyawo Orunmila se nigbati 6 je pe isu m~jQ
lasaD I'QkQ won gbA bo QdQ Olofin.
6. 'Ere Ai~otQ ko dara.' Fi ohun t'6 Kl~ si Ori, Qnm ati Bebe, fa
Ododo gb616hun yl YQ.
7. E16 ni ow6 ti a npe ni tanga?
OTITQ-INU L'6 PE 9)
8. Salaye itumo gb616hUn QrQ wonyi:
(a) ma fi dUdupe funfun
(b) otito inu kl i sin 'm r'ajo k'a padanu
(d) Id enia j'ogb6, j'atQ
(e) tu k~k~QrQ dasil~
(Q) 'jQun k'6 0 ku' tilQ ni Q.
21 Oniwo saba aie
$ffull-~ffun l'a fzta~f
Gfjf-gfjf ['a 0 gb'og9:
L'o difdfun Oniwo, {)mQOdo-Ob«
T'o timl larin ip(5nju.
Oba ni Oniwo i se, 6 j~ okan ninu awon Oba pataki igbaanl,
Awon enia f~ran r~ jojo, ko si Ie pase ki nwon so pe aja wo 1'6
rigbo nibe.
Bi nwon ti feran Oniwo to yI, nkankan wa t'6 ba ajawo je-
apa r~ gb6rin ju itan 10: Oniwo ko ni kQbQ a YQna IQwQ. Oju
ow6 pQn oba yI de'bi t'6 fi f~r~ le ri imi eran n'il~' k'6 pe e
1'6w6. tpQnju yI PQ t6~ g~ ti odidi oba fi nta awon ohun-lni
r~ jeun.
Nigbati 6 ri i wipe i$~ yI ~ npQ jiI b'6 ti tQ 19 ni 6 ha to
babalawo 10 lati mo kini oun le se ti oun yio fi bQ kuro ninu
ipQnju yI. Odu t'6 jade ni ojQ na IQhun ni aope ni '<)~-fun-un'.
NWQn so fun Oniwo pe k'6 fi okQ at'Ma rabo; ati papa pe
oko ni yio ro la.
Lal$iyem~ji bi Oniwo ti se 10 ra OkQ ati ada jo niyi o. 6 ra
OkQ oun ada tan, 6 mu igb6 gan 10 rebe-rebe. B'6 ti gan 'gb6
tan, ko duro reti ki ojo rQ t'6 fi mu ire gbln=se nwon kuku ti
so fun un pe oko ni yio ro la. 6 f~r~ ma si ohun ti ko gbin sinu
oko Qhun tan. Bi nwon ha si so fun Oniw~ pe ak6ko nkan
gbigbln ko ti i to, ki 6 je ki ojo de, a dahun pe ki nwon fi oun
sile nitori oun mQ ohun ti oun nse,
OtQ-lttQ, bi eni pe kini Oniw~ gbin awon ire wonyi tan ~i ni,
16jiji ni ojo bu dasil~. Ojo yI rQ, rQ, rQ, 6 f~r~ le hu oku
alagbara. Ojo ko-modun yI rQ d'6ju r~; nse 1'6 dabi eni pe
Oniwo ti igi bQ Q 16ju ni, Bayi ni gbogbo awon ire t'6niw~
gbin fi bQ s6ju r~ r~gi bi eni fi owo moluke d'Imu.
Agbado oko Onlwo gbe QmQ PQn l~hin 10 tQQkiI-tQQku. Isu
tmpa san'l~ 10 I6n ebe pere-pere; ti ghagiIda ko tile ni siso, k'a
ma tun $~$~menukan awon ire ~~-~-p~ miran.
92
onr ~UPA 93
Inu Oniwo dun gidi nigbati ak6ko lk6re t6. Adodo agbado
ko n'iye larin oko, pepe isu ko 1'6nkaj apo ~gUsi IQ kiti-klti,
Ak6ko ti Oniwo kore tir~ tan ni QdA kanna-kanna da. Ojo
da pan, 6 si ke>ko re>mo. Gbogbo nkan na buru n'ilu t'6 fi j~
pe ag~ kan ko nl onje tita, ayafi Oniw6 nikan 1
Gbogbo ara ilu beresi i rQ girl girl wa sodo Oniwo lati ra
onje, Ko tile nse awon ara llu r~ nikan 1'6 nwa ra onje yI,
awon ara ibomiran nwa ra pelu, Gbogbo awon t'6 ti nfi Oniwo
~f~ t~l~rl ni enu won WQ wOVfo. OrQ wa di pe bi a ko ba ri
Oniwo ati m'QwQ r'enu di Qran. Bi Onfw6 ti se k~r~-k~r~ di
ol6w6 niyi, bi baba ti nkQle 1'6 nkan aas~.
Se, 'biile aiye ha ny~ 'ni, lwaibaj~ l'ai hu: 1'6 difA fun Elerhpe
ijQsi, t'6 de iho agilhiti YQs'orun. Eyi ti Oniw6 ibci maa fi ~sQ
j'aiye ni m~IQ-m~IQ, 6 tl o. Nigbati 6 Je t'6 y6 tan nse ni 6
beresi -I fi QWQlu ap<>ow6 $Q-$Q-$Q,a nl, 'Ow6 re e l' B'6 ha ya,
a fi ife b'enu, a maa sure lako-lako,
Awon t'6 gbQf~ wat~ ohun t'6 tifi ife wi yl tl. Nigbati nwon
jli ife yI ti ni nwon ba de omoge kan si i pe k'6 ba awon wa
itumo ohun ti Oniwo nfi ife SQyI. Omoge yI j~ okan ninu awon
omobinrin t'6 ti nwa lati ()yQ wa ra onje IQwQOniwo.
Bi omoge yI ti nawo if~ si Oniwo ni 6 han an ponkan bi
igbati okun m'eran. tf~ti Oniwo til~ ni s'omoge yI tun ju eyi ti
6 ni si awon iyawo t'6 f~ s'lle, Ko me> pe, 'Etutu ko feran
porop6ro de'nu: ibi ki 6 fije 1'6 mo'. Ko ~ rara ti Oniwd fi SQ
ohun t'6 nf'lf6 wi fun omoge yI. 6 nl ohun t'6un nwi niyi:
Ero ()yQ 0, er wi f'Qba,
P'emi Oniwo $Rba aje 01
Bi omobinrin yI ti gbQ 3.$lri ohun t'6niw6 nfi ife wi 1'6 ti
sare paarapa IQ si ile Oba OIQYQ,6 si SQ nkan ti Onlwc oft
ife wi f'Qba.
OlQYQ dahun pe, 'Oniw6 nA! 6 ma ti di nkan nisisiyi I I'
Omoge yI papa se sunnasi pe, 'Ok6te ma ti kuro ni iye a nta a
ni QrQ Oniwo'.
OlQYQni oun odidi oba pataki na ni Oniw6 nSQko QrQ si ~!
Nigbawo ni ok6 d'ow6 ti ana, na, na, ti ko tan ~! Mara, 6 ni
ki nwon IQ ha oun mu u wa; enu ti lgbin fi b'6rl$i, yio fi gbo'l~.
Eyi ti a ti nwi yI ~, nwon ti gba ogun jo lati IQ fi mu Onfwo.
Bi QrQ yI ti ta firi si E$u l'eti, 6 gbera, 6 to Oniw6 IQ, 6 s1
94 ONiw6 $ABA !UE
~6fof6 fun un pe QIQYOnranse bo wa mu u.
Aiya Oniw() ja. 0 t~wQ e~ si E~u pe kini oun wa le se?
E~u ni b'6 ha ti le rubo oun le se e ki ogun OIOYQma fi le mu u
IQ. t~~jU ~ya, Oniwo ti rubo lati fi ta ebo ~u elanu.
Lehin ti E~uti fa a l'ori, t'6 fi c)dei kun an tan, 6 kQ Oniwo
pe ki 6 10 ra apo 'Idoho jQ, kl 6 si fi won da agbada ati $okoto
pelu fila. 6 tun kQ Q pe ki 6 ge igi oparun jQ, ki 6 g~ ~ ni ap6,
ki 6 si gbe ap6 wonyi fun awon o~c)na ki nwon ha a fi a~
dudu, pupa, ati funfun 1>0won l'ara. Lehinna kl 6 so won
dlro-dlro-dire-diro mo agbada yI. Ti ogun ha ti de, 8$Q yI ni
k'6 yi wole ki 6 IQ wc)jade ko ogun nft. 16ju. Bi nwon ha ri i,
aiya won yio ja, nwon a si maa ja ara won niyan pe se ~ni ti
nwon so pe 6 ~M aje na re e! Eleyi kl i se aba aje, aba ap6 ni.
K'a wi, k'a fQ, ogun wo Ode-Iwo, okiki kan gee, ariwo ta
lahi IQ ha Oniwo pe ogun de! Were, Oniwo ti yi WQI6,6 si ti
gbe agbada r~ yI WQjade g~g~ bi E$uti kQ Q. B'6 ti YQju s'ode
bayi, ti awon ogun OlOYQri i, jlnnl-jlnnl dei 1>0won: awon t'6
si ya ojo ninu won juba ehoro.
Nigbati awon t'61aya ninu won sunmQ Q. Nigbati nwon ri ~wU
agbada 1'6 wc) nwon ni, 'Iwo Oniw6 na ni l~ run YQ l'ara r~
to bayi. Sebi nwon so pe 0 saba aje l'
Oniwo dahun pe oun ha to ~ ni 11uti 01QYQwa! AM apo ni
oun wi, oun ko so pe oun se aba aj6. Nwon n1 ki 6 tun korin
na k'awon gbQ. L'Oniwo ba tun ~r~:
Ero OyQ, ~ wi f'Qba,
P'emi Oniwo ~M ap6 o!
Ni c)rc) ha pesije. () di agbetl ti genge rigbQwQ, agbeti ti
omode kekere rigbe igi e18ra. Ni ogun QIQYQha ~ri pada IQ SO
fun OlQYQpe QrQ nft. ko cl ~ 0; aba ap6 ni nwon ri ti nwcn
ripe ni aba aje o.
ABye Qr9
(itml y1 ni a rl ninu odU irftt Al4je ,abi lriJ ~kUn)
$~N-$~ L'A NTA$~~ ni ora t1 6 Dke; didun r~ nigbati 6 ha
kQkQ ~r~ ni 'sefun sefun', eyfj~ apejuwe dldun r~
T'6 NMi LAJuN lPQNJu-t'6 mbe lann IpQoju
bJb Ko.MQDUN.......ojo
ti ko tele alc6ko tl ojo MQ ninu odun; ojo t'o
mQ ni ak6ko ti a ko reti ojo
OJU O$UPA 95
PI QWQ MQL1JKED'fMU-mQhike ni arun t'6 nwU si enia ni ~hln
9WQ. Nitoripe ~hln 9WQ onfmQhike ti sa. bl 6 ha fi ~hln 9WQ
yI di imu fun Ofun, nse ni ibi t'6 ga l'~hln 9WQ )'1 yio di oju
ihO imu r~gi
~u WQN wQ wowo=enu won ka le soro mo; kl enu enia maa
gb(ln laUes(lrQ
An M'QWQ R'~ DJ (,lRAN-~oro PUPQ lati ri onj~ j~
J' AlYE Ni M$LQ-MtLQ-j~ aiye ~l~-~l~
$A8A. AJE-~e adodo tabi aka ti nkan aje kiln inu r~
WQwo---bi otutu ba nmu enia, enu r~ yio mu gbQn pe-pe-pe, -bi
enu ti ~e ngbQn yl ni awon Yoruba npe of wowo
(,lDA KANNAKANNA-Qda tl 6 da 16jijl lairot~l~ nt Ak6ko ajo. Qda
tf 6 da nigbati 6 $i y~ ki ojo mu r(l
Danrawo
e
Orisa-nla se gan-an ri ti 6 fi ri QmQ na bi? Orisa-nla dahun pe
awon alawo kan ti a ripe ni 'Funfun-I'eiye-nsu' ni. Orunmila
ni Orisa-nla ko IDQ pe funfun ni 6 maa bi ri! Ki 6 tun gbe
QmQ pada to won IQ o.
Lati igbana wa ni ko ti se i se fun enia mo lati yi aWQ aCin
QmQ pada di dudu.
Alaye OrQ
(Jnu odu Owpnrin oun Ogundti ni a ti yp itim y()
Danrawo
1. Tani alawo t'6 difa fun Orisa-nla nigbati 6 nwa QmQ?
2. Tani da ti Qrunmila nigbati 6 fe SQ afin QmQ di dudu?
3. Oluwo wo 1'6 da fun Orisa-nla ti yio so alawo r~ di opurQ?
4. AWQn orl~a kan ni il\l Yoruba j~ ako, awon kan si wa ti nwon
j~ abo. Ewo m Orisa-nla j~ ninu won?
5. Kini ipo Orisa-nla ninu ilu won nigba aiye r~?
6. AWQn QmQ'~ Orunmila fi Q~ ~hln j~ ~ n'Isu ninu ltan yl.
LQna wo?
7. AWQn Yoruba maa mbo oke 8\lS\l bi orl~. Daruko oke meta t1
a maa mbo b~ n'il~ Yoruba.
8. Kini se ti oju fi nti Orisa-nla lati gbe QmQ r~ jade si gbangba ?
9. Daruko nkan meji tabi meta ti a le SQ pe 6 dudil kirimu.
10. SQ ~kQ ti itan yi kQ wa.
Bi O$Upa ti i tan imQI~ ka gbogbo orlgun mereerin aiye
yl, b~ g~g~ ni Ifa j~; nitoripe 0 riran kedere WQ inu
igbesi aiye ~dlL Idi nlyi ti a fi SQ iwe yi ni Oju O~upd
eyi ti a pin si Apa meji.
Ninu Apd Kejt yI ni a tun ka nipa awon odu ti 0 YQ 16ju
opon ifa pelu awon ltan ti 0 ti inu QkQQkan odu wonyl
wa. A SI tun se alaye awon QrQ ti '0 ta k6k6 lati mo.
A se iwe yI fun lilo awon QmQ ile-~k(> giga, papa fun
awon ti 0 ndirasile fun idanwo ninu Yoruba fun
iwe-er! W ASC ati ti GCE, ki a ma $~$~ SQ ti awon ti 0
nkQ ~kq olukoni. Bakanna ni yio wulo pupo fun awon
ti 0 nko ~kQ ijinl~ ninu Me ati a$a l$~dal~ Yoruba ni
gbogbo ile-eko giga julo,
ISBN 0 19 575219 g