Está en la página 1de 3

MOJUGBA BASICA.

Omi tuto, ona tuto,tuto owo, tuto oma, tut ilé, tuto egun, tuto nini, tuto orisha,
tuto ariku babawa. Omi fun Eggun, omi fun ilé, omi fun Olorun.

Moyugba Olofín, Moyugba Olorún, Moyugba Oloddumare


Moyugba Ashedá, Moyugba Akodá,Moyugba babá (nombre del padre),
Moyugba yeyé (nombre de la madre), Moyugba ará, Moyugba ilé Moyugba,
oluwó, iyalosha, babalosha, omó kolagbá Egún Timbelése Oloddumare.
Araorún, ibá é layén t'onú: nombres de los ancestros del ile oosa y de los
ancestros creadores de la misma seguido de ibá é.
Ancestros:
 Jose pate palo Urquiola Esu bi.
 Pepa Esu bi.
 Osha bi.
 Oba di meji.
 Efushe warikondo.
 Apoto.
 Osha Inle.
 Oya dei.
 Ogun relekun.
 Oban yoko.
 Shango miwa.
 Oshun miwa.
 Oshun Funke.
 Omi dina.
 Omi diero.
 Shango tola.
 Maleke la grande.
 Maleke la pequeña.
 Los jimaguas de palenque.
 Tata gaitan Ogunda ofun.
 Miguel febles odi ika.
 Benito oshe paure.
Ibá é layén t'onún gbogbó Egún araorún orí mí naní “Eleggua Su nombre de
oosa”: Nombre de todos los difuntos seguido de ibá é
Ibá é layén t'orún gbogbó Egún araorún orí babalorisa emí.
Ibá é layén t'orún gbogbó Egún araorún orí Oyugbona emí.
Ibá é layén t'orún gbogbó Egún araorún orí ni gbogbó igboro kalé ilé.
Kinkamasha padrino.
Kinkamashé Ojugbona.
Kinkamasha Oba.
Kinkamasha Oluwo.
Kinkamashé Omo elegba.
Kinkamasha Omo ogun.
Kinkamasha Omo oshosi.
Kinkamasha Omo Obatala.
Kinkamasha Omo Oya.
Kinkamasha Omo Oshun.
Kinkamasha OMo Aganju.
Kinkamasha Omo Shango.
Kinkamashé Omo yemaya.
Kinkamashé Orí Eledá mí naní su nombre de oosa.
Kinkamashé gbogbó kalenú, igboró, aburó, ashíre, Oluwó, Iyalosha, Babalosha,
kale ilé.
Elegba.
Eleggua baralayiki, alawana kokori, bita tente oluo alado ure eshu ire o awo,
eshu ire o omo, eshu ire o dedewantolokum.
Ogun.
Ogun awan meji laguer owo oro, Ogun shiviriki, Ogun moka, Ogun alawede,
Ogun ala ilua.
Oshosi
Oshosi odde mata, onibode akiloyu ayugba.
Ozun
Ozun durunganga labosi ma dide madubule.
Obbatala.
Obbatala, obbataisa, obbatallano, obiri gaulano,akatioke okuni aye, fiedenu
baba mi, ayaguna aleyibo, jekua baba ayugba.
Yemaya.
Iyami asarababi olodo, iyami asarababi olokum, iyami olalafara, iyami arubo,
obedi ako omone ishogun, koma iya, iya iya lolomio ayugba.
Shango.
Shango kawo kabiyesi, olueko ashe osanyin, ashere, oba lube ala lube, alafin,
kisieko, ogodo masa, akatabiomolefa, oba yakuta, olu oka jeri jeri jei ayugba.
Oshun.
Oshun mori yeyeo, aladekoyu debole, ebuyi odo, iyalode akpetervi olofin,
akpetervi orunmila, kwasi kwasi anya, di bangala bangala, aladekoyu, iyami
otolorefa ayugba.
Oya.
Yanza jekua jery jey, kakaza ake, Oya meza meza, Oya kochete ayugba.

También podría gustarte