Explora Libros electrónicos
Categorías
Explora Audiolibros
Categorías
Explora Revistas
Categorías
Explora Documentos
Categorías
IFAVERDADERO
ERES EL VISITANTE
7 - Òbàrà Méjì
(7)
C ontadores Web
I I Seguidores
II II
Participar en este sitio
Google Friend Connect
II II
Miembros (4)
II II
Òbàrà Méjì
¿Ya eres miembro? Iniciar sesión
(1)
Archivo del blog
▼ 2009 (9)
Yoruba
▼ marzo (9)
1 - Èjì Ogbè
2 - Òyèkú Méji / Èjì Òyè
Pelebe idi awodi oke laa wo 3 - Ìwòrì Méjì
Ka to moro agogo 4 - Òdí Mèjí / Ìdí Mèjí
A difa fun Orunmila 5 - Ìrosùn Méjì / Olósùn Méjì
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 1/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Español
en su festival anual.
El alabó a su Babalawos
Yo tuve éxito
Obarameji
El espíritu genuino
Ifá predice
Obarameji
El espíritu genuino
Ifa predice
Obarameji
El espíritu genuino.
(2)
Yoruba
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 2/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Ewe koko meji ni lura won
Pelenge pelenge pelenge
Adebe oje ni moju oloja
Español
suave e intensamente
(3)
Yoruba
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 3/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
A difa fun Akeke
Omo Ileepo
A difa mfun Eyele
Omo lasewe
Won ni ki won ru ebo
Won rubo
Won se Ifa fun won
Ni won ba bere si ni opolopo
alaafia ara
Igbati inu won dun tan
Orin awo ni won nko
Won ni mo yin o
E dabo
Mo moka
Omo ilu Iloro
Mo mere
Omo Ilabata
Mo makeke
Omo Ileepo
Mo meyele
Omo lasewe
Mo mo yin o
E dabo.
Español
El hijo de mascarada
Yo le alabo Ifá
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 4/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Yo conocí Oka
Yo conoci a Ere
Yo conocí Akeke
Yo conocí Eyele
Yo conocí Ifá
Yo conocí a todos
(4)
Yoruba
O ki mi ni paarapongba
Mo je ni paarapongba
O ki mi ni paarapongbe
Mo je ni paarapongbe
Kekere orore won ko legbe
Bi won ba ji
Won a ko wese wese
Won a ko wese wese
Won a si ko wese wese pelu
A difa fun Orunmila
To nlo di alayiki lola
Orunmila Ela soe
Ifa je ndeni apesin.
Español
Yo respondí severamente
Yo respondí solemnemente
El pequeño Orore
no es mayor
por la mañana
componen melodías
Orunmila se enriqueció
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 5/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Ifá usted debería
hacerme rico.
(5)
Yoruba
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 6/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Aran nikija
Opa kugukugu lojude Iserimogbe
Obara waa nyin awon awoo re
Awon awoo re nyin fa
O yanu koto
Orin awo lo bo sii l’ enu
O ni bee gege ni awon awo oun
Nsenu reree pefa
Gunnugun o tori abe rari
Ere awo Agbaale
Alagbede o fogun o tan laye
A dia fEji Obara
Eyi tii se omo ikeyiin won lenje lenje
Nijo ti won nlo
Lee sebo surusuru nile Olofin
Won o le fEji Obara seyin mo o
Iwaju lo gbe
Eji Obara, gbesin dudu
Eji Obara, gbesin pupa
Elegede mere,
Eji Obara ki lo ta
To o fi dolowo
Elegede mere.
Español
la faz de la tierra.
Pero, un día
Y las abrió
tercera
dentro de la cuarta.
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 7/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Esu borró con su mano las marcas
las calabazas
El se fue a la cocina
dentro de ellas
El empezó a bailar
El empezó a regocijarse
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 8/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
los tambores en la ciudad de Iserimogbe
la faz de la tierra
El estaba a la cabeza
(6)
Yoruba
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 9/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Akankatan lomodee
keyo oka.
Español
Llena de orgullo.
Y ella lo realizó
Llena de orgullo.
(7)
Yoruba
Keesekeese le ti nri
Kaasakaasa nbo leyin
Kaasakaasa babaa keesekeese
A dia fagbigbo niwonran
Eyi ti nsawoo lo sile Onikoromebi
Onikoromebi abayaa doko
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 10/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Aya Onikoromebi ndoko, lo beere si
Igba ti o fiya je obinrin naa tan
O gbe e ju agbala
O si de e lokun mole
Ni agbala ni Onikoromebi fi iyawoo re si
Ti o fi lo sodo Agbigboniwonran
Lo lee bIfa leere
Agbigbo ni ki Onikoromebi o se suuru
O ni eni ti o tori re bIfa leere
Nbe loride ninu agbala
Igba ti Onikoromebi gbo
Oju ti i
Ko lee lo tu iyawoo re sile mo
O ni ki Agbigbo o lo ba oun tu u sile
Igba ti Agbigbo debe
Dipoo ki o tu obinrin naa sile
Fife ni nfe e
Ni aya Onikoromebi ba mekun
O fi digbe
O fi iyere sohun aro
Awo kii sunkun ipin laluu ja
O ni keesekeese le ti nri
Kaasakaasa nbo leyin
Kaasakaasa babaa keesekeese
A dia fagbigbo inwonran
Eyi ti nsawoo lo sile Onikoromebi
Onikoromebi abayaa koko
Fife ni nfe mi o
Fife ni nfe mi
Agbogbo niwonran o tu mi sile
Fife ni nfe mi.
Español
la adivinación
El la tiró a su patio
esposa
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 11/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Agbigbo advirtió Onikoromebi que tuviera cuidado
Era hecha
el se avergonzó
la ciudad
para Abigboniworan
esposa adúltera
Agbigboniwonran no me desata
(8)
Yoruba
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 12/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
O bi lere nipa ala ti o la
Ifa ni ki Orunmila ki o sare rubo
Igba ti o ru u tan
Won gbe ebo naa lo si idi Esu
Laipe, Agbigbo gbe posi de ojude Orunmila
O ba Esu lojude
Esu ni ki ni Agbigbo o ki sinuu posi naa
Agbigbo dahun pe Orunmila ni
Esu waa bi i lere pe
Kini ni ohun oro ti yoo gba
Ti ko fi nii mu Orunmila lo
O ni oun o gba eku ati eye ati eran
Esu da a lohun pe gbogboo re naa
Ni Orunmila ti fi kun ebo ru
NI Esu ba ko gbogboo re jade fun Agbigbo
Haun ti Agbigbo ko gbogboo re
LO ba gbe posii re nle
O si kori si ona ibomii
Igba ti o lo tan
Esu ni ko gbodo so posi naa kale mo laelae
Titi di oni olonii
Posi naa mbe lori Agbigbo
Igba ti inu Orunmila dun tan
Ijo ni njo
Ayo ni nyo
O ni bee gege ni awon awo oun wi
Omii seleru o mu kengbe
A dia fun Agbigbo niworan
Tii se omokunrin igbeposi
Beku lo o baa gba
O gbeku
O maa yara lo
Agbigbo niwonran
Gberu e
Gberu e
Awa o ra
Beja lo o baa gba
O gbeja
O maa yara lo
Agbigbo niwonran
Gberu e
Gberu e
Awa o ra
Beran lo baa gba
O gberan
O maa yara lo
Agbigbo niwonran
Gberu e o
Gberu e
Awa o ra.
Español
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 13/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
El iría y lo pondría fuera de la casa de un hombre
El lo llevó
ataúd
Levantó su ataúd
De bajar el ataúd
El empezó a bailar
El empezó a regocijarse
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 14/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
coja la rata
Y márchese
Llévese su carga
Llévese su carga
Coja el pez
Y márchese
Llévese su carga
Llévese su carga
Coja el animal
Y márchese
Llévese su carga
Llévese su carga
(9)
Yoruba
o ro mi minijo
sosi, ewe koko meji, lo luara won
pelenje pelenje
pelenje, abebe oje, lo moju oloja tutu ninini.
To ba ba
won mule budo tan, to mu towo,
to mu taya, to mi taiku
ti o pari iwa.
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 15/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Español
o ro mi minijo
sosi ewe koko meji lo luara won
pelenje pelenje
pelenje,Abebe oje lo moju oloja tutu minini
A tomar la ciudad
llamada Budo.
Mas tarde el
Eji-obara.
(10)
Yoruba
ni awon babalawo ba ni ki o ma ro
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 16/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
oti, obi ati epo, nigba ti iwori ru ebo tan,
ijo ni njo.
Español
Y Obara no murió,
Vámonos a casa.
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 17/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
(11)
Yoruba
Mo ki o rarapongba,
O je mi rarapongba,Mo ki
o rarapongba,
Won si da wese
wese A difa fun Eji-obara ti yio di eni ajiki
lola, Eji- obara o wa di eni apesin,
Eji-obara.
Español
Mo ki
o rarapongba, O je mi rarapongba,
Eji-obara.
y mucha
Vamos y saludemos a
Eji-obara.
(12)
Yoruba
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 18/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Obara wo tu pere,
ni keke ba si rubo,
Español
Obara wo tu pere,
El hijo de Olomijo,
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 19/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
El hijo de Olomijo, Keke tiene venir el hijo de Olomijo,
Ha venido a mi regreso
Para bailar.
Yoruba
Español
Yoruba
. Ifá ni ire fun eniti o da obara meji Ifa ni ire ibudo, Ifa ni eniti to
da obara meji yio di oba ti won pe sin.
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 20/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
. Ifá ni ire ni fun eniti o da ifa obara meji, ifa ni awon nkan ti o
badawo le a yeri si rere.
Español
. Ifá dice que la persona que se le adivinó Obara meji logrará ser
Jefe en su vida y por eso la gente estará sometida a su dominio.
. Dice Ifa que hay buena suerte para la persona que la adivinación
dio Obara meji, que todas las cosas que emprenda tendrán éxito.
. Dice Ifá que la persona a quien la adivinación dio Obara Meji, sus
negocios prosperarán y obtendrá beneficios en cada negocio que
el invierta dinero.
Yoruba
. Ewure kan, opolopo iyan, eku,eja oti, ati opolopo obi igbamarun
oke-owo.
. Abo adie merin eyele merin ewure merin oke-merindinlogun oti ati
obi.
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 21/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Español
Yoruba
. Ifa ni aladimu, ao fi eyele bo ifa fun eni ti o da ifa yi,pelu oti, obi,
and epo.
. Esu ni aladimu, ao fi akuko die bo esu, pelu oti, obi, ati epo.
Español
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 22/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Yoruba
. Eniti o da ifa yi, yi o ma se iwure ni odo ifa nigbogbo igba pelu oti
ati obi.
Español
1 comentario:
Responder
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 23/24
11/10/13 IFAVERDADERO: 7 - Òbàrà Méjì
Introduce tu comentario...
ifaverdadero.blogspot.com/2009/03/7-obara-meji.html 24/24