Documentos de Académico
Documentos de Profesional
Documentos de Cultura
IBA BABA
IBA YEYE
IBA OLUWO
IBA OJUGBONA
IBA AKODA
IBA ASEDA
2. Homage
3. Acknowledgements
6. Prayer To Orunmila
A to'ogun
A mo I ku
Oluwa aiyere
A ba mo tan iba se ke
Ase o
Translation:
Sufficient as medicine
Ase o
Translation:
You are the light
I am the light
When the light is first appearing in the sky
Cast Ifa for Oloye Igale
The one with the good Ori that foams like soap
How does the head of a chief foam?
Upward with happiness!
That is the way the head of a chief foams
Our prosperity will foam up high
Another Morning
Prayer To Ifa
(From Oyeku Meji)
Opele lo yo tan
To da ikun dele
Ti se yeye ojumomo
Ojumo to mo wa lo ni
Ojumo ire ni
Gbogbo ni
Translation:
Photo: Sunrise
Prayer For Protection
(From Ogunda Meji)
Ifa lo loni
Ifa lo lola
Won n wi pe
O da Ogunda Meji
Won ni ebo ni o waa ru
O si ru u
Ni iku o ba le e pa a mo
bee ni arun o le e se e mo
Ijo ni n jo
Ayo ni n yo.
O ya enu koto
Ese ti o na
Ijo fa a
O ni bee gege
Ni awon awo oun n senu rere e pe Ifa:
Ifa lo loni
Ifa lo lola
Ojo tiku ba n wa mi I bo wa
Translation:
Of its bed
Odun wonranwonran
Orunmila ko ma se fa mi le ku lowo
K i un ko o sile mo
Ataare o ni binu
Ko taari omo re sita
Ara ni n fi san
Death never kills Otutu (Ide Ifa, Ifa Beads) in the home
of Ikin
Gbabila Gbabila
Won ni ko rubo
Won ni ko mo baayan ja
Ko si mo benikan
Inu e dun
N ni wa njo ni wa nyo
Gbabila Gbabila
Translation:
Gbabila Gbabila
Gbabila Gbabila
Divined Ifa for Iwori
O tu puke
Boo na gbaja
O na gbaja
Ko na gbaja
Ko fi ba Eji-Ogbe je ooko
Kangere
Ma dagba, ma da arugbo
Kangere
Translation:
If you want to unfold
You should do so
You should do so
Kangere
I will live long to old age
Kangere
Ebo ni won ni ko wa se
O gbebo, O rubo
Translation:
He complied
peace of mind
Bale ba le
Boorun o ran mo
Ti ngbeboo lo Ilu-mogbo
Omo toun ba ni o
Bo ba dale
Translation:
I will go
ni arokuro ojo
Translation:
All he plans to do
Will be fruitful
Ebo ni won ni ko se
O gbebo o rubo
Omo to niwaju
Omo a to leyin
Translation:
He complied
A oo jo jo jo
A oo yo yo yo
Translation:
Yam is good for festivity when it is mature
We danced a lot
We rejoiced greatly
O gbebo, o rubo
Ori je n nibudo
Translation:
He complied
Ori, please let me have stability
Otura funfunfun
Otura funfunfun
Otura funfunfun
Ile Oyin ma n ho o
Ti Ado n yo
Otura funfunfun
Otura funfunfun
They complied
Lo yojuu re sodoodo
Oyeepolu o mokan o
Isoro Olorun
E wa ba ni toro yii se
Isoro Olorun
Translation:
This was the Ifa cast for Oyepolu, the child of tradition in
ife
Oyepolu is a novice!
Prayer To Ori
(From Ose Obara)
Ose bula lago
Dia fu Ina
Ebo ni won ni ko se
O gbebo, o rubo
Iwa a re a si goke
Translation: