Está en la página 1de 6

The Ifa for protection

Akas, akas, akas

Aronikasako

Ina ni ngbenu aso yo abe

Itale ni ngbenu ile yo ida

Adifa fun oka, odifun Ere,

Oka ni ori ohun ohun ni

Ere ni ori ohun ohun ni

Aja Ogan ti oba jin, or arare ni o njin le

Aja okiti ti obajin, or arare lo njin si

Asasi pehinda ki olopa alasasi

Ki ebo pa elebo

Gbogbo eniti oba n bami se ota

Okari Kan kan ni omode n te eru - isu,

okankan, ki ota mi maku.

OFO EYONU AIYE

Akinoro awo ori ogun ode

Koleja awo ode idewure

P ye awo ode igbari

Eda giri giri awo ode iwafin

Awon mererin omo ikofa orunmila niwonse

Won wa sawo lo sapa okun ohun ilaji


Meji osa, won gbagun okun, won gbagun ide,

Won gba ola win ni win ni aso

Nigbati won ko de

Won wa paju otada si orunmila,

Won fi ojojo ba orunmila ja

Orunmila sun ori apere loju o run,

Baba ji oso ode iponrire kale oransepe Odimodimo onikiwon


wa dafa fun oun

Wonkori ohun meji oOsameji ni won ri,

Won ni akin oro nko?

Baba ni omo iko fa oun nise,

Won ni koleja nko?

Baba ni omo iko fa oun nise,

Won ni poye nko?

Baba ni omo ikofa oun nise

Won ni eda girigiri nko?

Baba ni omo ikofa oun nise

Won ni awon wonyi ni won nba orunmila se ota.

Orunmila ni haa bi oba ribe oni kiwon ku pata pata

Akin oro ku odi eiye oyo

Koleja ku odi eiye kowe eiye aje

Poye ku odi eiye ogbin gbin

Eda girigiri ku du odi owiwi


Won wa ni awon ti mo pe Orunmila lopa awon,

Won wa gbera won foro wa ba orunmila ja

Won de oju ona tan, won se apa

Won se ese won ko lee fomo,

Ara wa niwon pupo,

Orunmila wa nrinlo sode,

Baba bawon ni bi ti won gbe selapa selese si

Won wa nbe orunmila

Won ni orunmila dakundabo awon koni ba o jamo lailai

Orunmila ni bi abari eleiye keleiye tabi emere kemere ti oba

Tun da oju ija kowa nko?

Won ni odimule o

Woni won ase Lapa lese won koni gbadun rara titi won yio fi
ku

Sugbon ki orunmila ma pa ese

Orunmila ni kosa ma pese

won ni awo tun ku awo amosun awo amore otun ku awo

Osunsun tere- eyi tinse awo igi egungun

IFA AYAJO OBI OLOJU META (5)

Iba, jini iwo lomo bibi inu won

Ni ilu awusa (3 time )

Epe iwo lomo bibi inu won


Ni ilu ijebu ( 3 time )

Ase iwo lomo bibi inu won

Ni ilu ekiti efon ( 3 time )

Ase iwo lomo bibi inu won

Ni ilu ota

Nigba ti jini omo bibi

Inu won nilu awusa

Gbogun ti Orunmila, Orunmila pa jini

O yo okan jini o fi ro epo je (3 times)

Nigba ti epe omo bibi

Inu won ni ilu ijebu gbogun

Ti Orunmila, Orunmila pa

Epe o fi okan re ro

Epo je ( 3 time )

Nigba ti ase omo bibi

Inu won gbogun ti Orunmila,

Orunmila pa ase o fi okan ase

Ofi ro epo je

Nigba ti aje gbe ogun

Ti Orunmila, Orunmila

Pa aje ofi okan aje ro epo je

Emi ( name )

Ni mon fi okan yin


Ro epo je loni yi o.

IFA AYAJO

Iba,

Eke ni pa eru ( 3x )

Iyan jija ni pa iwofa ( 3 x )

Awon wonyi ni won difa

Fun ori yomi nigba ti nbe

Larin ota

Won ni ota nbe ni waju

Won ni ota nbe ni eyin

Won ni oriyomi bawo lo se ma yo larin ota sikiti

Ori yomi ni won le ba

Ori yomi ni ori toun ni o yo oun

Oni ___ nitori kini

Oni tolobi ba mu obi

Olojumarun dedi orisa

Ni se ni won nyo ofua

Re sile ni

Ori yomi ni wo o yo oun

Sile dandan ni

Oni oso o yo oun sile

Oni aje o yo oun sile


Awon emere o yo sile

Ki ori emi ( name)

yo mi sile

Ninu ibi omo araye o

Ase Olodumare Olodumare ase

También podría gustarte