Está en la página 1de 1

AGADAGODO ETI

Ori eku kan, ori ja kan, akan oke kan, isawuru kan, afomo igi kigi, atare
aja kan, ao jo papo, ao di mo agadagodo. Ofo-r: ja ki roju wole to eku,
bni eku ki roju wole to ja.
Alakan ki roju wole to isawuru, bni isawuru ki roju wole to alakan,
Airoju, airaye ni ko si ni j ki won wol to ara won.
Bni airoju, airaye ni kij ki Afomo tagbo wol.
Airoju, airaye yn ko lo ba lagbaja, airoju airaye loba atare aja ni ojo kinni
lo fi j pe, apo odidi toda omo sinur lonkisi, ohun na lo ba ja ti ko fi roju
wa eku losi papa. Airoju, airaye na lo ba Eku ti ki fi roju wa ja lo si odo
oluwri, ki lagbaja mase roju raye lati wami wa mo o. Ao ti agadagodo na
pa. Otan

También podría gustarte