Está en la página 1de 334

MANUAL DE

TRABAJO

IFA GBEMI

1

Ela Ola, LLC

2

Ela Ola, LLC

EBO

3

Ela Ola, LLC

EBO SEGUN IFA GBEMI

El babalawo le dice a Ifa el problema que trajo al cliente a la consulta según como el mismo cliente lo contó y después pasa a rezar a ifa este rezo apelando a Ifá para que resuelva el problema que tiene la persona:

Asabasin ooni Ilare Ojiloro ọbá ig dé Ó m jó olosi máá tan

Asabasin del rey Ooni Ojiloro del rey de Igede Ellos sabían que el día de la penuria terminaría

4

Ela Ola, LLC

Se reza por el nombre de la persona que va a ofrecer el sacrificio y por el motivo del sacrificio.

ÒtùráÒtùráÒtùráÒtùrá OsáOsáOsáOsá

(Rezo por el dinero que la persona ha traído para el sacrificio)

1111

Ọl fin k ’lé tán

Ọ kọ ojú rè s’

A d’ífá fún Òmìnìlògbà

Ti ikú àtí àrùn nwà kiri

Ọj ti ikú yọ sí Òmìnìlògbà, owó ló fi y

Òmìnìlògbà, owó la fi nyẹ ìpín ní run

Ọj ti àrùn kó Òmìnìlògbà, owó ló fi y

Òmìnìlògbà, owó la fi nyẹ ìpín ní run

5

Ela Ola, LLC

2222 ---- ÒwònrínÒwònrínÒwònrínÒwònrín ÒbaraÒbaraÒbaraÒbara (Rezo para quitarle las maldiciones y maleficios de la persona)

Owo otun awo Aba

A d’ífá fún w n lọdé Aba

Owo osi awo Abose

A d’ífá fún w n lọdé Abose

Atí owo osi kí rúbo fún ní àì m m dá yọyọ Ní ntí ilé y wà yọyọ ní ntí ilé Alapabo Wuru wuru ní nígbodé owu

A d’ífá fún Aṣewele

Ọmọ w n lọdé depenu Aba degun atí ẹpẹ Lé awo lórí kó m leeja Egun yíò pà Elegun Ẹpẹ yíò pa Elepe Kíní yíò pa Elepe fún awo Sawerepepe sare wà pa elepé fún sawerepepe

6

Ela Ola, LLC

Se coge la calabaza y se pone encima del dinero en el centro del tablero de Ifá y se canta:

(Rezo para pasarle el problema de la persona a

rúnmìlà) - Ìrètè Ìwórì

Àt pa Ìwòrì Babaláwo ẹrin ló d’ífá fún ẹrin Ẹrin mọ dí lé’rí Ẹrin nròde Àlọ Ìtàkùn tó bà ní kí ẹrin má dèé Àlọ T’òhun t’ẹrin ní nlọ Ẹrin, “Ni ígbàwo lo di òkè?” Ẹrin g’òkè Àlọ Àgùnfọn, ẹrin mà ti g’òkè Àlọ

(Suyere) Òsì ní abiyamọ ndá ọmọ r

7

Ela Ola, LLC

(El rezo para remover los obstáculos del camino)

Àt pa Ìwòrì babalawo erin A d’ífá fún Erin Erin nlọ rẹẹ gun oké alo Atí agba atí Itakún Tó bà ní kí erin ó m dé oke alọ Oun erin ní njó nlọ Eeyan tó bà ní kí ẹbọ M se dá kó m bà ẹbọ lọ

8

Ela Ola, LLC

(Se abre el ẹbọ rezando ṣé Òtùrà) Este rezo es para que Èṣù esté atento al ẹbọ y lo lleve al cielo

1111

Pankara wò wò wò idi Èṣù Kíí jẹ kèṣù otété gboro A d’ífá fún Etigbure Ti nṣe yẹyẹ ṣé Òtùrá Ìgbá àkùkò ndá já Eni tó ti sun kódide ṣé Òtùrá gbebo yì d run ó

9

Ela Ola, LLC

El sacerdote toca a la persona con el cowrie, o el maíz o el obi àbàtà para tener su consetimiento y si hay otros babalawos participando en el sacrificio, se les mostrarán para obtener de ellos el consetimiento para que el sacrificio se haga.

Awodi o lapa

O fese jale

A dia fun Alukulaka Nijo ti n sawoo rode Egba Ko sai fin lebo o Ohun ti Awo ba fowo ba Ko sai fin lebo

En Español

El halcón no tiene brazo

Pero usa sus pies para robar

10

Ela Ola, LLC

Hicieron adivinación para Alukulaka En el día que iba a adivinar a la ciudad de Egba Esto será definitivamente aceptado como sacrificio Todo lo que la congregación del Babaláwo toca Será aceptado en el sacrificio

11

Ela Ola, LLC

Rezo de Òtùrá Ìká con todos los materiales para el ẹbọ para que sean aceptado.

kín ningún-ningín awo Olókun

A d’ífá fún Olókun

Níjó omi òkun ò tóobù b

Àlùkò dòdòòdò awo Ọlósà

A d’ífá fún Ọl

Níjó omi sà ò tóóbù ṣin’ṣe Odíderé abìrìn ẹṣ kẹrẹw -kẹrẹw

A d’ífá fún Ollú-Ìwó Modù Ọbà

Ọmọ at run là gbègbá ajé kari wáyé

Ó túkà ó dà ká

rìgì lawo Àgbasà

A d’ífá fún w n ní ìṣ ṣe àgbéré

Nijó ti w n kó ohun ẹbọ s’ílè Ti w n Babalawo kiri

12

Ela Ola, LLC

A ró’hun ẹbọ lóníí a ro’hun ẹbọ

rìgì lawo Àgbasà

Ifá a rí `hun ẹbọ

ti nbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe

Rezando este verso, se van mencionando los materiales que se le van a presentar a Ifá para el sacrificio. Se deben mencionar todos los materiales,

por ejemplo:

rìgì lawo Àgbasà

Ifá a rí `hun ẹbọ

OtiOtiOtiOti ti mbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe

rìgì lawo Àgbasà

Ifá a rí `hun ẹbọ ObìObìObìObì àbàtààbàtààbàtààbàtà ti mbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe

13

Ela Ola, LLC

rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ OrógbóOrógbóOrógbóOrógbó ti mbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ AtaareAtaareAtaareAtaare ti mbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe

rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ AdìyAdìyAdìyAdìy ti mbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe

rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ ÀkùkÀkùkÀkùkÀkùk ti mbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe

rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ EwúrEwúrEwúrEwúr ti mbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe

14

Ela Ola, LLC

rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ EkuEkuEkuEku ti mbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe

rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ EjaEjaEjaEja ti mbẹ ní ilé yí nk ti ẹbọ ní í ṣe

15

Ela Ola, LLC

(Se continua diciendo todos los materiales que se hayan traido hasta que termine la lista)

rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ Bí ọl ti bá pọn ọtí tán dìdà á dà á

rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ Dàá dàá ní ṣe adìyẹ àba

rìgì lawo Àgbasà Ifá a rí `hun ẹbọ Dàní-dàní ní aṣiwèrè nrìn

16

Ela Ola, LLC

rìgì lawo Àgbasà

Ifá a rí `hun ẹbọ

Ẹni tó bá ní ki ẹbọ yìí má dá, á ma bá ẹbọ lọ

Cuantro encantaciones que se rezan para que rúnmìlà acepte el sacrificio

Ifá kó j k’ẹbo náà ó fín rúnmìlà koo j k’ér’u á dà Kóó j kó d’al de run dan dan dan

rúnmìlà r wá bara Ẹlésin Ọyán rúnmìlà r wá bara Âdàgbà Ojùmù Kí o wà l’áṣẹ si ẹbọ yíí dan dan

Ifá gb’èrù k’ẹbọ fín rúnmìlà gb’èrù j’ẹbọ dà Kóó j kó dá’l de run dan dan dan

17

Ela Ola, LLC

Ifá m ní kóo gbèrù kẹbọ fín Ifá m ní kóo gbèrù kẹbọ o dà Ifá m ní kóo gbèrù kẹbọ fídé àlàde run W n ní ná wò lo gbà tòó fi nj b

18

Ela Ola, LLC

Se comienza rezando:

Rezos de ṣéṣéṣéṣé ÒtùraÒtùraÒtùraÒtùra

ṣéṣéṣéṣé ÒtùraÒtùra,ÒtùraÒtùra iwo lọọ sááju ẹbọ Iwo lọọ síí kányin ẹbọ

1111

Òsétùrá gbà à tete Ajókànse lẹkún

A d’ífá fún akólóló

Ti n gbèbo lọ

Ti gbè ẹbọ ròde run

Aní ohun lohun t t dé ibi yìí

Ẹbọ ti

ní kà t t dé ọdé run

19

Ela Ola, LLC

2222

Pénpé lẹs tùbú là agẹmọ ní ò tó gèlè Ìbá tó gèlé Nbá mú relé l wé A d’ífá fún Awúrelà Ti n ṣawo ròde Ìj bú Àpèjin làá pe Oníy Àpèlà, àpèlà làá pe Awúrelà Ní Ij sé Awúrelà awo iré ní o

20

Ela Ola, LLC

3333

sétùtá awo Alara A d’ífá fún Alara Ọmọ Amurin kan dàgbà agogo ìdé sétero awo Àjèrọ A d’ífá fún Àjèrọ Ọmọ Ogbolu k rò ìjàjàlé Aj ṣe Oganna Imanse Adifa fún sétere ọmọ buba oye sé k j sé k sé ngbẹ bò r run wá yì Ìgbá ní olú odìdé Okiki ẹbọ á ṣí kàn kún Awa t t ru kó t t dá Ké bò wá ó t t dele Olódùmarè

21

Ela Ola, LLC

4

Pàákàrà wóó- wóó- wóó awo ìdí Èṣù

A d’ífá fún sé T r

Ti n gbebọ ilèé ròde run Ẹni í fówó ó ní

Ẹ wáá rán ‘fá nṣé

sé ngbebọ ròde run Bi ẹ nísé é rán Eni í fáya á ní

Ẹ wá rán ‘fá nṣé

sé ngbebọ ròde run Bi ẹ nísé é rán

Eni í f’ọmọ ó ní á ní

Ẹ wá rán ‘fá nṣé

sé ngbebọ ròde run Bi ẹ nísé é rán Eni í fère ẹ ní

Ẹ wáá rán ‘fánṣé

sé ngbebọ ròde run

Bi ẹ nísé é rán

22

Ela Ola, LLC

5555

Tóó n Olúwo

Tùféè ní Okúgbònà

Às al àse ààrò

A d’ífá fún arúgbó aborí ko-ko-ko

Níjó ti n lọ ọja Èjìgbòmẹkun

Kò tà, kò rà, ó mú ìwo àṣ rè l w

W n ní ó lósó

Ó ní ohun ò lósò

W n ní ó lájèé

W n ní gbogbo ohun tó bá wí

Ó ti ṣe máa n ṣe?

Ó ní ohun ò lósò

Ohun awo l r

Ohun awo làrẹ

23

Ela Ola, LLC

6666

Àwù lù wú lù manye

Àwù lù wú lù manye

Onìgbánso ní nfi ìgbá ire gbè jẹun

A d’ífá fún ewi awo aye

A d’ífá fún Egba awo òde orun

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Ire balè njó nilé

Esi njó loko

Babalawo lewi aye

rúnmìlà lẹ gbà ti nbè lòde run

Ẹyi owu ewi ayé owi

Lẹ gbà run ó gbà

Ẹyi owuwa awi

Irúnmọle egbáá siwa lenu

24

Ela Ola, LLC

7777

Tete ní tete da A d’ífá fún s teere Ti n gbẹbọ r de run Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Awa la tete ru Ẹbọ wà ní yo tete da Ẹbọ wà tetedele Olódùmarè sin gbogbo w n Gbogbo rè ní ifá gbo Gbogbo rè lọ gbalo s awurela ifá tigbo

25

Ela Ola, LLC

8888

Abẹ dé awo okira

A d’ífá fún Okira

Nijó tó nfọ jojumo sowo

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Aseti Abede ọdé Olódùmarè

M jẹkí nṣe Aseti laye

9999

Apadi ìgbá lẹro losoju beli beli

Bi ẹni pè kó gbe ri

A d’ífá fún yẹẹmi Osoronga

Ti ṣe iya awa awo ṣo ilé

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

M júbà ẹyin Ìyàmi Oṣoronga

M júbà ẹyin Ìyàmi Oṣoronga

M júbà

26

Ela Ola, LLC

10

Agbere gede ajuba aboju gbere ngebe A d’ífá fún Osun Sengese Oloya Iyun ó ngbè ibada ó ngbe ìkòkò Nbá ẹbọ gbogbo Irunmole yóò kú jẹ Ta lóní kẹbọ ọmọdá fẹlẹbọ Agbere gede ajuba ajuba náá Aboju gberen gede Osun Sengese A pè ó ṣẹbọ Agbere gede ajuba Ajuba aboju Agbere gede Yẹyẹ mi otoro ẹfon ẹjẹ kẹbọ Odá fẹlẹbọ omi Ota ó Edan ó Aagbo Irunmole ó

27

Ela Ola, LLC

Se reza el signo atoyale (el Odu que salió en la adivinación) y seguido el signo hermano contrario. Por ejemplo: si salió Ogbe Iwori, se marca este Odu y se reza alguna encantación y del Odu contrario Iwori Ogbe se reza otra encantación

1111

Afẹfẹ ní ṣegi òkò wè’lé wè’lé Efunfun lélè ní mi loporo titi A d’ífá fún olayorijuwo Tíí ṣe ọmọ olofín Lojó ti n momi ojú s’ògbérè iré Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Gbogbo igi ní nbè lòkò Ope ní yò yòri jú w n lọ

28

Ela Ola, LLC

2222

yìn làá wò Ká tóó bù bòrọokìnní Díá fún Ọ̀rúnmìlà Tíí ọmọ aráyé yóó máá kò lákòbú yìn làá wò Ká tóó bù bòrọ okìnní Díá fún Òrúnmìlà Tií ọmọ aráyé ó máa kò lákòkí Ifá ìwọ ló ní kí w n ní ó máa bú mi Ẹnìkan ò bú mi báyìí rí Ifá Iwọ lọ ní kí w n ó máa bú mi Ifá ìwo ló ní kí w n ó máa kí mi nìkan ò kí mi báyìí rí Ifá Ìwọ lọ ní kí w n ó máa kí mi ó

29

Ela Ola, LLC

3333

Orí bara bi orí apesin Orí gogogo bi orí Elegbara A d’ífá fún rúnmìlà Ifá yò fi orí Èṣù Òdara ṣe tì Njé kínní rúnmìlà fi nṣe ayé rè lọ Orí Èṣù Òdara lọ rúnmìlà fi nṣe ayé rè lọ Orí Èṣù Òdara

30

Ela Ola, LLC

4444

Arutuu má njó ilé Agbo gboro ijá gbara jígi A d’ífá fún Abi Ti nṣe ọmọ ìyá lọjá Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Abi lóní aré Abi lọ laran Abi lọ lawó à nlù

31

Ela Ola, LLC

Ìwòrí Ogbé sáré wà o [aquí se usa el signo hermano del signo que salió en la consulta inicial]

Kó o wá gbè ẹbọ ọmọ ìyá rẹ lọ sóde òrun

A d’ífá fún Ogbè Ìwòrí [aquí se usa el signo que salió

en la consulta inicial]

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Kó í pé, kó í jiná

wá bá ní lá’rú fín ẹbọ

32

Ela Ola, LLC

1

Pa tì t rè babalawo Ìgbá Lọd ’ífá fún Ìgbá Ìgbá n f’omi ojú s’ògbérè iré Atorí ma nj gi babalawo awo Lọ dífá fún awo Àwọn n f’omi ojú s’ògbérè ire Léṣè lẹwí babalawo ilé Lọ dífá fún Ilé Ilé lohun ó fi odidi ẹniyán ṣó fẹj Apo Ìgbá babalawo ayé Lọ dífá fún ayé Ayé n f’omi ojú s’ògbérè iré Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Agun fọn ní yangede Ifá lóní ẹmi yò orí iré t mi Ójójumọ ní ewé iré nri rè Ela kíí gbè orí igi òkò tì Kò má nlá Ejinrin loní w n owá fi rè jinmi Ìwórì bogbè Ifa kòó wà gbemi dé lẹ iré

33

Ela Ola, LLC

2

Ka fọmọ ri ìgbá bò gbá Ka fọmọ ri awo bawo Ka fọmọ ri Ìwòrí ka ẹbọ ó m Ogbè má nlẹ Kọmọ Ogbè ó mán báà yan kú láí-láí A d’ífá fún rúnmìlà Iré gbogbo nlọ lodé Okokan kóyalé Ifá ní m ẹjẹ yè olú wéréwéré Ẹyẹ adaba wéré wéré wà ajá ka m dẹyẹ olu wéré wéré Ẹyẹ adaba wéré wéré wajé àgbádo m dẹyẹ olú wéré wéré Ki iré gbogbo o wéréwéré wà lèé mí

34

Ela Ola, LLC

3

Ka fìgbá bò ó Ka fi awo bò ó Lọd ’ífá fún Ìwòrí Ti nlẹ rèé borí Ogbè má nlẹ wuruwuru Ìwòrí wò lamperi Ìwòrí tóborí Ogbè má nlẹ wuruwuru

35

Ela Ola, LLC

4

Ìwòrí bogbè niji j Ìwòrí bogbè ní munu Ìwòrí bogbè lere òrò bi yò ọba ṣe ri Lọ dífá fún Oton p rò Ti nṣe ọmọ ọba laladé oyo Ìgbáti nsun pè ohun korí ré Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Njé otonporo dagi nú Iré ti délẹ kókó

36

Ela Ola, LLC

5 – RESOS

Se comienzan a rezar los Odus desde Èjí Ogbè hasta Òdí Méjì. Estos versos son un ejemplo, pero no es obligatorio que sean los versos que se tienen que rezar. No todos tienen que rezarse de forma obligaría tampoco, excepto. Eso sí, no se puede dejar de rezar el Odu que salió en la consulta.

37

Ela Ola, LLC

ÈjíÈjíÈjíÈjí OgbèOgbèOgbèOgbè

1111

Para la prosperidad

Ẹjí ẹjí ní mogbè Ẹmi kó gbè ọmọ ẹníkan m A d’ífá fún Alara Ẹyiti yíò níire méjì lọọjo Ifá dakún mojẹ kíi rè t mi ṣé mi reku reku oko Kíí jẹ kó rè kojá ọná

38

Ela Ola, LLC

2222

Para vencer a los enemigos

Awodí ní nfi iyé apa selu legan A d’ífá fún Akalàì papo Ti nṣe elenini barapetu Ẹni to bà nṣe elenini awa Abe Ifá amo ge w n idá olominrin mirin Kíí yun ní l run ti Akalàì papo ku aye Ifá dọfẹ more

39

Ela Ola, LLC

3333

Ota gbà;

Àrìra gbà;

Òkè ṣe rìbìtì ṣó rí s ns

A d’ífá fún rúnmìlà

Ifá ní sàwọn rọdé Ìlá ọba mowó

W n ní rúnmìlà ó j rè ní Ìlá ọba mowó

Ṣé gbogbón kó rúbo

Ó ṣì rúru ó sì ké rè délé

Ijó ní níjó ọta gbà

Àrìra gbà

Òkè ṣe rìbìtì ṣó rí s ns

A d’ífá fún rúnmìlà

Ifá ní sàwọn rọdé Ìlá ọba mowó

W n ní rúnmìlà ó j rè ní Ìlá ọba mowó

Adéẹké lọmọ Ifá

Èrè lọmọ Ọòní

rúnmìlà jẹ nmérè délé kokooko

40

Ela Ola, LLC

4444

Poolo Itákun

Itákun poolo

Bi kó bà ṣe ìr k

Amo ṣe orí o r

A d’ífá fún bàbá alaburo akòkò

Ìgbà ti n bè láàrin ọtá

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Ifá ní ẹ ó lé pa

Ẹ ó lẹ mú

Ẹ ó lẹ lẹlọ

Apa yin o ní o ka bàbá alaburo akòkò

41

Ela Ola, LLC

5555

Otoo-too-too

Otoo-too-too

Otooto láá ko’le

Ogbon táá fíí ko’le

Kó to eyi táá fíí gbe’nu u rè

A d’ífá fún rúnmìlà

Nijó tí Ajogun mẹrin ka w n mo’le l’Otu Ife

Ti Bàbá lẹ w n, lẹ w n

Ti w n ó lọ

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

wá bá ní jèbútú iré gbogbo

42

Ela Ola, LLC

6

Asure tètè bẹmọ lorí Lorúkọ lá npè Ifá Abiringnẹrẹ gbàmo ní gbọ Lorúkọ lá npè Èṣù À kó jàìnjàìn wolú Lorúkó lá npè Ẹyin ìyamí Ọṣaronga Tókúnrin tobínrin Lọbá npè Orí ẹmi nibi Ojú ní adiẹ nrò ti fún pa ẹyin rè Ki á w n otá à mi ó máá rojú pàrá w n

43

Ela Ola, LLC

OyékùnOyékùnOyékùnOyékùn MéjìMéjìMéjìMéjì

1

Para tener hijos y mucha popularidad

Oye ní nṣese là bò Loke w n ṣe bi ojumo A d’ífá fún feja Ti nṣe ọmọ enibu apoju

44

Ela Ola, LLC

2222

Para vencer a los enemigos y larga vida

Oye ní nṣeṣe là bò loke w n ṣebi mimo loju nm A d’ífá fún agogo Nlọ rẹẹ pade opa ní p p opa loun yíò pa agogo Kó lẹ pa agogo opa ní yíò kú agogo Asi gbele iro ní w n npa opa kole pa agogo Abinu ẹni kole pa kadara dá

45

Ela Ola, LLC

3333

Àgbá y kú y kú orí gbà Ìgbá owó Àgbá yekete kal Adifa fún olọmọ Awaiyé kú W n ní orúbo àìkú kó ṣe p pá Ogun òdun oní ó Okengbè làìkú gbòní gbòní Gbòní gbòní nítòkè Òkè òkè gbòní gbòní Ìgbá òdun oní ó Okenbe làìkú gbòní gbòní Gbòní gbòní nítòkè Òkè òkè gbòní gbòní Ìgbá gbogbo okenbe làìkú gbòní gbòní Gbòní gbòní nítòkè Òkè òkè gbòní gbòní

46

Ela Ola, LLC

ÌwòrìÌwòrìÌwòrìÌwòrì MéjìMéjìMéjìMéjì

1

Para que los deseos se cumplan

Ekin ewo Ekeji ewo Ìgbátí ewo dí méjì lodi otito Ìgbá ewo dí méjì lodi ododo A d’ífá fún Olofin ajiwoye akoko Ewo kán Ewo kán ẹyin Ti olófin nwò ajasi iberere

47

Ela Ola, LLC

2222

Para que todo resulte bien sin dificultades

Ogodo owu logboke odo Lọfẹyin kékéké sì oloko A d’ífá fún rúnmìlà B’abá yíò m ṣe oun gbogbo bi idan ire aje Ní oun ó ní bi idan ní kose Ire gbogbo bi idan bi idan awo rere Ní ogodo owu tó ó Gboke odo tófẹyin kékéké sì oloko

48

Ela Ola, LLC

OdíOdíOdíOdí MéjìMéjìMéjìMéjì

1

Para tener fertilidad e hijos

Oodu ní kó yì gbirigbiri Jana a d’ífá fún w n nidi kún rin Abú fún w n nidi bi nrin w n jí ekun Ọmọ ní w n nsún ìgbá idi dí méjì ní ire Ọmọ wade ìgbá idi dí méjì lawa nbimọ

49

Ela Ola, LLC

2222

Para tener suerte, estabilidad, buenas

oportunidades y hacer dinero

Idi mejéjè loto oluware joko A d’ífá fún Oníbode Ajengbede jengbege odun Ẹyi ti yọ gbè ibi kán jifá Yíò gbè ibi kán ire gbogbo Oju kán oju kán ti m joko sílè gbè ní ire gbogbo Yíò m wà bami lẹ gbè

50

Ela Ola, LLC

3333

Agbinkingbinkin inu ẹrin Nkán jobojobo l run ẹfon Alamo-ẹdẹ bi kó bà bò kíí’fe A d’ífá fún Mayami Tíí sọmọ odú meréèrin Ìgbatí ó nt run bò walè aye Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Eji-Ogbe o níí fi Mayami tire fún Ikú pa Oyeku-Meji o níí fi Mayami tire fún Ikú pa Iwori-Meji o níí fi Mayami tire fún Ikú pa Odi-Meji o níí fi Mayami tire fún Ikú pa Gbogbo iworo-nsope

51

Ela Ola, LLC

ÌkáÌkáÌkáÌká MéjìMéjìMéjìMéjì

Bí Ìká bá kari ẹbọ Kí Ìretè ọmọ iya rè ó tèé

1

Ká gbáa níbùú Ká gbáa lóòlóò A d’ífá fún Áàs Ti nlọ ogun Ilurin Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Táàs bà lu’rin tán Ara a rè a sì le kokooko

52

Ela Ola, LLC

2

Para salir victorioso en todo

Ẹni kí Ika Ẹkeji Ika A d’ífá fún Ika aye Abú fún t run Ika aye lá npè ọbá Ika run lá npè Sàngó Kó í p , kó í jiná wá bá ní lá rú ìṣégun

53

Ela Ola, LLC

3333

Para tener protección y evitar accidentes de

cualquier forma y protección

Agba fáá nibu agba fáá A d’ífá fún walami Nlọ rẹẹ bà w n tún iwa okose M m jẹkí oko odá Walami M m jẹkí oko odá

54

Ela Ola, LLC

ÌrètèÌrètèÌrètèÌrètè MéjìMéjìMéjìMéjì

1111

Iwo ote ẹmi ote Otedi méjì odi ooto Ote méjì méjì odi Ododo a d’ífá fún Bàbá Alórí rere m lẹṣẹ rere Ifá jẹjí nlọrí rere Kí nsi lẹṣẹ rere Irere kó lórí agberule orí rere niti irere

55

Ela Ola, LLC

2222

Para que todas las cosas buenas se acerquen a la persona

Àkùkò bàbá mi itá bi itá Àkùkò bàbá mi irele bi irele Àkùkò bàbá mi lofi apapa idi nalé r here han hun A d’ífá fún yẹẹmi otoro ẹfon iyẹ Mẹṣẹ ilé iddo nsúnkun poun kóní ire gbogbo Ire aye tolo ti kó ti dé ẹedẹ lóní kodé Owinrin winrin ẹdẹ lóní kọdé

56

Ela Ola, LLC

3

Èèrùn-ùn yán ni ìfofò kété Díá fún Atóka Tií ṣe ìkàrì Olódùmarè Mo di Ìlàrí ikin Èmi ò r’oko Atòka di Ìlàri Olódùmarè Mo di Ìlàrí ikin Èmi ò r’oko Atòka di Ìlàri Olódùmarè

57

Ela Ola, LLC

4

Ọkọ rè Aya rè Díá fún kéké jègbè Ti yóó fé’bìnrin ikú tán Ti yóó fobì méfà tan Èrò Ìpo Èrò Òfà wá bá ní l’árùúṣé ogun Àgbàgbè nifá ó gbà laya

58

Ela Ola, LLC

wònrínwònrínwònrínwònrín OgbèOgbèOgbèOgbè

1

Èṣú peerejegede

Egba peerejegede

Awo ní ṣo

Awo ní jẹgẹ

A d’ífá fún Oloogesa

Ti okoro l j t yin t’ọmọ

j awa koro à ó kuman

Atij ìgbá ewé jò gb

j awo á sì koro

59

Ela Ola, LLC

2222

Koko ẹtí aṣo abeti ṣẹṣẹ A d’ífá fún yerepe ogele Yíò gbà arare Yíò sì gbà igi Oko igi ti yerepe Bà dimọ ọbọ lówó asewe Ọbọ lówó aṣegi Osan pọn ganrin ganrin Kẹni m m tó Yerepe ẹẹyan tó náá mi egbe Ní yíò ná oluware Yerepe m m dé abaṣo jin gbi ní

60

Ela Ola, LLC

3

wónrín Ṣogbè, awo ayé wónrín Ṣogbè, awo òdé òrun A d’ífá fún àgan ìgbàl Ti ọmọ aráyé nf ìdí rè é rí Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Òdọmọdé kíí rídíí àgan Igi ìgbàlè lẹ rí

61

Ela Ola, LLC

4

Olú kínndínrin

Àsà kínndínrin

A d’ífá fún wónrín

Ti n ṣawo lọ àpá Òkun

Tòun Ìlà Méjì

Ó n l ó gbágún Okún

Ó n l ó gbágún Ọlógìnnìngìnnì, aṣọ odé walé

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Olú kínndínrin

Èṣù wónrín-Ṣogbè p’ajé wá

Olú kínndínrin

Èṣù wónrín-Ṣogbè p’aaya wá

Olú kínndínrin

Èṣù wónrín-Ṣogbè p’ọmọ wá

Olú kínndínrin

Èṣù wónrín-Ṣogbè p’ogbó wá

Olú kínndínrin

Èṣù wónrín-Ṣogbè p’re gbogbo wá

62

Ela Ola, LLC

5555

w nrín Ṣogbé, ooro tệệrawo inú igbó A d'ífá fún ènìyàn Èyí tí Èşù dàrà nwtèll'hìn Mo rú'b y 'le Mo rú'b y oko Elèṣù padà l'ẹhìn ò mio ó, elèṣù

63

Ela Ola, LLC

ObaraObaraObaraObara OgbèOgbèOgbèOgbè

Aworan ó loju ekun

A d’ífá fún Latoose ọmọ Arole

Sigidi o yirun pada

A d’ífá fún Siinrinkusin ọmọ Osun

Ọpẹ eluju abimo gudugudu

A d’ífá fún Soorowo ọmọ iyami aje

Oju wonu ibu ó jokoo

A d’ífá fún karubo kó dá ọmọ Elegbara

Njẹ báá bà feku rúbo jẹ kó móò fin

Siinrinkusin

Ifá jẹbọ í dá felẹbọ Siin rinkusin Báá bàfeja rúbo jẹ kó móò fin

Siinrinkusin

Ifá jẹbọ í dá felẹbọ

Siinrinkusin

Báá bàfeja rúbo jẹ kó móò fin

Siinrinkusin

Ifá jẹbọ í dá felẹbọ

Siinrinkusin

64

Ela Ola, LLC

ObaraObaraObaraObara OgbèOgbèOgbèOgbè

2

Ikú yòó

Àrùn yòó

Irunbi níí gbè bàá run fìofìo

A d’ífá fún w n lóde ido

Níjó ajogun ká w n mólé pitpiti

Ẹbọ ní w n ní ki w n wáá ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Ikú ilé yìí kó dẹrù

Ko máa lọ ó wirìwìrì

Àrùn ilé yìí kó dẹrù

Ko máa lọ ó

wirìwìrì

65

Ela Ola, LLC

Ẹjó ilé yìí kó dẹrù

Ko máa lọ ó

wirìwìrì

À ó finá Ifá wì w n lára ó

wirìwìrì

Òfò ilé yìí kó dẹrú

Ko máa lọ ó

wirìwìrì

À ó finá Ifá wì w n lára ó

wirìwìrì

66

Ela Ola, LLC

3333

Apópó ibìkan ò so ní poro oko

A d’ífá fún Òòṣànlá ṣèèmàgbò

Ti yóó pa ikú lọpàá Òjé

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Njé Òòṣànlá ṣèèmàgbò

Oun lọ pa ikú lọ pàá Òjé

Ọba Ijiwó ló pa Ikú awo ní gbangba

67

Ela Ola, LLC

4444

Itawéréré níí s'awo w n nilé aládó Òjíjí mọbá awo ọdé iwonràn Ọp sàgá Tíí s'awo w n lọdọ àwọn èrìnmògún Lọdọ àwọn èrìnmògún Ní w n ti n mọpé ṣe ibọ yanrayanra Bi ojúmó bá m iwo a lá gbòò Bí ojúmó bà m iwo a lá gboro Ifá ní ẹbi kíí pa gúnnugún dálé èèwo alé àná nkó Ifá fí wà owo lọ fún níí lọná oko eewo alé àná nkó Ifá ó fí wà awó lọ fún mi l'ojúdé fóó fóó fóó Ti nbè lọdé ilé yíí Obara bogbe ó ebi má npà ọmọ awo

68

Ela Ola, LLC

4444

Òbàrá Ògbe iyere moye Adifa fún eko Ti nlọre gbire lowo bàbá rè Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Èrò Ìpo Èrò Òfà Njẹ ẹ ti á sú fún eko Keko kó mú n yr run Kó í p , kó í jiná wá bá ní lá’rú fín ẹbọ

69

Ela Ola, LLC

OgundaOgundaOgundaOgunda SorireSorireSorireSorire (Ogunda(Ogunda(Ogunda(Ogunda Ogbè)Ogbè)Ogbè)Ogbè)

Para alejar la muerte y las enfermedades con la asistencia de Ogun

1111

Afi ikú pin A d’ífá fún fowu Nkó ọmọ rè lọ sì Ilagbede nitorí ikú

Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Afí ikú pin nigba yi awa kó kumọ Adiẹ popi afi ikupin ikú pin Ikú pin ní Alagbede ṣe ogun

70

Ela Ola, LLC

2222

Para que los enemigos dejen de desear cosas malas

Enu w n lejí

Enu w n leta

A d’ífá fún alapinni Iyofori

Ti nṣe ọmọ abegun jẹun

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Awo eleran apinni enu

W n eleran apinni lá ẹ lá ẹ

71

Ela Ola, LLC

3333

Igara ní n dasa A d’ífá fún Isimola Ti n ṣe iya Ẹbọ lalade run Ìgbá ti ọmọ Araye n gbero buruku Si ẹbọ ọmọ rè nilé aye

Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Njé Isimola ó dé Ṣẹbi iwo ní iya ẹbọ Tètè surè wá Kowá gbè ẹbọ lọ Surè wà ó wà gbà ẹbọ isimola

72

Ela Ola, LLC

4444

Tòtò ní òmu igi lóké A d’ífá fún ọba Ti nlọ sókó àlerò l dun Ẹbọ ní w n ní ki w n wáá ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

M roko Mo j gburu ajé lóko Ọba tó làlààlà Ti w n npè ní Obàtàlà Ọba tóta ilá tó là làlààlà Ní w n npè ní Obàlálà Ọba o má ti là làlààlà

73

Ela Ola, LLC

5555

Àkètè ó lẹ lèlèlè Kọmọn lẹ dá orí dé

A d’ífá fún Ògundá ti yìó làlàlà

Ti yìó lọ eti odo

Yìó bò ogbè monlè tunrutu Ẹbọ ní w n ní k ṣe

O gbẹbọ nibe ó rubo

Njé mogbè dé ó genge M gbefa olá wole dé Èrò Ìpo Èrò Òfà Iyẹmọja láá bò nibe tiba binu

74

Ela Ola, LLC

ÌwòrìÌwòrìÌwòrìÌwòrì fúnfúnfúnfún

Para viajar con suerte y tener prosperidad

1111

Ìwòrì towofún towofún Ìwòrì tẹṣẹfún tẹṣẹfún Ìwòrì ti ara mejeji fún ṣerú Serú a d’ífá fún Agbado gogo nlọkọ alero l dun Kíní Agbado amubo? Ìgbá aṣo nlá gbado amubo Ìgbá ọmọ nlá gbabo amubo Kí ní Agbado amubo ire gbogbo Ní Agbado amubo ire gbogbo

75

Ela Ola, LLC

2222

Àgbáàrin lọ fojú iràn wá pè

A d’ífá fún Erelu

Tíí ṣe yèyé wọn

A d’ífá fún wọn

W n ní ó wá pabi dá

Kó wá ṣó ibi dire

Ìgbá tẹẹ logun oorí

Tẹẹ ó lọ gbòn àkàrà

Ohùn ní wọn wá pabi dá

Tó sì ṣó ibi diré

Njé wọn pabi dá ṣobi diré

76

Ela Ola, LLC

3333

Ìwórí tọwọfun tọwọfun Ìwórí tẹsẹfun tẹsẹfun Ìwórí ti ara méjẹjí fún ṣe rù A d’ífá fún ọpe elejú Ti n f’omi ojú s’ògbérè iré gbogbo Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Igi ka nbè lọdán Gbogbo aráré owó ní fin ṣo

77

Ela Ola, LLC

kánrànkánrànkánrànkánràn OyekúOyekúOyekúOyekú

Para no caer en deudas

1111

T kí ti awo ọmọdé T é kááta awo agbalagba Oku owo kán kó hu Ẹyi ó yẹ bẹẹ ní kolé hu Ẹji ó yẹ m a d’ífá fún bàbá Kuku ṣebọ k run ọmọ awa M ṣẹbọ k run ọmọ more

78

Ela Ola, LLC

2222

Para que los hijos tengan buena salud

Yangí oju oná Abotí kugu A d’ífá fún fọmọ lokánran Tó ti nyan kú ọmọ olokánran Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Ẹti yan kú nm ó apari isu kíí jọbá

79

Ela Ola, LLC

3333

Abẹ kèkèrè aboju rahu rahu

Àdá nlá ní nṣe aya kótó pọ pa´lé

Ṣonṣo idá ní oṣe gbà ri

A d’ífá fún w n ní ilú Ajankorodugbe

W n ti nt ru èrù w n odá

W n wà tó Olódùmarè lọ

Olódùmarè ní kí lọdé t fi rúbo ti ofín

Tiẹ t ru ti odá

Olódùmarè ní kí w n olọrèéba

rúnmìlà lọdé Isaluaye

Oní tọba ti rubo fún yin ẹbọ yin a fin

Èrù yin ó sì dá

O dá fa fún w n oní w n ó rúbo

W n wá rubo ẹbọ w n sì gbà

W n ní àwọn rúbo ẹbọ dá náá o

Ajankorodugbe

Iré ajé wo’lé towá o

Ajankorodugbe

Iré gbogbo wo’lé towá o

Ajankorodugbe

80

Ela Ola, LLC

OgúndaOgúndaOgúndaOgúnda OsáOsáOsáOsá

1

Para alejar todas las fuerzas negativas y la muerte

Tan pepe ní fi otu gbugbu sele A d’ífá fún olófin Ẹyí ti yotá ikú atarun sì oja Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Amuku amu arun Amu gbogbo ibi afi ta soja

81

Ela Ola, LLC

2222

Ó ṣoju kulukulu bì ká gbè jọ

Ó ṣenu waji waji bì pè kó bú ní jẹ

A d’ífá fún bàbá arugbo (Obátalá)

Ó nlọ katare akala l dun

Bàbá arugbo reru kán lóní

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Ẹbọ oní ní

A bí oogun lọ nsa

82

Ela Ola, LLC

3333

Para evitar problemas de justicia

Ògunda m n sa Ijá ranhin m n sòjò Ogun ti a ó sá Ti a ko sòjò Ohun ni a pè ni ogun ajamolu A d’ífá fún w n ni ilú aimese Nibi w n ti n gbè n gbè gbogbo ẹyẹ dé A d’ífá fún ogun Ti n sáwo lo oná to jin gbungbun bi ojo Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ogun nikan ni bè lẹyin ti n rubo Njé ẹyin o ri ogun to wà ṣe Ẹyin o ri ogun to wà dí Ẹyin o ri ogun to wad a gbogbo ẹyẹ dá silé Ewé tude lóní kide tawa o tu Ewé orínjin lóní ki w n o forí jin awo

83

Ela Ola, LLC

4444

Ògundá Sa awo orí otá A d’ífá fún rúnmìlà W n ní kí bàbá rúbo sì Lá ikú ara rè Bàbá gbebo ó rúbo Ope lọ pè Ògundá tó sáa lẹ fún Ope lọ pè Ògundá tó sáa lọsun

84

Ela Ola, LLC

5555

Para vencer a los enemigos

Odún sáré titi w n ó bà odún

Osu rin rin rin w n ó kó osu loná

Ọmọ kéré kéré kéré sun ibenbe ojú béè ní w n o ri

ihaho Olorun

A d’ífá fún rúnmìlà

Bàbá n lọ rèé bà ogun tè oníré nifá

Ẹbọ ní w n ní kó ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Njé ogun dé m nlá ju were

Ó bà bowo fún awo lojo kan ijá

Nijó ogun

Nijó òde

Ogun dé m nlá ju were

Ó bà bowo fún awo kan ijá

85

Ela Ola, LLC

ÒtùrúpọnÒtùrúpọnÒtùrúpọnÒtùrúpọn kànránkànránkànránkànrán

1

Para alejar los miedos

Otutu npọkànrán Ẹbọ dí ẹbọre Otutu kí pọkànrán Sìdi Ogundere Ó lọ rẹẹ wò sinú oko Lagba wò pèlú A d’ífá fún Kanna kanna Olorí Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Ẹṣọ w n ní sì nṣe akin? Oleyin kó mọpẹ Tojo ní ntó tóò

86

Ela Ola, LLC

2222

Ikin wéré wéré Ikin Otoluaye awodí Loun iyere mofo awo otun ilé Olosi aga agbon Lú keke mofo awo alado ewi Lọ d’ífá fún Alado Ọmọ arara ojo Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Nṣebọ bẹẹ ní kó d run nṣe tutu bẹẹ Ní ké gbà ẹyí ti aru lóní yi Ifin lóní kó fin Egbesi gbesi igi oko Ifá mọjé kẹbọ náá osun ná Sinkún lẹkún nmu eran Egbesi gbesi igi oko Ifá mọjé kẹbọ náá osun ná Eran ti oka bà fẹnu ṣo enu oka loun kusi Egbesi gbesi igi oko Ifá mọjé kẹbọ náá osun ná osunna

87

Ela Ola, LLC

ṣéṣéṣéṣé ÌwòríÌwòríÌwòríÌwòrí

1111

ṣé awo ìwòrì na awo A d’ífá fún lube Abú fún lube lube sọdé operin

Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Awo rere ní ṣé Ìwòrí Lube sọdé opefon Awo rere lọ ṣé Ìwòrí

88

Ela Ola, LLC

2222

Para que el mensaje del ẹbọ llegue bien al cielo

Bọmọ bà m iṣe jẹ amoje oniṣe Bọmọ kosi mọjẹ amo jẹ oluṣe oniṣe loyeni Oluṣe kó yeni Ogbogba Leru jiyo lọbe oun Olowo rè A d’ífá fún Ayasun Ẹyí ti ṣe ojiṣe Olodumare Jé ṣe ẹbọ tóní si rere iwo Ayasun ọbá m m jí ṣe ẹbọ tó ní si rere

89

Ela Ola, LLC

3

Alangajiga A d’ífá fún sé Alaba owo Abú fún Ìwòrì Alaba ọká Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo ṣé nlówó Ìwòrì nlá gbà Alangajiga

90

Ela Ola, LLC

ṣéṣéṣéṣé ÌrètèÌrètèÌrètèÌrètè

1

Para tener larga vida y prosperidad

ṣé t t Ìrètè awo eku

A d’ífá fún efku

ṣé t t Ìrètè awo eja

A d’ífá fún Eja

ṣé t t Ìrètè awo Eran

A d’ífá fún Eran

ṣé t t Ìrètè awo amure odagba

A d’ífá fún amure odagba

Ẹbọ ẹmi rè ní w n ṣọpẹ Kó wà ṣe ikú ṣẹbi ere ọpẹ ku Ọpẹja ikú pẹyẹ ọperan ó wà kú amure nilé Orí ogbo láá bà amure kí kú ọmọ pa amure odagba

Kó m ṣẹbi feriwo

91

Ela Ola, LLC

2222

Para no caer en las trampas que la gente le hace

Jin sì koto Jin sì gegele Ẹni tó jin sì koto Lotí kó ara yóò kú logbo A d’ífá fún fọse Ẹyi ti yíò bi Ìrètè sílè aje ṣé nlobi îrètè sílè aje Ẹni ẹni ká sa wà bini sọlá

92

Ela Ola, LLC

3

ṣé tètè Ìrètè tètè Awo esinsin lọdifá fún esinsin Nìgbá ti nt run bowa sayé Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Njé bi esinsin baji À rawo rasé sì Olóhun ọbá

93

Ela Ola, LLC

ÌròsùnÌròsùnÌròsùnÌròsùn ÌrètèÌrètèÌrètèÌrètè

1111

Ekanna Winwinwin awo ẹmi

A d’ífá fún femi ẹmi

Nt run bo walé aye yíò sì wà jẹ

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Olọlá ninu ara koun ọmọ ṣe ẹmi

Oun kó gbogbo ṣe ẹmi

Ẹmi sáá ní olọja ninu ara

94

Ela Ola, LLC

2222

Ígbá ti kó gbò niṣe ọbẹ ta mu

A d’ífá fún gberu

Ti yíò sáwo lá nilé aye

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Modi alaba modi

Alase awo ní gberu sẹẹ lá awo

95

Ela Ola, LLC

3

Ìrosùn Òpinmì

A bú sì tun yin

A d’ífá fún Ojo

Ojo tíí ṣoko Agbado

Enu ti w n fi bu Awo

W n ó sàì tun fi yin ní lẹyin wà

Njẹ a bu sí tun yin

Ojo loko Agbado

A bú sì tun yin

96

Ela Ola, LLC

Para cerrar el ebo

Rezos de ṣéṣéṣéṣé ÒtùraÒtùraÒtùraÒtùra

1111

Òsétùrá gbà à tete Ajókànse lẹkún

A d’ífá fún akólóló

Ti n gbèbo lọ

Ti gbè ẹbọ ròde run

Aní ohun lohun t t dé ibi yìí

Ẹbọ ti

ní kà t t dé ọdé run

97

Ela Ola, LLC

2222

Òsétùrá gbà a t t Ajikansee lekun A d’ífá fún Akilolo Ti n gbebo rọdé run A pè ẹmi ni m m m m kó kó kó dẹbi yíí Ẹbọ toun ní kó t t t t t dá Ẹbọ toun ní kó t t t t t fin Riru ẹbọ Eerú atukèsù Aye yẹ wà tuturu

98

Ela Ola, LLC

3333

Pénpé lẹs tùbú là agẹmọ ní ò tó gèlè Ìbá tó gèlé Nbá mú relé l wé A d’ífá fún Awúrelà Ti n ṣawo ròde Ìj bú Àpèjin làá pe Oníy Àpèlà, àpèlà làá pe Awúrelà Ní Ij sé Awúrelà awo iré ní o

99

Ela Ola, LLC

4444

sétùtá awo Alara A d’ífá fún Alara Ọmọ Amurin kan dàgbà agogo ìdé sétero awo Àjèrọ A d’ífá fún Àjèrọ Ọmọ Ogbolu k rò ìjàjàlé Aj ṣe Oganna Imanse Adifa fún sétere ọmọ buba oye sé k j sé k sé ngbẹ bò r run wá yì Ìgbá ní olú odìdé Okiki ẹbọ á ṣí kàn kún Awa t t ru kó t t dá Ké bò wá ó t t dele Olódùmarè

100

Ela Ola, LLC

5

Pàákàrà wóó- wóó- wóó awo ìdí Èṣù

A d’ífá fún sé T r

Ti n gbebọ ilèé ròde run Ẹni í fówó ó ní

Ẹ wáá rán ‘fá nṣé

sé ngbebọ ròde run Bi ẹ nísé é rán Eni í fáya á ní

Ẹ wá rán ‘fá nṣé

sé ngbebọ ròde run Bi ẹ nísé é rán

Eni í f’ọmọ ó ní á ní

Ẹ wá rán ‘fá nṣé

sé ngbebọ ròde run Bi ẹ nísé é rán Eni í fère ẹ ní

Ẹ wáá rán ‘fánṣé

sé ngbebọ ròde run

Bi ẹ nísé é rán

101

Ela Ola, LLC

5555

Tóó n Olúwo

Tùféè ní Okúgbònà

Às al àse ààrò

A d’ífá fún arúgbó aborí ko-ko-ko

Níjó ti n lọ ọja Èjìgbòmẹkun

Kò tà, kò rà, ó mú ìwo àṣ rè l w

W n ní ó lósó

Ó ní ohun ò lósò

W n ní ó lájèé

W n ní gbogbo ohun tó bá wí

Ó ti ṣe máa n ṣe?

Ó ní ohun ò lósò

Ohun awo l r

Ohun awo làrẹ

102

Ela Ola, LLC

6666

Àwù lù wú lù manye

Àwù lù wú lù manye

Onìgbánso ní nfi ìgbá ire gbè jẹun

A d’ífá fún ewi awo aye

A d’ífá fún Egba awo òde orun

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Ire balè njó nilé

Esi njó loko

Babalawo lewi aye

rúnmìlà lẹ gbà ti nbè lòde run

Ẹyi owu ewi ayé owi

Lẹ gbà run ó gbà

Ẹyi owuwa awi

Irúnmọle egbáá siwa lenu

103

Ela Ola, LLC

7777

Tete ní tete da A d’ífá fún s teere Ti n gbẹbọ r de run Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Awa la tete ru Ẹbọ wà ní yo tete da Ẹbọ wà tetedele Olódùmarè sin gbogbo w n Gbogbo rè ní ifá gbo Gbogbo rè lọ gbalo s awurela ifá tigbo

104

Ela Ola, LLC

8888

Abẹ dé awo okira A d’ífá fún Okira Nijó tó nfọ jojumo sowo Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Aseti Abede ọdé Olódùmarè M jẹkí nṣe Aseti laye

105

Ela Ola, LLC

9999

Apadi ìgbá lẹro losoju beli beli Bi ẹni pè kó gbe ri A d’ífá fún yẹẹmi Osoronga Ti ṣe iya awa Awo ṣo ilé Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo M júbà ẹyin Ìyàmi Oṣoronga M júbà ẹyin Ìyàmi Oṣoronga M júbà

106

Ela Ola, LLC

10

Para tener el poder completo del Ase

Tóó ní toluwo

Tufee nítí ojugbona

Aṣe ale adé awuro babalawo augbo

A d’ífá fún Arugbo

Nlọ sì ọjá ojugbo mẹkún

Kotá kora ogba iwo

Aṣe rè mu lowo girigiri w n ní oní

Oṣo oloun kó loṣo

W n ní oní aje Oloun koí aje

W n ní oṣe nṣoro tó nṣe looro

Oní ẹyin kó m pè oun awo loso oun

Awo loro oun awo laṣe

Gbogbo nkán tó m

Nṣo kó m ṣe sì rere

107

Ela Ola, LLC

11111111

Agbere gede ajuba aboju gbere ngebe

A d’ífá fún Osun Sengese Oloya Iyun ó ngbè ibada ó ngbe ìkòkò Nbá ẹbọ gbogbo Irunmole yóò kú jẹ Ta lóní kẹbọ ọmọdá fẹlẹbọ Agbere gede ajuba ajuba náá Aboju gberen gede Osun Sengese A pè ó ṣẹbọ Agbere gede ajuba Ajuba aboju Agbere gede Yẹyẹ mi otoro ẹfon ẹjẹ kẹbọ Odá fẹlẹbọ omi Ota ó Edan ó Aagbo Irunmole ó

108

Ela Ola, LLC

Despues de rezar ṣéṣéṣéṣé ÒtùráÒtùráÒtùráÒtùrá se pregunta a Ifá:

1- Si los animales son un regalo para el babalawo así:

"Awo Yelerun"

Si dice que no, se pregunta:

"Ẹjẹ balè" - Se recomienda siempre darle algo a Esu.

Mientras se le da sangre se reza:

Canto para la sangre

Ajalu toro toro

109

Ela Ola, LLC

Coro:

Ẹjẹ balé ibi Adero Arubi ní ṣerù ita

Coro:

Ẹjẹ balé ibi Adero Alagbede kó ijiṣe ogun

Coro:

Ẹjẹ balé ibi Adero Apọn omi ta kó ji ṣe osun

Coro:

Ẹjẹ balé ibi Adero Esinsin tó nbà oderin yíò mu ẹjẹ yóò

Coro:

Ẹjẹ balé ibi Adero Ẹniyán tó nbà àwọn ri yíò ri edo kí eran jẹ

110

Ela Ola, LLC

Coro:

Ẹjẹ balé ibi Adero Ẹjẹ balé ta ṣọọ ṣọọ

Coro:

Ẹjẹ balé ibi Adero Ẹjẹ balé tasi Ifá lara

Se cogen los caracoles y se le ponen en la frente al cliente. Se reza:

Kókó oun eepe ní agbe Fi ledí kán ede owo ní babalawo Fi ntún orí w n ṣe orí ti aba Fi owo wè agbo ato

111

Ela Ola, LLC

Se cogen los caracoles y el dinero y se colocan en la estera y se reza:

Okiki lọ gbo ó kíí kí legbe Adífá fún ilé Abu fún ikin Nkán ta fún ilé kilé Ogba fún ikin

112

Ela Ola, LLC

Se le pregunta a Ifa los caracoles que se incluyen en el sacrificio. Después de la respuesta, se le da a la persona para que rece sobre los caracoles y el babalawo reza el siguiente:

Ògbe Òtúrùpón

Ògbe tọmọ pọn

Ògbe sún m si

Bọmọ bà nsúnkun

Iyá láá kéé sì

A d’ífá fún Agan o ribi ile ife

Ẹyi tí nṣofon gbaja gbaja lórí ẹbọ

W n ní ẹ ẹ m pè lẹnu ẹlẹbọ

N lẹbọ gbee fin

Lenu ẹlẹbọ

Lẹbọ ó gbee dá

113

Ela Ola, LLC

La persona pone los caracoles en el ebo, se le echa aceite de palma y finalmente iyerosun mientras va rezando:

Ó Owonrin Ogbe ó wà tete ó

Ó Obara Ogbe ó wà tete ó

Ó Ogunda Ogbe ó wà tete ó

Ó Ìròsùn Ìrète ó wà tete ó

Ó Ose Otura ó wà tete ó

Ó Okanran Osa ó wà tete ó

114

Ela Ola, LLC

Se marca Okaran Osa y se le pregunta a Ifá:

"Sì bilari"

Si Ifa dice que si, se reza Okaran Osa:

Ká mú gégé lu gégé Awo ilé àlá koókó Igbin otera niná yiyá Awodi ní ó pa sáá gbádie rà Oluwo meta ìrúkèrè méfa Ogun ti a fi esín si Ti a ó léé sì Ogun ti a fi oko ja Ti a ó leja Kinni edú fi tu m ore Irukere i´edú fi lúmo rè Tú m ikú Tú m arun Tú m ejó Tú m ofo

115

Ela Ola, LLC

1

Para tener buena conducta

Okànràn Osa ó Eleru ara ohun ohun Nṣe igun nugun Igun kó yana Ara nṣe Akalamogbo bẹẹ ní koya o run Adiẹ kati kati odí ó njẹ A d’ífá fún rúnmìlà Bàbá nlọ rẹẹ gbè iwa níyawo iwa Lobi ṣowo iwa lọpọn ṣeyin Ewa wò ọmọ iwa were rúnmìlà fún ní iwa rere wù

116

Ela Ola, LLC

2222

Ìyá ìgbá ó lẹ m on wè Kọmọ rè ó béri lọ A d’ífá fún Tèntère ọpẹ Ti nlo réé gbè ẹlẹbọ léké Njé bikú nbò wà Kó gbè ẹlẹbọ léké Tèntètè ọpẹ gbè ẹlẹbọ léké Bi arun nbò wá Kó gbè ẹlẹbọ léké tèntèrè ọpẹ Gbè ẹlẹbọ léké Gbogbo ibi ti nbò wá Ko gbè ẹlẹbọ léké tèntèrè ọpẹ gbè ẹlẹbọ léké

117

Ela Ola, LLC

3

Para alcanzar grandes éxitos en la vida

Okán sáá A d’ífá fún Asa Nlọ sì oko iwa jẹ oko Asa Kíí balé kó sàwon Ti awodi kíi balé kó pọfọ Kí ọmọ mu amubo

118

Ela Ola, LLC

4

Para tener prosperidad y larga vida

Okán sale sakuta

A d’ífá fún Oko

Ti nṣe ọmọ oniré sa nbè Okán sale sakuta

A d’ífá fún Aso

Ti nṣe ọmọ oniré sa nbè Okán sale sakuta

A d’ífá fún Ilé

Ti nṣe ọmọ oniré sa nbè Àì gbo kú oko àìgboku ilé Àìgboku aso afi bò gbọ

119

Ela Ola, LLC

5

Para tener la victoria sobre los enemigos

Òkànràn sáá Awo ẹjọ ló difá fẹjo Ejo nbè laárin otá Njé itakun Iẹjo Ti o bá si ori A bá mẹjo di igi Itakun Iẹjo Ki orí gbè wà nija

120

Ela Ola, LLC

6666

kànràn sá o Gbà á tètè tètè kànràn sá níí pari àrúdà ẹbọ kànràn sá kíí bà ẹbọ àìmọda

En este momento se le entrega el ebo a la persona para que diga lo más fuerte posible:

"To,"To,"To,"To, To,To,To,To, To"To"To"To"

Esto lo reza primero el babalawo y después el cliente. Coge la calabaza y toca la cabeza, el hombro derecho y el izquierdo después de haber pasado la calabaza alrededor de la cabeza. Finalmente se toca el pecho una sola vez y se pide que se abra las manos para sujetar la calabaza.

121

Ela Ola, LLC

Se recita entonces .

Okúta pete Alamoseje Babalawo owo A d’ífá fún fowo Ọmọ abimọ marun jere ararun Ọmọ loju owo kí toju owo kú Ọmọ loju ẹṣẹ kíí toju ẹṣẹ r run Ọpẹlọpẹ okútá Alamoṣeje

En este momento el ebo se pone en el tablero y se pregunta: Otan? Si dice que sí, se pregunta el destino del sacrificio:

• Èsù: que puede ser cualquier Oríta, cruces de

caminos o conjunción en forma de T (Òtún Èsù), el altar de Èsù, Agbèrù o Wòròkó.

• Ojú ònà (borde de la carretera)

• Odò (río)

• Ojú ilé (patio delantero)

122

Ela Ola, LLC

• Èyìnkùlé ( patio trasero)

• Iboji (cementerio, ile Oya)

• Balùwè (cuarto de baño)

• Esè Òkè (junto a una montaña)

Después de haber llevado el ebo hacia donde ha sido indicado, la persona regresa y pone sus manos en el tablero y se reza:

ÌkáÌkáÌkáÌká ÒwónrínÒwónrínÒwónrínÒwónrín Wáá mi babalawo akika Lọdifafún akika Ti nlọ rẹẹ dipo ọpẹ mu Ó ó bà dọpẹmu kóó rí wà Akika ó dọpẹmu kóó rí wà Akika

123

Ela Ola, LLC

Entonces, se echa el polvo de ìyèròsùn encima y se reza en silencio por un rato ya que se acabó el ẹbọ. Después se lleva a donde se ha dicho y se termino el ebo.

OkànrànOkànrànOkànrànOkànràn OsaOsaOsaOsa Iyé Òkànrán sá í í bẹbọ ó m fiin Iyé Òkànrán sá í í bẹbọ àì m

Si dice que no, se le pregunta que es lo que desea:

"agua, aguardiente, miel, etc."

Se ponen dentro de la calabaza la cantidad requerida de caracoles y si lo solicita, se le echa aceite de palma, agua, sangre, miel de abeja, etc.

124

Ela Ola, LLC

Rezo para el agua Para tener una vida serena y tranquila

Ilé tutu oná A d’ífá fún ilé oluweri mogeti Atojo ateerun ilé oluweri Kíí gbona

Rezo para la sal

Ayóòyogo Ayóòyogo Ayóòyogo A d’ífá fún rúnmìlà Bàbá nlọ rẹẹ bàwọn mu iyo yora Awa ti aba w n mu iyo yora r Ayo ní kó m bà wà r ibanujẹ kán kíi bà iyo

125

Ela Ola, LLC

Rezo para el aceite de palma

Lugbu lugbu gbe gbe A d’ífá fún ẹpọ Ti nṣe ọmọ yẹyẹ ẹbọ Ẹpọ gorire odi Ẹbọ lugbu lugbu gbe gbe Ẹpọ gorire osì dẹbọ osinsin Ẹbọ ní pa igun lerín

126

Ela Ola, LLC

. Uso de la miel para rezar

Oyin rèé ó A kíí lá oyin ká tutó Ayé ó ní tutó sì r ọmọ yíí ó A kíí la oyin kía pọ ṣe Ayé kó nú pọ ṣe sí r ọmọ yíí ó Ohùn tó bá dun ní ọmọ arayé wà ogin si Ohùn tó bá dun ní ọmọ arayé ó m wà ọmọ yíí sì

127

Ela Ola, LLC

. Uso para el eja aro y el eku ifa

Eku jìgìnnì ní w n fi nbò ri alàdó Ikori abẹnu hán há ní w n fin bori awujáale Gbámi gbámi làáké Gbámi gbámi la Àgbà Èníkan kí ìgbá n ò ṣe r r A d’ífá fún Orúnmìlà Ifá ò gbà alàdó ewí tilé tilé taya taya tọmọ tọmọ Ọjà òde awo Àgbàlá Ifá n ọba rawo rere Àgbàmila

128

Ela Ola, LLC

Si la persona tiene que darle de comer a las Iyami se reza:

Para alejar y virar par atrás las cosas malas

Òbàrà Méjì

Ẹjẹ eku sinsin ẹ ẹ fún Ifá jẹ Ẹjẹ eja sinsin ẹ ẹ fún Èṣù jẹ Ẹjẹ akara du nm aje Sakoto ní w n a d’ífá fún iyotí àkùkò Itan galaja nlọsi ó gbà Awo ojo pa àkùkò lóní ire idi Dodí asubi awo ada sure Òbàrà Méjì dí Òkánrán Méjì Lóní ire idi dodí asubi awo adi Asure Ase

129

Ela Ola, LLC

Òfún Ìwòrì

Pápá nlá nlá wò il run Ẹran lá wò ìyọdán Isuru gu dú bú à nnsáwo ilé Èṣù A d’ífá fún Orúnmìlà Bàbá ngbèmi irogun otá Ifá lofí ofun ká igun malè Ifá lofí Ìwòrì tè akala laya Òfún pa gbọ rì ó Ifá wà mi ìṣegun ọtá mi Òfún pa gbọ orí Njé owu nru ó Owu nlá Ní soju lẹ lẹyẹ lowu lá

130

Ela Ola, LLC

Este verso se usa cuando se le ofrece la okete a las brujas

wwww nrinnrinnrinnrin ofunofunofunofun

w nrin wofun wè dó A d’ífá fún ìyami orongo Nijó tí w n nsáwo ròdé ipokia Ẹbọ ní w n ní kiw n ó ṣe W n gbẹbọ nb w n rúbo Njé ìyami fi oju bà òkètè Ó oyin n sew n sinrinkun oyin

131

Ela Ola, LLC

Este verso se usa para el ipese a las brujas (machos) Ìròsùn ose/ oso/ ayope/ jee jee

Ó foju jò oso

Ohun ẹnu nika

Asoju r ní nmú w n dí aje

A d’ífá fún ótááta (ẹyẹ)

Eyi tí n lọ réé yè ẹyin tire sinu igbo

Ẹbọ ní w n ní kó ṣe

Ó gbẹbọ nb ó rúbo

Njé ótááta kiko lako ẹyin rè á otá

132

Ela Ola, LLC

Este verso se usa para recibir la ayuda de las brujas y no tener conflicto Osa méjì

Ela wèwè awo abe owu

A d’ífá fún owu

Igbà tí n je lawiyo elleye

Ẹbọ ní w n ní kó ṣe

Ó gbẹbọ nb ó rúbo

W n ní ki èjí wéré wéré kó lọ ree pà owu

Eji wéré wéré pà owu n ruwe

W n ní I’agbàra gííri ojo kó lọ réé pà owu

Owu n idagbà

W n ní ki run gabgab kolo réé m n pà owu

Oorun gangan pà owu

Owu nṣo

Owu nlá

Njé owu nru ó

Owu nla

Ní soju lẹ lẹyẹ lowu lá

133

Ela Ola, LLC

Osa méjì – Se usa para echarle el epo a las brujas en la ofrenda

Apelebe gbegi lọruko tí a npè ikú Ifá má njẹkí ikú ó pami lọmode Or bale ṣe sin lọruko tí a n pea run Ifá monjẹ kẹmi ó farun lọle aye Afogigi munjẹ lọruko ta npè yìn ìyamí aj Ẹyin ìyamí ajé emon mi ej tèmi ẹpọ ní emon mu Ilé tí n munpo kíí munjẹ eniyan sá méjì lọ rogba yinwa si òde isalaye Ẹmi ọmọ osa méjì náá niyi Aj kíí roror kó kowu Ẹmi ẹpọ ní tiw n mo Emo pami j ati aw n ọmọ mi

134

Ela Ola, LLC

Para alejar y virar par atrás las cosas malas

Òfún Ìwòrì

Pápá nlá nlá wò il run Ẹran lá wò ìyọdán Isuru gu dú bú à nnsáwo ilé Èṣù A d’ífá fún Orúnmìlà Bàbá ngbèmi irogun otá Ifá lofí ofun ká igun malè Ifá lofí Ìwòrì tè akala laya Òfún pa gbọ rì ó Ifá wà mi ìṣegun ọtá mi Òfún pa gbọ orí Njé owu nru ó Owu nlá Ní soju lẹ lẹyẹ lowu lá

135

Ela Ola, LLC

Este verso se usa para ir con las ofrendas al pie de Èsù con el machete (Ada Orisa)

Osa méjì

Isansa méjì lọ tọná gere wolú

A d’ífá fún gbogbo oko kanlè Ìrunmọlẹ

Nijotí gbogbo ẹyẹ nlẹ w n bowà

A d’ífá fún Òrìsànlá

Nijotí àwọn ẹlẹyé nlẹ bowà Òrìsà npè Orúnmìlà gbàmi ó

A w n ẹlẹyé npè ìgbá p l p gbèmi

Orúnmìlà pè àdá Òrìsà ní mogba

Àdá Òrìsà ní mogba Àdá gbongbo owo ó mi ó Àdá Òrìsà ní mogba

136

Ela Ola, LLC

Para hacer que las brujas ataquen a sus enemigos

Osa méjì

Olugbo asolu Arè asolu Solu solu lobinrin n gbàle A d’ífá fún Orúnmìlà Nijó tí w n ní aw n koni bà bàbá se lotu Ifá m n Ẹbọ ní w n ní kó ṣe Ó gbẹbọ nb ó rúbo Njé ako lọ lonu kó ní bami ṣe Rere ìyami oṣoronga m n lew n bò rere Gbogbo eni toba lohun ki ní bami ṣe Ẹnu ní igbin fi n bu orisa Aya ní fi lá tè to Rere ìyami oṣoronga m n lew n bò rere

137

Ela Ola, LLC

Ẹbọ Orukọ kan Abo adirẹ méjì p lọp ẹpọ pùpá Òkètè méfà Igbin méfà Obi abata méfà

En español

Olugbo asolu Arè asolu Solu solu es el sonido que hacen las mujeres cuando están barriendo Hicieron adivinación para Orúnmìlà En el día que le dijeron que no iba a hacer más nada con él en otu – ife Se le dijo que hiciera sacrificio Y obedeció

138

Ela Ola, LLC

Por eso, si hubiese sido un hombre el que dijera Que no iba a ser más nada conmigo Las ìyami oṣoronga lo estarían persiguiendo todo el día Todo el que diga que va a dejar de hacer las cosas conmigo Recuerde que es la boca de la babosa la que llega hasta los Orisa Y es con todo su pecho que llega a donde están los Orisas Que las ìyami oṣoronga los persigan hasta que lleguen a mí

139

Ela Ola, LLC

Para hacer que las brujas acepten el sacrificio

ObaraObaraObaraObara owowowow nrinnrinnrinnrin

Pandoro oke lowa lọ n ta bi eyi Oba ṣo nile ata boo boo á ju isu lo A d’ífá fún Orúnmìlà Bàbá n lọ réé bà ìyami oṣoronga múnlé ní morere Ẹbọ ní w n ní kose Ó gbẹbọ nb ó rúbo Njé agbori ile á jeku Agbon ile á jeja Agbori ile á jeye Agbori ile á jeran Eeyan kíí gbori ile kó ṣeke Ase dowo ile tí ajo mun

140

Ela Ola, LLC

Para cerrar la ofrenda que se le va a llevar a las brujas. Seguido a este verso se lleva la ofrenda al pie de Esu

OseOseOseOse oturaoturaoturaotura

Apáádi igbàleroni n m igiri timo

Timo bi eni tí ó jebe ri

A d’ífá fún ìyami oṣoronga

Eyi tí n ẹe yèyé awo

Ẹbọ ní w n ní kiw n ó ṣe

W n gbẹbọ nb w n rúbo

Njé ati rúbo lóní ẹbọ awa fui á juba

Iyewa oṣoronga á juba

A soogun lóní oogun awa jò á juba

Iye wà oṣoronga á juba

141

Ela Ola, LLC

Medicina para hacer que las brujas ataquen a sus enemigos

Osa méjì

Se quema una okete grande complete junto con las hojas de segun sete hasta que se hagan polvo. Se echa el polvo encima del tablero para marcar el signo y rezar la encantación. Después de rezar, se echa el polvo sobre una babosa la cual se ha metido antes en una bolsa de algodón. Finalmente se amarra la bolsa de algodón con hilo blanco y negro y se cuelga en la parte delantera de la puerta principal de la casa para que las brujas reconozcan su propiedad y la respeten. El resto del polvo que quede se mescla con agua y la persona se lo toma.

142

Ela Ola, LLC

Rezos para dar Obi a Ifa y los Orisas

Estas encantaciones son las que se necesitan rezar cuando se le va a ofrecer Obi a Ifa o a Osun u otros Orisas

1

Oturupon Ofun bisi bisi A d’ífá fún Eleeribisi Ẹyi ti yíò m fi obi beku Kinni Ifá nfi obi ṣe? Ipe ní Ifá nfọ bi ṣe ipe kini Ifá nfọbi ṣe Oyin ní Ifá nfọbi ṣe oyin

143

Ela Ola, LLC

2

Ela were awo obi A d’ífá fún obi Obi ní t run bò walé aye Ela were ọdé awo obi Kó ṣeeyan tó m pè ọmọ obi yoyan

3

Erin kẹẹ oyin ṣeṣe A d’ífá fún kowe Yíò pabi laujo kin ní Ifá Yíò fi obi yiṣe? Erin kẹẹ oyin ṣeṣe lalade Yíò fi gbodi

144

Ela Ola, LLC

4

Adepeju lawo ilé Alareunda Adamupo lawo Adamupo ademuje A d’ífá fún Okokannirino Irunmole W n dawojo w n yóò ran obi Kóbi ọmọ bà ṣe siwi iṣe Ti aran obi jeere Ó iṣe ti aran obi

145

Ela Ola, LLC

Si el sale en la consulta un Meji, Ìròsùn Méjì se reza después de Odí Méjì en el orden normal de los Méjì

Ìròsùn Méjì

1111

Àdá fọwọ fẹjú ẹ w n Àdá fọwọ fẹjú ẹ w n A d’ífá fún onídèrè N súnkun pè ohun kò bi’mọ Ẹbọ ní ṣo pè kó wá ṣe Ìgbá t t àdán di métà Ọmọ yọyọyọ nilé Onídèrè

146

Ela Ola, LLC

2222

Ìtarúkú lawo ìtarúkú Ìtarúkú lawo ìtarúkú Ìtarúkú lrúkù taa taa taa A d’ífá fún Ìgbá ṣaso rọdé yó Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ìgbá rúlá, ígbá rúkàn Ìgbá rú èṣù gbọọrọ Bi a bá wa’lé ayé ẹni À ní ìgbá

147

Ela Ola, LLC

wónrínwónrínwónrínwónrín MéjìMéjìMéjìMéjì

1

wón owó lá n ná owó mini

wón owó lá n ná owó mini Onjẹ lọ w n lá n pè ní ìyàn

A d’ífá fún Òùn Yọw n ọmọ Ọbaléyò ajòrí

Níjótí nru àpà ìl k

Lọ si’lé Onísin ìko

Ẹ sáré wá ẹ wá ẹ wá rajà ọmọ ọba

Ẹpọ ṣéṣé wá ẹ wá raja Òùn Yọw n

Ẹ sáré wá ẹ wá ẹ wá rajà ọmọ ọba

148

Ela Ola, LLC

2

Ikún níí fi agbárí ṣelé Àtàrí níí kò j kóòrùn ó pagb n ìsàlè Ọl b hùnbọhùn níí fi apá ara rè dá gbèdu A d’ífá fún Oláítán Ọmọ bibi inú Agbọnnírègún Ọla Ifá kíí tán ọla kù lẹyìn Ọla ikin kò lè run

149

Ela Ola, LLC

ÒbàràÒbàràÒbàràÒbàrà MéjìMéjìMéjìMéjì

1

Òtòó ọbàá

A d’ífá fún àwọn nlọ rèé wẹrí ọla lódò

Ẹbọ ní w n ní k ṣe Òtòó ọbàá ó Orí rere law n n wè

2

Gúnnugún ní kó torí abẹ farí Erè lawo àbàtà

A

d’ífá fún Èjì Òbàrà

T

nlọ rèé pabì féríwo

Ọ bá dúró kó m bi féríwo Èjí Òbàrà Dúró kó m bi féríwo Èjí Òbàrà

150

Ela Ola, LLC

3

Isè osohun amusie Ìya o sohun amo s’awoda A d’ífá fún ejì Obara Ti nra agbon ola Ti abogbà aráyé nrì Elègèdè meréè Elègèdè meréè Ejì ogbàra kí nlọtá Kí nlọtá tóòfi da’laye Elègèdè meréè.

151

Ela Ola, LLC

kànrànkànrànkànrànkànràn MéjìMéjìMéjìMéjì

1

Ọya ní osa á ra Kúrú kúrú otá mana mana Àk àparò Àbà àparò W n lá àbẹ lorí sàí sàn Lọ di’fafún Ọlófin Ọlófin nrọté w n ní ó gbodo kute na ṣe Aya rè nṣo j j àrùn W n ní ó gbodo ku àrùn Okan bi, ọmọ rè nṣo régede W n ní ẹ fọ régéde kú Oni dùdu gbà dùdu Oni pupa gbà pupa Alayinrin gbà Ayinrin Barapetu Ọba máa ko kú ó ka run Barapetu

152

Ela Ola, LLC

2

Etí ti gbáyùn-ún Ẹni n gb àb A d’ífá fún Òkànràn Méjì Yóó fowó kan ṣoṣo sowó Kèè pè kèè jìnnà Ẹ wá bá wa bọlà bà rè gbogbo

153

Ela Ola, LLC

3

Òkànràn kannihin Òkànràn kan lohun Òkànràn Méjì ọderin Òkànràn Méjì odi ọdọdọ A d’ífá fún Olófin Adgodiworan Ogbo agborako logbo ahun Adagbarako rin niti igbin Ogbo agborako logbo ahun

154

Ela Ola, LLC

4

Apatanlá abaya kakara

A d’ífá fún Igba Igi

Ìgbátí w n nt run bò waye

Apatanlá abaya kakara

A d’ífá fún Igba Sàngó

Ìgbátí nbè láárnin ọtá

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Sàngó náá gbebo nbè orúbọ

Njé igi gbogbo ní Sàngó pa

Arira kíí pa ṣé

Igi gbogbo ní Sàngó pa

155

Ela Ola, LLC

ÒgúndáÒgúndáÒgúndáÒgúndá MéjìMéjìMéjìMéjì

1

Ògúndá Méjì Awo ibòn Lọ di’fá fún ibòn Nígbátí nfi nj ní ropo ọtá Ẹnu ti ìbò nfi nfọ hun Lọfi nṣegun Èrò Ìpo Èrò Òfà wá bá ní la rú ìségun Ibòn á nì enu ti m mun

Fohun ní m mun ṣegun

156

Ela Ola, LLC

2

Òkìkí

Ariwo

A d’ífá fún Ogun

Ti

yóó bi’mọ kan náà

Ti

yóó wùsì ka’yé

Ẹbọ ní w n ní k ṣe Njé Òkìkí o

Ariwo Òkìkí ọmọ Ogun kan

157

Ela Ola, LLC

sásásásá MéjìMéjìMéjìMéjì

1

Òsá yóó Babalawo ayé lọ difa fún ayé Ayé n wojú ọmọ rè kiri Ẹbọ ní w n ní k ṣe Ó ṣi gb bo nb ó rúbo Awa rojú a sì rí aayé Awa mọ rí ohun wà y

158

Ela Ola, LLC

2

Àtàtà kurà kurà Ẹnu ẹyẹ kò lè ran òkúta A d’ífá fún rúnmìlà Ifá nbè láàárín otá eleyi Ẹnu yín kò lè ran mí m o Ìgbá ẹja kíí dári ṣo w r Ìgbá ẹja

159

Ela Ola, LLC

3333

On’ilé ẹti ojá níí wò irawo saasaa l’oke

A d’ífá fún kutu

Ti nt’ run bò waye

Ti yóò sì fi gbogbo ara K’aje wa’le

Ẹbọ ní w n ní k ṣe

Ó ṣi gb bo nb ó rúbo

Kó í p , kó í jiná

wá bá ní jèbútú iré

W n á ní ẹṣẹ ire ní Erukuku fi n te’le

160

Ela Ola, LLC

ÒtúrúpÒtúrúpÒtúrúpÒtúrúp nnnn MéjìMéjìMéjìMéjì

1